Itoju oloyun

Itoju oloyun We treat all kind of infection,we give pure organic solution to all kind of disease

FUN OBINRIN TO NWA OYUNOdindi adan NLA kanEmo ajaoEmo agboAo lo si oja, lodo a won iya  olobi, ao ra ewe ti won fi nsi o...
23/07/2025

FUN OBINRIN TO NWA OYUN
Odindi adan NLA kan
Emo ajao
Emo agbo
Ao lo si oja, lodo a won iya olobi, ao ra ewe ti won fi nsi obi
Ao jo gbogbo eroja yi papo, ao da sinu ike
Obinrin na yio ma fi f'oko mu kete to ba park nkan osu e. Fun ojo marun
Next month oyun ni confirmed.
OBINRIN TI KO NI SOMURORO EDA TUBE BLOCKAGE ATI INFECTION LO WA FUN

OGUN INFECTION FUN OKUNRIN ATI OBINRIN.Ogun yi confirmed gan fun awon anbelorun. Epo igi amuyanEso baraEwe akokoEwe ekej...
23/07/2025

OGUN INFECTION FUN OKUNRIN ATI OBINRIN.
Ogun yi confirmed gan fun awon anbelorun.
Epo igi amuyan
Eso bara
Ewe akoko
Ewe ekeja
Obu otoyo
Ao fomi ogi se, mimu ni araro ife kan

HEPATITIS BEwe eyin olobeEwe tea (lemon grass)Ewe ibepePelu gingerAo fi Omi se mimu ni igbameta lojumo, half cup. Confir...
23/07/2025

HEPATITIS B
Ewe eyin olobe
Ewe tea (lemon grass)
Ewe ibepe
Pelu ginger
Ao fi Omi se mimu ni igbameta lojumo, half cup. Confirmed

OKA ORI OMODEAo gun eru alamo kunna ao po mo epo pupa ao ma fi pa ori Omode yi oka ori Omode ma lo
23/07/2025

OKA ORI OMODE
Ao gun eru alamo kunna ao po mo epo pupa ao ma fi pa ori Omode yi oka ori Omode ma lo

OGUN INARUNInarun je aisan to lewu, o le fo eniyan loju to ba pe lara.Epo igi oganwoEpo igi obi edunEpo igi poroporoEpa ...
23/07/2025

OGUN INARUN
Inarun je aisan to lewu, o le fo eniyan loju to ba pe lara.
Epo igi oganwo
Epo igi obi edun
Epo igi poroporo
Epa ikun
Ao gun won po, mimu eko ni daji sibi kokan

23/07/2025

FUN EDA. OGUN YI CONFIRMED GIDI GAN
Omi osan wewe igo 1.
Ose dudu bi oni #100
Ao fi ose dudu sinu abo kan, omi ekunwo kan ao fi po dada, lehin na ao da omi osan weee yensi, ao fi iyo die si, obinrin na a ma mu die die,, ko le mu igo kan yen tan ki oyu to de.

OSI INU.Arun yi ma nyo awon omode lenu, ti won ma ru, ti egungun iha won ma han sita.Egbo asunwon egbaÈrù, ao se pelu om...
12/07/2025

OSI INU.
Arun yi ma nyo awon omode lenu, ti won ma ru, ti egungun iha won ma han sita.
Egbo asunwon egba
Èrù, ao se pelu omi
Mimu ni sibi kan ni aro.

OGUN GBOGBO KOKORO INU EJEBi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni gbogbo igba tabi ki kok...
12/07/2025

OGUN GBOGBO KOKORO INU EJE
Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni
gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro
eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo
n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi...
Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna
daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si.
Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti
o ba ni arun jerejere(Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo
omi lasan.

Health Is WealthIlera loro, toju emi e, Ao ni ba won kuku owowo,ododun ni sapo ruwe, akalamagbo kin pa odun je.emi wa as...
12/07/2025

Health Is Wealth

Ilera loro, toju emi e, Ao ni ba won kuku owowo,ododun ni sapo ruwe, akalamagbo kin pa odun je.emi wa ase opo odun laye..

INU RIRU - MESTRA PAIN
Ao wa bara, epa ikun, epo amuyan, epo sapo, e se pelu omidun ao ma mu diedie.

DIABETES
Ewuro oojo,aofi omi osan wewe gbo Dada,cup kan ni aro kia to jeun ati cup kan ni ale kia to sun.

TYPHOID
Eso ibepe, ao sa ti yio gbe Dada ao wa lo kuna ao ma fi mu ogi gbigbona.

ASTHMA
Ewe Emile,ao fi omi agbo gbo,ao da oyin si, ao ma mu die die.

ORI FIFO
Ewe papasan ewe akoko ao gun papo no ose dudu ao wa lo gbe ile ao fo ori wa sibe

OGUN IMU RIRUN TABI INU GBIGBONAE lo wa efo munu tutu,ewe lapalapa funfun,ewe lara eyikeyi,ao gbo papo pelu omi,ao se,ao...
12/07/2025

OGUN IMU RIRUN TABI INU GBIGBONA
E lo wa efo munu tutu,ewe lapalapa funfun,ewe lara eyikeyi,ao gbo papo pelu omi,ao se,ao fi iyo si mimu ni cup kan laro,o tun wulo fun obinrin ti onbe olorun fun oyun

FUN KOKORO ARAE JE KA RA OGERE EPO PUPA KA WA RA TAGIRI NLA KAN SI E JE KA FI PELEPELE PA NI PANSA KA HO DIE NINU ITAGIR...
10/07/2025

FUN KOKORO ARA
E JE KA RA OGERE EPO PUPA KA WA RA TAGIRI NLA KAN SI E JE KA FI PELEPELE PA NI PANSA KA HO DIE NINU ITAGIRI YEN SITA NI IWON BI O SE MA GBA OGERE EPO YEN KA WA GBE SINU ORU KO LE GBONA DAADA KI N SE ORI INA O INU ORUN NI MO PE KA MA FI PA ARA WA FUN KOKORO NI OKOKORO ARA

Address

Abeokuta

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Itoju oloyun posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share