25/12/2025
1. *ATOSI EYIKEYI*
Ao WA bara, AO ge kekeke, AO ko tele ikoko AGBO, AO Fi kanhun bilala die SI, AO da ewe ibepe bo mole, AO SE pelu omidu TABI omi Lasan. Enina yio momu die die bi omi.
2. *OGUN ATOSI (GONORRHEA)*
Bara kan, Epa Ikun 3, Baka die, Ako Kanhun die (Kanhun bilala), Ao lo Kanhun yen, Awa ge gbogbo Awon nkan toku kekeke, ao ko sinu kegi 5liters. Ao da Oti le lori ao fi sile fun Ojo meta.
Ao ma mu shot kan lemeta lojumo.
3. *ATOSI*
ewe Atori, AO Fi stout SE kojina dada, eni na yio momu die die.
4. *ATOSI ELETUTU TO YARA BI ASA*
Capsules red and yellow ati clorafenico one pack awa da gbogbo re sinu gin igo kan tabi osawewe igo kan, Eni naa yio momu ni gas kokan LARO ATI LALE sugbon ki eni naa ma mu omi dada ki obale tete flush re.
5. *OGUN ATOSI*
AO wa odidi atare kan AO gun tepo tepo mo egbo Teso, Kodi powder. (ni agunmu). Ao mofi mu eko gbigbona LARO.
6. *OGUN ATOSI*
Epakun, ao ge kekeke, sinu kegi kan, AO fi 7up TABI omi re, ao file fun bi ojo meta, ao mo mu ni gas kokan.
7. *ATOSI EYIKEYI*
Ao wa bara, ao sun nina, yio de, dada, ao fun omi nu re, ao tun wa omi epo oyinbo(pineapple), ao fun omi inu re dede, omi TI afun jade Lara, bara Yan, ao wa omi osan oronbo naa be, ao da papo, ao gbe kale fun bi ojo MEJI,
LEYIN re, ao mo mu ni spoon MEJI, maji. TI oba Po Lara, ao mu ni spoon mefa.
8. *ATOSI OLOJOPIPE*
Ao wa bara bi meji, AO be epo Ara re kuro ATI omo Inu re, AO WA sese ge kekeke, AO dasi Inu pot kan, AO WA Big stout bi merin, AO da le Lori, AO SE lagbo ko jina dada, t**i ti yio Fi dinku bi two stout quant**ies. Leyin na ao momu ni short kokan LARO ATI LALE.