Asiri Isenbaye Awon Agba

Asiri Isenbaye Awon Agba To promote the use of traditional herbs and
To initiate the culture of Yoruba traditional in the whole world....

ÌKÉDE PATAKI👇🏻👇🏻👇🏻A NFI AKOKO YII KEDE FUN WA BAYII PE IWE AKOJỌPỌ AṢIRI AWỌN AKỌNI AGBA AKỌNI AṢIRI EWE ATI EGBO TODAJU...
16/12/2024

ÌKÉDE PATAKI👇🏻👇🏻👇🏻

A NFI AKOKO YII KEDE FUN WA BAYII PE IWE AKOJỌPỌ AṢIRI AWỌN AKỌNI AGBA AKỌNI AṢIRI EWE ATI EGBO TODAJU ỌGBỌN JU AGBARA LỌ AAPA KEJI ((( SECOND EDITION ))), TI JADE BAYII FUN AWA ỌMỌ ẸGBẸ TAA TI NI AAPA KINNI ((( FIRST EDITION ))) RẸ LỌWỌ NIKAN NIO. AAPA KEJI IWE YII KUN FUN AWỌN NKAN AṢIRI AGBARA LORISIRISI TIWỌN DAJU ATI BẸBẸ LỌ, ((( ₦50,000 ))) PERE NI IWE AṢIRI AAPA KEJI YII. O WA NILẸ BAYII FUN TITA, ỌJỌ KEJÌ TẸ BA SAN OWO IWE NA SINU ACCOUNT NUMBER ẸGBẸ YII NI AO ṢE ÈTÒ IWE NA LATI FIRANṢẸ SIYIN NIBIKIBI TẸ BA WA PẸLU ÒGO ỌLỌRUN ỌBA... E JỌ AWA TAO BA NI AAPA KINNI IWE AṢIRI YII É JẸ KIA TETE GBIYANJU LÁTI KỌKỌ NI LỌWỌ, KIA LE NI ORE ỌFẸ LATI RA AAPA KEJI RẸ ỌGBỌN JU AGBARA LỌ. EWE ATI EGBO YOO MA JẸ FUN WA PẸLU ÒGO ỌLỌRUN ỌBA OOO...✍️

Atejise yii wa lati ọdọ 👉🏻OLÙDÁSÍLẸ̀ ATI APAPỌ IGBIMỌ MAJEOBAJE ẸGBẸ AṢIRI EWE ATI EGBO LAGBA TRADO MEDICAL HERBALIST ASSOCIATION OF NIGERIA WORLDWIDE PẸLU AJỌṢEPỌ ATI ÌFỌWỌ́SOWỌ́PỌ̀ ẸGBẸ AṢIRI ISENBAYE IMỌ YORUBA CULTURAL INITIATIVE WORLD WIDE🍀☘️🌳

Anfani wà fún awa ta jẹ Ojúlówó ọmọ ẹgbẹ yìí, fún àwa ta ba ní ìfẹ sí ÌWÉ AKOJỌPỌ AṢIRI OGUN AWỌN AGBA AKỌNI EWE ATI EGB...
04/12/2024

Anfani wà fún awa ta jẹ Ojúlówó ọmọ ẹgbẹ yìí, fún àwa ta ba ní ìfẹ sí ÌWÉ AKOJỌPỌ AṢIRI OGUN AWỌN AGBA AKỌNI EWE ATI EGBO LAGBA TODAJU, #47,500 pere ni bayii. Ati àwọn IWE OGUN AṢIRI ISENBAYE IMO YORUBA TODAJU, Aapa kinni, Ìkejì, ìkẹta àti Ìkẹrin . Gbogbo awọn iwe na lo wa nilẹ bayii fún títà. Ọjọ Kejì ta ba san owo rẹ ní ào firanṣẹ Si yin pẹlu aṣẹ eledumaree. Awa ta ba ti ṣetan fún iwe na bayii, e jẹ kíá kọn siwa lori awọn nọmba ẹgbẹ yìí 👇👇👇

👉 +2348152632034, ( WhatsApp chat only)

👉 +2349043606151, ( Call only ) ...✍️

ÀTẸJIṢẸ YII WA LATI ỌDỌ 👉 OLUDASILẸ ATI APAPỌ IGBIMỌ MAJEOBAJE ALAKOSO ẸGBẸ AṢIRI EWE ATI EGBO LAGBA TRADOMEDICAL HERBALIST ASSOCIATION OF NIGERIA WORLD WIDE PẸLU ÌFỌWỌ́SOWỌ́PỌ̀ ẸGBẸ AṢIRI ISENBAYE IMO YORUBA CULTURAL INITIATIVE WORLD WIDE ☘️🍀🌳

AGBO AKO JEDIJEDI TODAJUBara kan, ao ge kekeke, Akogun, Muru, Epa ikun, ao ko gbogbo re sinu ike tabi Igo totobi kan, ao...
26/11/2024

AGBO AKO JEDIJEDI TODAJU

Bara kan, ao ge kekeke, Akogun, Muru, Epa ikun, ao ko gbogbo re sinu ike tabi Igo totobi kan, ao bu omi ti o ba mo dada le lori, leyin ojo
keta ao ma mu ni ekan lararo... Yóò ba wa lara mú pẹlu ogo ọlọrun ọba ooo ✍️

DUPE KOLEJE FUN EE

AWỌN IWE AṢIRI TODAJU WỌNYII WA NILẸ BAYII FUN TITA, IWỌ TO BA NIFẸ SI TO TI ṢETAN RA BAYII KIO KỌN SIWA LORI AWỌN NUMBER ẸGBẸ YII TO WA LARA ÀWỌN ÌWÉ NA....✍️

Fún iwọ to ba ni adojuko àrùn ara kan sí ìkejì, tabi adojuko lori ọrọ igbesi aye rẹ ti gbogbo nkan tiwa su rẹ pata, fi ọkàn rẹ ba le ni igbagbọ pe gbogbo ogun ayé rẹ ti dopin lati oni lọ pẹlú àṣẹ eledumaree ati agbára rẹ ti nbe ninu lilo ewe ati egbo. Awọn iṣẹ ATUDE GBOGBO AMI BURUKU LARA, ẸYỌNU NLA TODAJU ati awọn iṣẹ todaju bẹbẹ lọ lokankojokan taa ti ṣe sílẹ bayii fún ànfàní gbogbo awa ọmọ ẹgbẹ yìí toni ìfẹ sí ní owo tiko pani lara. Iwọ ṣa ti gbiyanju lati kọn si BABA WA OLUDASILẸ ẸGBẸ YII pẹlu awọn nọmba ẹgbẹ yìí 👉 09043606151 (calling), 08152632034 (WhatsApp only)....✍️

MIO GBA OWO KONKON LỌWỌ WA ṢUGBỌN GBIYANJU LATI DUPẸ KI AWỌN IṢẸ YII LE JẸ FUN É DAADAA.... IRE ÒOOO

ELEYII NI ẸYONU GBOGBO AYE TODAJU 👇 👇 👇 Ao wa Ẹyin ibilẹ ororo mẹta, Ẹnu igbale to pọ pẹlú odidi atare nla kan, ao jo pọ...
19/11/2024

ELEYII NI ẸYONU GBOGBO AYE TODAJU 👇 👇 👇

Ao wa Ẹyin ibilẹ ororo mẹta, Ẹnu igbale to pọ pẹlú odidi atare nla kan, ao jo pọ, ao ma fi fọ Ẹkọ tutu mu tabi ka da sinu oyin igan gidi ao ma la laro ati lale. Ào ma pe ohun yii sii;👉 Gẹgẹ la ngbe ẹyin adiẹ, Gẹ gẹ gẹ ni ki ọmọ araye ma gbe emi-L-omo-L, fun rara igbale ni fi ẹnu rẹ tun ile ṣe, fun rara ọmọ araye ni ki wọn ma fi ẹnu wọn tun te mi L-omo-L ṣe ooo. Ao ma fi abẹrẹ ọpọrọ ko jẹ. Odaju púpọ, yóò jẹ fún wa pẹlu ogo ọlọrun ọba ooo ✍️

ELEYII NI ẸYONU IMULẸ AWỌN ÀGBÀLAGBÀ TODAJU👇👇👇Ao lọ Ewe afeloru mokanlelogun pẹlu ata ijosi ẹyọ mẹta ào fi se ẹyin agric...
19/11/2024

ELEYII NI ẸYONU IMULẸ AWỌN ÀGBÀLAGBÀ TODAJU👇👇👇

Ao lọ Ewe afeloru mokanlelogun pẹlu ata ijosi ẹyọ mẹta ào fi se ẹyin agric mẹta jẹ pẹlu adura. Orí ni ao fi se epo rẹ, ao sọ sori òṣukà ni idi rẹ ko gbọdọ kon ile rárá opo. Yóò jẹ fún wa pẹlu ogo ọlọrun ọba ooo ✍️

ELEYII NI ISE EDA OBINRIN TODAJU 👇👇👇Ào wa Ewọ silẹ Ewe epin, Eemo agbo, Eemo ajawo, Ewe emo, Akọ kaun bilala, Eesan ekur...
19/11/2024

ELEYII NI ISE EDA OBINRIN TODAJU 👇👇👇

Ào wa Ewọ silẹ Ewe epin, Eemo agbo, Eemo ajawo, Ewe emo, Akọ kaun bilala, Eesan ekuro, a o gun gbogbo rẹ papọ, a o ma fi maa fọ ẹkọ tutu mu laro laro. Yóò ba wa lara mú pẹlu ogo ọlọrun ọba ooo...✍️

Dupe ko le jẹ fún e. Ire ooo

OGUN IJU (FIBROID) TODAJUAo wa Epo osan wewe pupo, Eso Bomubomu pupo, Kahun bilala die. A o jo gbogbo re papo, a o da et...
20/04/2024

OGUN IJU (FIBROID) TODAJU

Ao wa Epo osan wewe pupo, Eso Bomubomu pupo, Kahun bilala die. A o jo gbogbo re papo, a o da etu naa sinu (keg 4 liter), a o fi oti schnapps ati omi osan wewe re fun ojo merin. Omi osan wewe ati oti naa gbodo je osuwon (size) kan naa o. Obinrin naa yoo ma mu gaasi kekere kan leemeta lojumo....

AWỌN IWE AṢIRI TODAJU WỌNYII WA NILẸ BAYII FUN TITA, IWỌ TO BA NIFẸ SI TO TI ṢETAN RA BAYII KIO KỌN SIWA LORI AWỌN NUMBER ẸGBẸ YII TO WA LARA ÀWỌN ÌWÉ NA....✍️

Fún iwọ to ba ni adojuko àrùn ara kan sí ìkejì, tabi adojuko lori ọrọ igbesi aye rẹ ti gbogbo nkan tiwa su rẹ pata, fi ọkàn rẹ ba le ni igbagbọ pe gbogbo ogun ayé rẹ ti dopin lati oni lọ pẹlú àṣẹ eledumaree ati agbára rẹ ti nbe ninu lilo ewe ati egbo. Awọn iṣẹ ATUDE GBOGBO AMI BURUKU LARA, ẸYỌNU NLA TODAJU ati awọn iṣẹ todaju bẹbẹ lọ lokankojokan taa ti ṣe sílẹ bayii fún ànfàní gbogbo awa ọmọ ẹgbẹ yìí toni ìfẹ sí ní owo tiko pani lara. Iwọ ṣa ti gbiyanju lati kọn si BABA WA OLUDASILẸ ẸGBẸ YII pẹlu awọn nọmba ẹgbẹ yìí 👉 09043606151 (calling), 08152632034 (WhatsApp only)....✍️

MIO GBA OWO KONKON LỌWỌ WA ṢUGBỌN GBIYANJU LATI DUPẸ KI AWỌN IṢẸ YII LE JẸ FUN É DAADAA.... IRE OOO

Address

Atan Ota

Telephone

+2349057251013

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Asiri Isenbaye Awon Agba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Asiri Isenbaye Awon Agba:

Share