OGUN EWE ATI EGBO

OGUN EWE ATI EGBO Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from OGUN EWE ATI EGBO, Medical and health, Ejigbo market, Ejigbo.

IYARA YI WA FUN ÀWỌN OGUN ATI ALAYE NÍPA IRAWỌ ẸDA.

Ẹ FI ỌKÀN BALẸ AWỌN ÌSẸ TI MA MA FI SÍLẸ MA DAJU

WhatsApp number 09037334757

Contact me directly on 09158484610 glo
09037334757 mtn

ASINA OWO KIAKIAA Ao lo wa odidi schnap kan,a o ja ewe ehinolobe to po die,a o da sinu schnap naa,pelu owo ẹyọ original ...
06/07/2025

ASINA OWO KIAKIAA

Ao lo wa odidi schnap kan,a o ja ewe ehinolobe to po die,a o da sinu schnap naa,pelu owo ẹyọ original tiko luju, pelu #1000 naira tuntun ninu schnap náà.

Ao ma yomu laro laro kutu,

ona owo ama la kiakia ire o

OOGUN AJEGUNAAo wa egbo tude , erunrun ide , a o gun mo ose dudu iwe ekan , a o wa gbo ewe iyalode mejeji , ewe ewuro tu...
05/07/2025

OOGUN AJEGUNA

Ao wa egbo tude , erunrun ide , a o gun mo ose dudu iwe ekan , a o wa gbo ewe iyalode mejeji , ewe ewuro tutu , sinu omi , a o da sakiti re nu , a o wa fi ose yi we omi yi , a o fi epo paraki ato we , ekan lodun ni iwe yi o...

AJẸ FUN WA O!

AWENU OWO KOWO PROMISE AND FAIL AMUBO OWU ALANTAKUN IKORIRAOA o loja ewe lapalapa mejeeji (funfun ati pupa),A o gbo papo...
02/07/2025

AWENU OWO KOWO PROMISE AND FAIL AMUBO OWU ALANTAKUN IKORIRAO

A o loja ewe lapalapa mejeeji (funfun ati pupa),A o gbo papo dada,A o wa fi ase se sakiti re danu,A o wa lora iyo didi Loja,A o fite ejiogbe sori opon ifa abi paper funfun kan, A o wa so bayipe:

EYAN MEJI KINBA IYO SOTA, BI EYAN BADI LOJA, EYAN KAN ATU NILE, LATI ONILO, KI GBOGBO IRAN NKAN TIWON PENI OWU ALANTAKUN, IKORIRA, AMUBO,e.t.c kiobere sini tu,ki omo araye yonu Simi.

A o wa da sinu ike 2litre kan, A o mata sinu omi iwe wa diedie

ise yi kere loju sugbon ota lenu nifa.

Atude Asina odajuEye egaegbo tudeatare kanogede ominiAo Jo papo ao mafi je ogede omini die die.
29/06/2025

Atude Asina odaju
Eye ega
egbo tude
atare kan
ogede omini
Ao Jo papo ao mafi je ogede omini die die.

EYONU ASINAewe ola tutu a le lo gbigbe na sungbo tutu lo da ju. pelu ewe etiponola tutu ao gun po pelu ose  ao ko sinu i...
27/06/2025

EYONU ASINA

ewe ola tutu a le lo gbigbe na sungbo tutu lo da ju. pelu ewe etiponola tutu ao gun po pelu ose ao ko sinu ike funfun , ao ma fi we lararo.

Tude todajuEpo obo,iku ojia,igi nlaata ijosieru alamoAidan  ao gun gbogbo re mo ose dudu ao ma fi we gbogbo ide aye lara...
23/06/2025

Tude todaju
Epo obo,
iku ojia,
igi nla
ata ijosi
eru alamo
Aidan
ao gun gbogbo re mo ose dudu ao ma fi we gbogbo ide aye larawa loma tu Danu.

ASINA BIBO ASIRI.... ata ijosi topo die, egbo tude die, epo obo. A o gun awon erojayi dada lototo. A o wa po mo ose Ghan...
21/06/2025

ASINA BIBO ASIRI....
ata ijosi topo die, egbo tude die, epo obo. A o gun awon eroja
yi dada lototo. A o wa po mo ose Ghana tabi ose dudu. A o
fi opolo ijoku aye kan tele ike funfun kan a o wa gbe ose yen
le Lori. A o ma lo leyin ojo meje.

*OGUN EYONU AIYE TODAJU*Eku asin gbigbe meta, Oga gbigbe meta, Opolo gbigbe meta,Igbin agbonu nla meta, Odidi atarenla m...
19/06/2025

*OGUN EYONU AIYE TODAJU*

Eku asin gbigbe meta, Oga gbigbe meta, Opolo gbigbe meta,Igbin agbonu nla meta, Odidi atarenla meta, a o ko won sinu ape ijogun, a o wa da opolopo ewe ajeobale le lori, a o jo po, a o lo, a ofi die sin gberen kan si orikerike ara , a o bu die sinu epo pupa, a o ma la, a o po iyoku mo osedudu, a o ma fiwe lararo. Ise yi dara pupo, gbogbonise ni papajulo eniti nba ko orin kiko..

AWURE APASEAo ra lofinda bintu igo kan ao lo ja ewe akese tutu ao ra ao fu omi re sinu lofinda yin ao ma fi para.OhunreT...
16/06/2025

AWURE APASE

Ao ra lofinda bintu igo kan ao lo ja ewe akese tutu ao ra ao fu omi re sinu lofinda yin ao ma fi para.OhunreTakese ni se larin owu,gbogbo nkan ti nba so ko ma se be

EBE AWON AGBA. Ewe egele funfun, ewe ajeobale, epo obo, igbin odidi kan, ao wagun gbogbo re pelu igbin yentikarahun, a o...
14/06/2025

EBE AWON AGBA. Ewe egele funfun, ewe ajeobale, epo obo, igbin odidi kan, ao wagun gbogbo re pelu igbin yentikarahun, a o gun pomo Ose dudu, a o ko sinu ikarahun Miran ti a titoju sile. AKIYESI:-Ako gbodo soro ti aba gun ise yii lowo, kehinkein ayaba LA o fima we Ose yii,Ni aro ki orun toyo,Akosi gbodo soro ti abafe bu Ose yii.

ASIRIAo lo epo obo ti koju omori ike eva water lo. Leyin naao tun lo ewe igbo ti oun na koju ideri ike eva waterbakan na...
12/06/2025

ASIRI
Ao lo epo obo ti koju omori ike eva water lo. Leyin na
ao tun lo ewe igbo ti oun na koju ideri ike eva water
bakan na. Ao sese wa da mejeji po. Ao wada sinu
lofinda miss paris ao mafi para kato sun ni ale. Pelu
aro ti abafe jade opari gbiyanju e koyin oloun logo
asiri ni

ASIRI TIA FIN KOLE NI KIAKIAHahun Suratu yasin 41, suratu Wakia 41, suratuMuliku 41, isaja 41, afi omi fo, gbogbore si o...
10/06/2025

ASIRI TIA FIN KOLE NI KIAKIA
Hahun Suratu yasin 41, suratu Wakia 41, suratu
Muliku 41, isaja 41, afi omi fo, gbogbore si oju kan
no,odidi okan Malu eyi ti omi oti kan ni ara, age si 41,
afi idaji ninu huntu yen se ha fi iyo die si, omi hun tu
yen ma gbe mo ni ara, ase adurasi a je, tia ba tin je
idaji huntu tio ku yen lama mamu le lori, tia fije ton
Confirmed

Address

Ejigbo Market
Ejigbo
232116

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when OGUN EWE ATI EGBO posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to OGUN EWE ATI EGBO:

Share