23/05/2025
IMULE IYAKERE
Ofore: Eye werewere eye ori Ogun, oni omo Ogun ni oun se(3*), eye gboga gboga ori igi ose oke, oni omo igi ose ni oun se (3*) iwa pele nitetu omo agbon miregun, oni omo agbon miregun ni oun se (3*). Awon meteta ni won n ti ikole orun bo wa si ikole aye, won pade awon Arugbo meta ni orita meta apata agba- nsala. Awon arugbo yii ni ki won pada seyin won ni awon oni pada seyin. Igba ti won burin gada, iwa pele nitetu pada lo si odo babare agbon miregun, oni awon ri awon arugbo meta ni orita meta agba-nsala. Oni won ni ki awon pada seyin, awon si sowipe awon o ni pada seyin. oni nitorire ni oun se wa so fun iwo baba oun agbon miregun. Agbon miregun ni oseun, igba yi ni oun to no wipe omo oun gidi ni Iwo nse. Orunmila wa fun omo re 9 ni nkan merin, akoko... o fun ni IMULE, ekeji..o fun ni ISU KOOKO, eketa... O fun ni epo igi ose, o tun fun ni EWE ROROO sekerin. Oni ki iwa pelenitetu ma lo sode aye, oni gbogbo nkan ti iwapelenitetu ba dawole lode aye, oni aye oni baje mo lowo. Oni gbogbo Oran yio wu ti o ba da, oni asegbe ni yoo ma se. Oni toripe Arugbo akoko ti o ma koko ri bi oti se nlo yi, oni ASAKE ni oruko re nje, Arugbo keji to tele ODERE ni oruko re nje, oni Arugbo to gbeyin IYA KERE loruko re nje. Orunmila ni ti o ba de odo won, ti won ba da oro sile ki iwo naa da oro sile. Ti won ba sope OLOMU ki iwo naa so wipe OTUKANRAN, ti won ba sope OFUNJA ki iwo naa so pe OFUNKO. Nigbati iwapelenitetu yo si won, won da oro sile ni tooto oun na si da oro si won. Won so pe nje omo oruko awon, oni oun mo oruko yin... Iwa pele nitetu ni Arugbo akoko ASAKE ni oruko re nje, Arugbo keji ODERE ni oruko re nje, oni sebi IYAKERE ni Arugbo keta nje. Iwa pele nitetu wa senu koto orin awo bo si lenu. Oni ASAKE mohun Mi oooo, ODERE mohun Mi oooo, gbogbo eleye moba yin mule lonio, IYAKERE mohun Mi, oni kooko loni ki oro emi Lomo L ki o ko loni si rere(3*), ASAKE mohun Mi oooo, ODERE mohun Mi 0000, gbogbo eleye moba yin mule lonioo, IYAKERE mohun Mi. Alupaida loni ki e pa gbogbo ibi ti o ba nbe Lara Mi da si rere loni(3*). ASAKE mohun Mi 0000, ODERE mohun Mi oooo gbogbo eleye moba yin mule lonioo IYAKERE mohun Mi, sebi Igbo ki roro ki roroo ma ba gbe(3*). ASAKE mohun Mi 0000, ODERE mohun Mi oooo, gbogbo eleye moba yin mule lonioo IYAKERE mohun Mi, Aje ki roro ki o je igi ose(3*), ASAKE mohun Mi 0000, ODERE mohun Mi oooo gbogbo eleye moba yin mule lonioo IYAKERE mohun Mi, Atare ki kere ko ma lomo ninu(3*) lati kekere Mi ni kin ti ma ni owo lowo. IMULE OWO nlala ni mobayin se o, Mi o fi omo Mi seda, Mi o fi Aya Mi seda, Mi o fi ara Mi seda oooo, IMULE owo nlala ni mo ba yin se. Ki ebere si ni dari awon olowo nlanla wa s**o Mi towotowo owo won.(2)*
ALFA OLA ADUA GBEMI 09159185940