17/12/2024
SAGITTARIUS & JUPITER
MAY 22-JUNE 21(Osu June) je osu igbeyawo ati alajosisepo fun yin,ti e o gba osise tuntun tabi ki won gba yin si ile ise tuntun tabi ki e ri opolopo eniyan be yin nise tabi ba yin ra oja ti e n ta(more sales or patronage). Gbogbo ojo Wednesday naisi ati akoko naisi ti n be losu kookan ni e o fi koju isoro igbeyawo ati alajosisepo tabi ki ede-ko-yede ati ija sele laarin yin ati oko tabi iyawo tabi alajosisepo yin.
JUNE 22-JULY 21(Osu July) je osu iku ojiji, ijogun,ipingun,adanu dukia,sisonu(missing person) ati owo lara iyawo tabi oko tabi ana (in-laws) tabi alajosisepo yin. Aisan to ba bere si se yin tabi alasunmo yin lojo Monday naisi ati akoko naisi ti n be losu kookan le se okunfa iku ojiji fun yin.
JULY 22-AUGUST 21(Osu August) je osu irinajo losi ilu okeere(overseas),eko kiko ni university tabi polytechnic, oro esin(religious matters) tabi asa(culture), adua tabi ogun(medicine) ati orisirisi ala(dreams) fun yin. Kosi oore fun yin lori irinajo ti e ba lo lojo Sunday naisi ati akoko naisi ti n be losu kookan tabi ki won da yin pada sile(deportation) bi e ba ti rin irinajo losi ilu okeere tele.
AUGUST 22-SEPTEMBER 21(Osu September) je osu owo nlanla, ise nlanla ati dukia nlanla latodo ijoba ati alase ilu. O tun duro fun ipo aye,okiki agbega lenu ise(promotion) ati asegbayi fun yin, ti e o di olokiki,olola,oba ati alase laarin awon eniyan ti e ba wa,ti e o ni agbega lenu ise tabi ki e se freedom fun omo yin tabi ki e nawo lori omo yin to wa ni university/polytechnic tabi se ikomo fun omo-omo(grandchildren) yin. Gbogbo ojo Wednesday naisi ati akoko naisi ti n be losu kookan ni e o fi koju isoro lori awon nkan ti a ka soke yi.
FUN IBEERE ATIITOSONA LORI IRAWO YIN AKOSEJAYE YIN ATI AKOKO ORIRE YIN E PE 08056412713 TABI KI E WHATSAPP 08039212046 SUGBON E O SAN #1500 CONSULTATION FEE.