11/03/2026
ASIRI TI A FI NKOLE PARI
O seni laanu wipe Opolopo lo ti nkole Lati bi Odun mewa Tabi ju belo sugbon ti won Kori Ile na ko pari latari wipe won Kori Owo tujo Lati fi ri Ile na ko pari .
Mofe ki o mo amodaju loni wipe, Eniti kobamo Asiri Ile Aye yi, Eni na yi o pada sare ku ni, nje Iwo SE Akiyesi wipe Awon ti Iwo bere Ile kiko siwaju won ti pari Ile ti won o, sugbon Iwo wa dake, boya ni o mo wipe Eye koni so fun Eye wipe oko nbo!
Koda, Iwo Ti o ti RI Owo Lati fi ra Ile, debi wipe o fe ko ile, Mo fi nda o loju loni wipe, Ti o bale gbiyanju ohun ti mofe ko o yi, mofi oba Ti o da Ewe Ati Egbo se eri, o ma pari Ile ti e na Ninu Odun TI a wa yi.
AWON OHUN TI O MA WA
•Ile Eye Ega
•Okiti ogan (Ile Ikan)
•Epo Obo
•Odidi Agbon
•Ose Eyikeyi
BI AO SESE ISE YI NIYI
Ao gun Gbogbo Eronja yi papo Ninu odo (multer), ao fi Ose na ko, ao wa fo Odidi Agbon na, Omi re ni ao fi po Ose yi, ao ko sinu Ike Funfun.
LILO RE
Ao Mafi Ose yi we ni ojojumo pelu Gbolohun bayi wipe:
"Enu Ega ni Ega fi nkole Ti e pari"
Akotan ni ikan ma unko Ile ti e pari"
Kosi Eni kan Tio mo bi Omi Sede Inu Agbon,koye Eda kan
"Ona ti EMI LAGBAJA OMO LAGBAJA yi o fi ko ile temi pari, ki o mase ye Omo Eda kankan"
Ao wase ADURA si ki a to we Ose na.
IMORAN
Ile kiko kiise Ohun ti a ma npariwo re Ti a ba nko lowo o, Eniyan kofe ki a ru eru kaso, Ori Eni lo nsoni o👂
Iwo na Bami Comment, like, and share re fun Anfani Awon Elomiran!
Mogba ladura pe Gbogbo wa pata ni Eledumare ma kole Ayo Fun ooo🙏🙏🙏
Fun Ibere Tabi Ohun Miran Tabi ofe ki abo se kia gbe ranse si o
Whatssap :- 09133275017
08051996013
FOR MORE QUESTIONS ASK 👇👇
This is IYAOSHA ((Many Mother)) AGBOMOLA TRADOMEDICAL FOR ALL Native things, what do you want me to do for you? about your problem mention your problem I will know what to do for you in a Native way
if you want to discuss with me putting your message down or WhatsApp,, me, I will go true it, I will give you feedback call or Whatsapp me let talk about it .to no what to do this my WhatsApp number 09133275017 08051996013 or
My Link 👇
https://chat.whatsapp.com/BUV8jWvpNMMJPeUVHrwrZ6
me, I will go true it, I will give you feedback call or Whatsapp me let talk about it .to no what to do this my WhatsApp number 09133275017