15/08/2025
OKO ORUN / OKO ORU....✍️
⚠️⚠️⚠️⚠️⚠️
Oko meji ni ayan Mon Obirin
Oro Asiri Nla Nipa Oko Orun
Ati Oko Oru, Hmmmm 🙊
opóo eniyan ko ló mon iyató larin awon mejejí..
Opóo Obirin ni awon isoro mejeji yii tí dà aye won là mun atí opóo ilé lo tí kun fun ijà ati wahàlàh Nipa se Oko Oru ati Oko Orun.
Sugbon 👉 ise won yato si ràa won sugbon kise pupo eniyan ló móo iyató larin won.
Kini Ohun Iyató nbé 🤷
Ohun nipé Oko Oru loó ma wa bà obinrin tise iyawo ré ni ajosépó ni igbà to bà wú
lati ri Ololufe ré Owón..
Oko Oru mà wà pelú igboyà ati ifokanbalé nitori pe akoko to ba ma wà kosi nkankan to ma da duró nitori nàa NI o sé yan oju orun ni ayanfé ré lati lé wa mà sé isé bi ré, nitori pe oru lo lé ri Ise owo re sé, sugbon eyi to tí gbóo to tí gbà dun Ololufe ré dàdà kosi igba ti oun kole wa, lósan ati Owuro tabi iyàletà kosi okoko ti kole wà nitori pe otí pé tí oti mà wà nbé.
🤷 oti di adun ifé larin won...
Awon Damage Ise Owo ✋ Oko Oru nipe, o ma ba oyun je ninu Obirin tabi ki o ma je ki Obirin naa ni Omo laye Nipa sé pé o ma bà lé oyun naa tabi Obirin nàà ao sese ki iru eniyan nbé ma tete loyun ta bi bimó... Oko Oru re Igbadun tó wa larin ohun ati Obirin nàa lo ma fàa ko ma fun Obirin nà ni aye ati loyun tabi bi omo... Sugbon kise gbogbo Obirin Loni Oko Oru
OKO ORUN JE EYI TO NI AGBARA
JÚ LÓ KO KI TETÉ LO BÓ RÓO
FUN GBOGBO OBIRIN.👌
Oko Orun je Okurin oké eyi tó le dà Ara tó wu ni akokó to wú, ohun ló ma dà Ile rú ohun lo ma dà irin ajo Obirin la mun ati oko ré papó koni je ki awon mejeji ni isimí koni si ifokanbalé wahalah lótun wahalah losi, orisirisi ona lo ma ma fi da rin Ajo Okurin nàa la mun, ti Okurin nàa a fi mo pé Obirin ti ohun fé lo sé okun fà awon isoro ti ohun làa kojà, nitori pe o ma dorí gbogbo nkan kó doó tóje pe atijéun ati mun yoó ni agbara yóo dógun. Ija ni gbogbo igba
HMMM ....🤔🤔🤔
Ayàa fí ko wà opin si awon mejeji tabi eyi ti o bàa Mon pe o doju kóo ninu won.
Jóor mà gbà si ràa won wóo
Iyató kadegbe wà larin won
Sugbon 👉 Oko Oru lo ma lo fi Oru boju lati fi se ise ibi papa julo awon ika eniyan Maa nlo oko/aya Oru lati fi gba kadara eniyan,
Fun ALAYE ati ona abayo, call or message on
WHATSAPP NUMBER
09051598260 / 08147543150
゚ ゚viralシviralシfypシ゚viralシalシ
Asiri Irawo Akosejaye Ebe Adua Ati Ona Abayo 09051598260 / 08147543150
Asiri Irawo Akosejaye Ebe Adua Ati Ona Abayo 09051598260 / 08147543150
ASIRI IRAWO, EBE ADUA ATI ONA ABAYO, ( SPIRITUAL WAY OUT ( 09051598260 )
Asiri irawo, ebe Adua ati ona abayo 09051598260, 08147543150