28/06/2025
OSE_TIA_FI_NWE_OWOKOWO_KURO_LARA.
(1) Obi abata oloju meta
(2) Ewe iyalode meta
(3) Ewe akoko meta
(4) Ose die.. Eyikeyi ose
SISE_RE:-
Ao pa obi yi, ao mu awe kan pelu ewe iyalode kan, ewe akoko kan ao lo kuna daada, ao wa pomo ose iwe ekan soso, ao se be lona meta, ao fi ori para ti aba fe we ni akoko, epo pupa ni ao koko fi para ti a bafe we ikeji, eyin ororo ni ao fi para ni ojo iketa, ao we ni ojo aiku, ojo aje, ati ojo isegun.
IKILO PATAKI:- RIDAJU WIPE O FI COMMENT RE SE ADURA TOBA WU E FUNMI, TI O BAFE KOSISE FUN O(LIKE COMMENT AND SHARE. MASE AFOJUDI OO KOLEJE FUN OO)
IWO TI ISENA BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE ABI TI O MA BI OSE FESE MOLE SE FUN YIN PE NUMBER MI TOWA NISALE ABI KO MESSAGE MI LORI WHATSAPP.
LATI OWO OLUDASILE YARA asiri Osole todaju adebayo lfatunde
FUN IBEERE ABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI OGUN TI OUN DOJUKO CALL OR WHATSAPP TI O BANI IGBAGBO 07012678483