EwE NjE BeE Backup

EwE NjE BeE Backup IWULO EWE ATI EGBO FUN IWOSAN, ITUSILE ATI ILOSIWAJU PELU AWON AWORAN ERANKO EWE PELU EGBO.

Kini oruko ewe yi
25/07/2025

Kini oruko ewe yi

Nje e feran lati maje iru obe yi?
25/07/2025

Nje e feran lati maje iru obe yi?

Ewo eranko yi,iru eranko wo lojo
25/07/2025

Ewo eranko yi,iru eranko wo lojo

Kini oruko eso yi
25/07/2025

Kini oruko eso yi

Kini oruko igi yi
25/07/2025

Kini oruko igi yi

AWOROori ako ati abo alangba aojomo odidi atare kan aofi iyo die si aoro sinu ato aosoko inu ile abi shop.aonide lenu
22/07/2025

AWORO
ori ako ati abo alangba aojomo odidi atare kan aofi iyo die si aoro sinu ato aosoko inu ile abi shop.aonide lenu

Nje o mo bi won se nlo nkan mejeeji fun ogun anu bi? Se ki fi kale fun ile 🍃
22/07/2025

Nje o mo bi won se nlo nkan mejeeji fun ogun anu bi? Se ki fi kale fun ile 🍃

AWEBI WEPE DANUAo lo wa epo obo die ao gun mo ose dudu pelu ewe bomubomu ao lo fi we lodo lekan soso.
22/07/2025

AWEBI WEPE DANU
Ao lo wa epo obo die ao gun mo ose dudu pelu ewe bomubomu ao lo fi we lodo lekan soso.

ASEJE OWOewe abamoda kan ewe ogbo kan aolo pelu ata ijosi aofise igbin ilako kan je lepo niyo
22/07/2025

ASEJE OWO
ewe abamoda kan ewe ogbo kan aolo pelu ata ijosi aofise igbin ilako kan je lepo niyo

EBE AWON AGBAEPO AKOKO, PELU EWE AKOKO AOGUN PO MO OPOLO KAN ATI EPO OBO, AOGUN GBOGBO PO OSE DUDU AOFI EPO PUPA DIE PO ...
20/07/2025

EBE AWON AGBA

EPO AKOKO, PELU EWE AKOKO AOGUN PO MO OPOLO KAN ATI EPO OBO, AOGUN GBOGBO PO OSE DUDU AOFI EPO PUPA DIE PO MOSE ,ALE NI WIWE RE TIA BATI FE SUN TI AKO NI JADE SITA MO LAMA WE NWE PELU KANKAN TUNTUN LAMA FI MA WE T**I YIO FI TAN.

AGADAGODO ETI Ori eku kan, ori èja kan, akan oke kan, isawuru kan, afomo igi kigi, atare aja kan, ao jo papo, ao di mo a...
20/07/2025

AGADAGODO ETI

Ori eku kan, ori èja kan, akan oke kan, isawuru kan, afomo igi kigi, atare aja kan, ao jo papo, ao di mo agadagodo. Ofo-rè: èja ki roju wole to eku, bèni eku ki roju wole to èja. Alakan ki roju wole to isawuru, bèni isawuru ki roju wole to alakan, Airoju, airaye ni ko si ni jè ki won wolé to ara won. Bèni airoju, airaye ni kijè ki Afomo tagbo wolè. Airoju, airaye yèn ko lo ba lagbaja, airoju airaye loba atare aja ni ojo kinni lo fi jè pe, apo odidi toda omo sinurè lonkisi, ohun na lo ba èja ti ko fi roju wa eku losi papa. Airoju, airaye na lo ba Eku ti ki fi roju wa èja lo si odo oluwèri, ki lagbaja mase roju raye lati wami wa mo o. Ao ti agadagodo na pa. Otan tested laimoye igba

AWORAN EWE TI E NWO NI NISALE YI NI WON NPE NI EWE JINWINNIASEJE ASIRIBIBO ODAJUewe jinwinni, ewe etiponla eyo 7,epo jeb...
20/07/2025

AWORAN EWE TI E NWO NI NISALE YI NI WON NPE NI EWE JINWINNI

ASEJE ASIRIBIBO ODAJU
ewe jinwinni, ewe etiponla eyo 7,epo jebo die,ewe aje,igbin agbonu kan, aoge igbin naa si meje,ata ijosin niwonba,
Lilo papo ao fi se igbin naa je lepo niyo,
Ao koje ni gbigbona,
Ifa o gbo Odaju,
Edumare yio fi albarika si

Address

Ijebu Ode

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00
Saturday 09:00 - 17:00
Sunday 09:00 - 17:00

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when EwE NjE BeE Backup posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share