ISESE LAGBA ASIRI

ISESE LAGBA ASIRI Fun iwo ti o nwa Promotion Tabi Obinrin ti o nwa Ọmọ bibi lati ọjọ Pipẹ,Fun Ajo Owo ,

31/12/2025

Happy new year ẹyín ènìyàn mí ìbẹ̀rẹ̀ oṣù yí igbega, ìtẹ́síwájú, ise réré ní yíò jẹ́ fún gbogbo wá óò Ọ̀nà yíò là fún wá láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏🙏🙏❤️❤️❤️💖💖💕♥️♥️✨️✨️🎈🎈🎈🎈💸💸💸💵💵💵💵💵🎁🎁🎉💋✨️✨️✨️♥️♥️🎈🎈🎈🎈♥️

Aku ọdún óò ẹyín ènìyàn mí  Ẹ má gbàgbé ǹkan ọdún mí óò  Ẹ̀mí wá yíò ṣé ọpọ ọdún láyé óò láṣẹ Elédùmarè Mò nifẹ gbogbo y...
31/12/2025

Aku ọdún óò ẹyín ènìyàn mí Ẹ má gbàgbé ǹkan ọdún mí óò Ẹ̀mí wá yíò ṣé ọpọ ọdún láyé óò láṣẹ Elédùmarè Mò nifẹ gbogbo yín lọkunrin lóbìnrin óòóò 💯 ♥️♥️♥️💛💙💙💙❤️💗❤️💗💗🎈🎈✨️✨️✨️

Ẹkarọ sir Ẹkarọ má óò ẹyín ènìyàn mí Ṣé dada lẹjí óò
31/12/2025

Ẹkarọ sir Ẹkarọ má óò ẹyín ènìyàn mí Ṣé dada lẹjí óò

Mo kí ẹyín ènìyàn mí lowurọ yí ní òní ọjọ́ Monday ọjọ́ Ajé wípé Ẹkarọ sir Ẹkarọ má óòóò Ṣé dada lẹ jí óò Òní ọjọ́ Ajé Mo...
29/12/2025

Mo kí ẹyín ènìyàn mí lowurọ yí ní òní ọjọ́ Monday ọjọ́ Ajé wípé Ẹkarọ sir Ẹkarọ má óòóò Ṣé dada lẹ jí óò
Òní ọjọ́ Ajé Monday
Ào rí tí Ajé ṣé óò
Ajé yíò wá wà rí óò
Ào rí Ajé jẹun, Ào rí Ajé mú, Ào rí Ajé ná ó
Lóni ọjọ́ Ajé Monday Ajé kòní sá fún ẹnì kánkán wá óòóò
Ào rí Ànu gbà óò
Ànu yíò fọhun nínú àyè ẹní kánkán wá óò
Lóni ọjọ́ Ajé Monday ọmọ aráyé kòní bọ bàtà ọfọ bàtà ẹkùn sí ẹnu ọ̀nà ẹní kánkán wá òòò
Ào rí owó ná, Ào rí owó lò óòóò
Láti òní lọ ilẹkun Ànu yíò sí fún ẹnì kánkán wá óòóò
Àpò sasamura kí ń gbẹ Tọtun tòsí ní Ẹyẹlé fí nko irè wọlé Àgbìgbò ní fí orí ara rẹ dì ẹrú lọ fún oluigbo Ọtí jókò jẹjẹ àrà rẹ tí gbogbo ọmọ aráyé ńfí owó ńwá kákiri Láti òní ọjọ́ Ajé lọ ọmọ aráyé yíò fí owó ńláǹlà má wá ẹní kánkán wá rí óò
Ẹyín ènìyàn mí Ẹ sọ wípé Ajé fí ilé mí Ṣé ibùgbé lóni óò
Láti òní lọ Ajé Ajé Ajé Ajé yíò fí ilé ẹní kánkán wá ṣé ibùgbé láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏🙏🙏

Mo kí ẹyín ènìyàn pé aku ìsinmi òní ọjọ́ Sunday to gbẹ̀yìn nínú ọdún 2025 ,Ẹ̀mí ẹní kánkán wá tí ó rí Sunday òní yí yíò ...
28/12/2025

Mo kí ẹyín ènìyàn pé aku ìsinmi òní ọjọ́ Sunday to gbẹ̀yìn nínú ọdún 2025 ,Ẹ̀mí ẹní kánkán wá tí ó rí Sunday òní yí yíò tún rí 2026,Ẹ̀mí wá kòní bá ọdún 2025 yi lọ óò
Ìdàmú kòní dé bá gbogbo wá ,ìjáde wá, Ào ní jáde lè ikú àti Àrùn àti Ajinigbe lọ́wọ́
Bí aṣé njade, Ào má lọ rè, Ào má bọ rè
Ào má rí ṣé,Ào rí owó ná,Ào rí owó lò, Ào rí owó fí ṣé ǹkan réré ,Ẹ̀dá owó kòní dà ẹní kánkán wá, Ajé ní mò pé, Ajé ní mò pé, Ajé ní mò pé Ajé yíò fí ilé gbogbo wá ṣé ibùgbé láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏🙏🙏

Ẹkarọ sir Ẹkarọ má ẹyín ènìyàn mí Àsì kú ojúmọ́ òní óò ojúmọ́ irè ,ojúmọ́ Ayọ ní yíò jẹ́ fún gbogbo wá láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏...
27/12/2025

Ẹkarọ sir Ẹkarọ má ẹyín ènìyàn mí Àsì kú ojúmọ́ òní óò ojúmọ́ irè ,ojúmọ́ Ayọ ní yíò jẹ́ fún gbogbo wá láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏🙏🙏

Ẹkarọ sir Ẹkarọ má ẹyín ènìyàn mí,Mò kí yín wípé aku ọdún àná óò Ẹ̀mí ẹní kánkán wá yíò ṣé ọpọ ọdún láyé láṣẹ Elédùmarè ...
26/12/2025

Ẹkarọ sir Ẹkarọ má ẹyín ènìyàn mí,Mò kí yín wípé aku ọdún àná óò Ẹ̀mí ẹní kánkán wá yíò ṣé ọpọ ọdún láyé láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏🙏🙏

25/12/2025

Mo kí gbogbo ẹyín followers mí pátápátá nílé lóko lajo níbí gbogbo ní àgbáyé wípé Ẹkarọ sir Ẹkarọ má Asi kú ọdún òní óò Ẹmi ẹni kánkán wá yíò ṣe ọpọlọpọ ọdún láyé láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏🙏🙏🥂❤️❤️❤️🥂🥂 Mo wá pẹ̀lú yín ní gbogbo ìgbà òòò Ayọ̀ àti Àlãfíà ní gbogbo wá yíò fí ṣe ọdún óò láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏🙏🙏🥂🥂🎉🎉❤️❤️❤️❤️🎈🎈🎈🎈🎈🍷🍷❤️❤️

[             Àdúrà Owurọ ọjọ́ Ajé                ]Ìjáde wá lowurọ òní ọjọ́ Monday ọjọ́ Ajé, Ào ní jáde lè ikú lọwọ, Ào ...
22/12/2025

[ Àdúrà Owurọ ọjọ́ Ajé ]
Ìjáde wá lowurọ òní ọjọ́ Monday ọjọ́ Ajé, Ào ní jáde lè ikú lọwọ, Ào ní jáde lè Àrùn lọwọ, Ào ní jáde lè Ajinigbe lọ́wọ́
Eni Monday ọjọ́ Ajé Èdùmàrè jẹ́kí á rí tí Ajé ṣé lóni tọmọtọmọ
Ojúmọ́ tí ó mọ̀ wá lóni ojúmọ́ irè ní ojúmọ́ Ayọ̀ ní ojúmọ́ ìdùnnú ní fún gbogbo wá
Lóni ọjọ́ Ajé, irè, Ìtẹ́síwájú,igbega yíò dé sí ẹnì kánkán wá
Ào rí Ànu gbà lóni, Ànu yíò fọhun nínú àyè ẹní kánkán wá lóni
Ào rí owó ná, Ào rí owó lò, Ào rí owó fí ṣé ǹkan réré, Láti òní lọ owó ńláǹlà yíò má wọlé fún ẹnì kánkán wá
Ajé óò Ajé óò Ajé óò Ajé wá fí ilé ẹní kánkán wá ṣé ibùgbé lóni láṣẹ Elédùmarè Àmín Àmín Àmín Àṣẹ Èdùmàrè 🤲🙏🙏🙏

ÒGÚN ASEJẸ́ AWURE AWỌRO TÍ Ó DÁJÚ Ẹkarọ sir Ẹkarọ má ẹyín followers mí pátápátá nílé lóko lajo níbí gbogbo ní Àgbáyé Àsì...
21/12/2025

ÒGÚN ASEJẸ́ AWURE AWỌRO TÍ Ó DÁJÚ
Ẹkarọ sir Ẹkarọ má ẹyín followers mí pátápátá nílé lóko lajo níbí gbogbo ní Àgbáyé Àsì kú ìsinmi òní óò ẹ̀mí ẹní kánkán wá yíò ṣé ọpọ ìsinmi láyé láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏🙏🙏
isẹ yí bí ó ṣé kéré ó lè má jọ ẹní kánkán lójú, Amọ́ bí ó ṣé kéré yí Ògún ní ẹyín ènìyàn mí
isẹ ná rè ẹyín ènìyàn
Ào lọ rà Èdè fúnfún pupọ díẹ̀, Ào lọ já ọjẹlẹ Èwe ọpọtọ díẹ̀,Ào lọ pẹ̀lú ata ìjọsì díẹ̀, Ào wá fà sínú ìkòkò Asejẹ́,Ào wá dà èdè fúnfún ná sí, Ào fí èpò àti iyọ̀ sí, Ào ṣé jìnà tí ó bá tí jìnà tán, Ào sọ sórí ǹkan kán ìdí rẹ kò gbọdọ kán ilẹ óò, tí ó bá tútù, Ào wá gbé,
Ọfọ rẹ sínú Asejẹ́ ná
Ọmọ Èdè kán kí ndá rìn Èdè má ńpè jọ rìn ní ,Kí gbogbo ọmọ aráyé lọkunrin lóbìnrin kí wọn má péjọ fí Isẹ ńláǹlà pẹ̀lú owó ńláǹlà wá èmi lagbaja ọmọ lagbaja rí láti òní lọ, Isẹ yí dájú gàn ẹyín ènìyàn mí.
Yíò jẹ́ fún yín yíò tún bayin lára mú láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏🙏🙏

Fún ibere tàbí ǹkan míràn
Fún iwọ tí o nwa Promotion
Tàbí Ìwọ tí wọn fí ogún alakala ńbá ńjá ní gbogbo ìgbà
Tàbí Obínrin tí ó ńwá Ọmọ bíbí láti ọjọ́ Pipẹ,Tàbí Obínrin tí Ọkọ Ọrùn ndá lamu,Fún Àjò Ajé, Fún Court case,,Lati má rí Ànu gbà dada, Fún Promise and Fail, Fún Ìkọ Asmar, Láti má rí Ojurere làti ọwọ́ Ọgá, Láti lówó kíákíá Fún Iwọ tí o ntà ọjà, fún travel, Ànu Alanu, Awọro Ọjà, Ọba Ẹyọnu àti bẹbẹ lọ. e.t.c Ẹ pèmí sórí number yi tàbí kí ẹ message mi lori Whatsapp number mi 09065621220.

Mo kí ẹyín followers mí ẹyín Olólùfẹ́ mí ẹyín ènìyàn mí ní owurọ yí wípé aku ojúmọ́ óò ilẹ̀kùn Ànu,ilẹ̀kùn ìlọsíwájú, il...
20/12/2025

Mo kí ẹyín followers mí ẹyín Olólùfẹ́ mí ẹyín ènìyàn mí ní owurọ yí wípé aku ojúmọ́ óò ilẹ̀kùn Ànu,ilẹ̀kùn ìlọsíwájú, ilẹ̀kùn igbega yíò ṣí fún ẹní kánkán wá lóni láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏

Ẹkalẹ sir Ẹkalẹ má óòóòóò ẹyín ènìyàn mí ,Bí gbogbo yín ṣé ń follow mí tí ẹ ń tẹle mí gbogbo yín pátápátá òkè òkè ní ẹ ó...
19/12/2025

Ẹkalẹ sir Ẹkalẹ má óòóòóò ẹyín ènìyàn mí ,Bí gbogbo yín ṣé ń follow mí tí ẹ ń tẹle mí gbogbo yín pátápátá òkè òkè ní ẹ ó má lọ ẹ ní di èrò ẹyín láṣẹ Elédùmarè 🤲🙏🙏🙏

Address

24 Old Benin Road Ijebu
Ijebu
110001

Telephone

+2349065621220

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ISESE LAGBA ASIRI posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to ISESE LAGBA ASIRI:

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram

Category