27/01/2026
EYI DIE NÍNÚ ÀWỌN ASIRI TO WÁÁ NÍNÚ IWE OÒGÙN IBILẸ TÓ-DÁJÚ TI AA GBÉ JÁDE LATI OWO
Bàbá Ọlọrun-Aiku Home of Traditional Spiritual solutions To Life Challenges
PRICE FIRST EDITION 85,ooo Naira
SECOND EDITION 5o,ooo Naira
EYI NI OGUN TALE FI TA ILE (HOUSE)TABI TA ILE(LAND)
Ti o ba je ile tabi ile.....iyepe ile yen, ewe ejinrin wewe, ewe efo odu..orii, omi agbon to po daada. Ao gun gbogbo re papo, ao fi die ninu omi agbon yen po ose yi....ao ko sinu ike kan.
LILORE... ao bu die ninu ose yi, ao po ninu omi agbon to po daada, ao lo fi wan ile naa... odaju.
Ti o ba je wipe motor tabi nkan miran ni..... Efo odu, ewe ejinrin wewe, orii, ao gun papo mo ose ni ilele lasan ti yio fi yi iyepe...ao maa fi fo motor naa. Odaju
AWURE TI AFIN TA ILE TABI ILE (HOUSE)
ITO AIFOHON OYIN IGAN GIDI AO FI RO AGBADO FUNFUN AO WO LO WON SORI ILE TABI INU ILE NA (HOUSE)KIAKIA LAMA RI ILE NA ATA
ELEYINI OGUN TO N SISE FUN ENITI ORA ILE TI AWON AJUNILO TUNFE GBA ILE NA LOWORE.
ALUBOSA FUNFUN NLA KAN
IYO(salt) DIE
A*O ORI AKITAN
AO LA ALUBOSA YI SI MEJI
AO BU IYO SI APAKAN AO TE NI IFA EJI OGBE
AO FI IKEJI BO AO FI OWU ETUTU DIPO DAADA
AO FI A*O ORI AKITAN WE DADAA AO WE NI OWU FÚNFÚN ATI DÚDÚ,AO GBE ILE AO JU SINU ILE NAA,AO WA YAGBE LE LORI,AO MA SOPE OJO TI ALUBOSA YI BAWU NI KI WON TO ROJU WASI ORI ILE YII NITORIPE AKINFI ORO ILE BI AKITAN.,
ARIMOLE TI AFI NPARI ILE (HOUSE) NI KIAKIA:
Odidi eye etu kan aoge ori ati esere mejeji soto. Aotu gbogbo iyẹe ara re ti eyokan kogbodo din nibe a oó dá iyẹe sinu apẹe ijoogun
Aofi atare odindi kan si aojo pomno ori ati ese re yen aolo kuna dada, Aoda ebu yen sinu ike funfun kekere kan aode pa aowa lo bo mo ori ile na ni arin meji ile na, Aofi eye etu yen se sara fun awon eyan tabi ki ase lobe ki alo gbefun oni bara.
IKILO: Aogbodo je ninu eye etu yen o iye arare ti atu kogbodo din kan. Odaju
OGUN TI AMARIMOLE FUN ILE KIKO
Àá oó lọ jaa Ewé Akoko ao gun kunna dada awa pomo ori awafi boo
Ìgbín ti oó baà gbonu lara ti ará rẹ kankan kò níí hàn sí ìta a oó wá lọ rí mo àárín ile tabi ile akọoku nà
Odaju
OKIGBE ATI MARAN OTA IBON TODAJU
Ao wa opolo ijokun ooye nla kan odidi atare kan, ao ju opolo ijokun yi sinu omi die ao fi omi yi bo Lori ina jina dada ti opolo yi yio fo petepete ti yio ro ao yo polo yi sinu ape ao fi omi ti afi se opolo yi jina po ogi fun fun leyina ao wa Jo opolo yi pelu odidi atare kan ao lokuna ao wa da gbogbo ebu yi sinu ogi funfun yi ao gbe mu lekana patapata asiri yi daju okigbe ati maran ota ibon ni, asile fi die ninu ebu naa singbere yipo ori wa, odamiloju pupo gan ni o.
AJESARA OKIGBE ATI OWO IBON TODAJU
Ào wa Egungun aja tiwon fi bo Ogun, egungun elede, awo iki, odidi atare kan ào jopo ao fi sin gberen meta meta lorikeriki ara wa, tiwon ba sa wa koniran wa tabi kiwon da enu ibon kowa koni dun beeni o da pupo.
*ELEYII NI OKIGO ORI TODAJU
_Ewe alupaida meje, eyo atare meje, ao jo papo ao fisin gbere meta meta sori legbe otun ati osi..
*ELEYII NI OKIGBE TODAJU
_Opolo kan ewe alupaida mesan, ewe abamoda mesan, ao jopo ao dasinu a*o funfun ao dinikobere ao ran ni ifunpa...✍️_
*ELEYII NI OKIGBE TODAJU
_Gbogbo ifun ako alangba, ao jo pọ mo odidi atare kan ao fisin gbenren meta meta si egbe wa mejeji..
*ELEYII NI OKIGBE TODAJU
_Ori ako alangba kan, ao ki oruka bo lenu, eyo atare meje ao we lowu dudu ati funfun ao ran ni ifunpa.
*ELEYII NI OKIGBE TODAJU
_Ikode kan, etu ibon oyibo, egungun ori aja tiwon bẹ fun ogun gbígbẹ, ao lo papo ao fisin gbere yika ori wa ni sale irun..
*ELEYII NI ỌWỌ AYETA IBON TODAJU
_agolo rub kekere, ao ko eyo atare mesan si, eso afola mesan si ao de ao we lowu dudu ati funfun, ao mafi sara jade...
*ELEYII NI OKIGBE TODAJU
_Opolo ijoku kan ao ko oruka si ninu ao lori mon ori akitan di ojo keta pere..
*ELEYII NI AYETA IBON TODAJU
_Oju olongbo merindinlogun, eyo atare merindinlogun, ao dini a*o pupa ao mafi ara jade
*ELEYII NI OGUN AYETA IBON TODAJU
_Orogbo kan, ewe alupaida, odidi atare kan, ewe awerepepe, ao fi owo wa ja ibepe dudu kan tikogbodo kan Ile, ao jo papo ao fi sin gbere lati iho orun de isale beni lati eyin orun nan dele
*ELEYII NI OKIGBE ATI IBON TODAJU
_Egungun aja tiwon fi bo Ogun, egungun elede, awo iki, odidi atare kan jijopo ao fisin gbere meta meta lorikiriki ara wa. Ti won ba sawa koniran wa tabi kiwon da enu ibon kowa ota yen yio ma da sile...Yóò jẹ fún wa pẹlu ògo ọlọrun ọba ooo