Balogun asiri isenbaye

Balogun asiri isenbaye BALOGUN ASIRI ISENBAYE TRADOMEDICAL CENTER Fun iwosan ati fun igbeyanju omo eniyan.

21/04/2024

ASEJE BIBO ASIRI TODAJU

04/12/2023

Aku Ojo meji meta ninu ile alayo yio
Emi omo yin na ni Balogun asiri isenbaye mo ki gbogbo omo egbe lapapo wipe aku osu tuntun, asi tun kun imura odun tuntun ooo, mo ki wa wipe yio bawa laye ati laye to dara.(ASE)

26/06/2023

EYONU AWON AGBALAGBA TODAJU TARA
EWE OYOO (EWEDU)
EPO PUPA
ORI
ADIN DUDU
OSE
IGBA AJE
SISERE:
Ewe oyo (ewedu) . Ao ja ti yio po die,Ao gun mo ose Ao fi epo pupa si pelu adin ati ori,A o fi eroja meteeta yi po daada.A o wa ko ose yii sinu igba aje na, a o lo gbe si ibi ti orun ti maa pa ti yio yo papo daada,leyin ojo meta la maa bere sini lo.
Gbolohun re: la maa pe si ose yen ninu igba ka to wa bu iwonba ta maa we.
Gbolohun re: bi orun ba yo, inu ori ayo.oso ile aje ile ori loni ki e yonu simi,ooyo loni ki e yonu simi borun ba yo, inu adin a yo, tokunrin tobinrin e yonu simi,borun ba yo inu epo ayo, tomode tagba e yonu Simi lagbaja omo lagbaja
Ise yi daju lopolopo
COMMENT,SHARE KI O SI LIKE RE,KI ISE LE JE FUN E.

26/06/2023

IWURE OJO AJE
AJE OGUGUNISO OOOO
AJE OGUGUNISO ONISO BOJI
AJE ALADE OWO WA FI ILE GBOGBO WA SE IBUGBE.LONI OJO AJE AJE WA BA WA GBE TOWO TOLA ALAFIA AIKU BALE ORO.AJE FI ODEDE WA SE ILE OOO(ASE)

IWULO EPO OBO FUN ORISIRISI IWOSAN ATI ITOJU ARA.1.Ki Owo aje ma tewa: Ao lo epo obo ti yio kunna.A o da sinu omi toba l...
25/06/2023

IWULO EPO OBO FUN ORISIRISI IWOSAN ATI ITOJU ARA.
1.Ki Owo aje ma tewa:
Ao lo epo obo ti yio kunna.A o da sinu omi toba loworo (togbona die) lowuro kutukutu. Ao fi we pelu ose tobawu wa.
2.AROBI:Epo obo lilo pelu iyo ati eru inu aro,ao po meteta papo mo ose dudu,ao ma fi we ni aro kutukutu pelu adura.
3.EYONU TO DAJU:
Epo obo,a o jo pelu odidi atare kan, ti oba ti fe jo tan,a o ju ori sinu agbada na, a o lo ti yio kunna daadaa, a o ma fi foko mu lalale.
4.EYONU:
Ao gba epo pupa lori ina ti o ba ti gbona dada, a o da epo obo Lilo si,a o fa ra ba le kogbona dada, a o yo epo na, epo obo to wa ni be ni a o po mose, a o ma fi we, ao si ma la epo na leyin iwe.
5.EBE AWON AGBALAGBA: Igbe adie ati epo obo pelu atare odidi kan,a o jo po, ao po mon ori. a o ma bu sinu eko gbona lararo a o ma mu.
Fun ibeere 08136763067
KI O LE JE FUN YIN SHARE,COMMENT ATI LIKE.

Address

Kwara State Ilorin
Asa

Telephone

+2348136763067

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Balogun asiri isenbaye posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category