15/01/2023                                                                            
                                    
                                            EWA IFE!
Egbin lo EWA IFE!
Egbin lo dara ju ninu eranko,
Okin lo rewa ju laarin eye,
Oje ori akuko lewe akuko,
Ife ni ewa ile aye.
Gbedogbedo fi igi omo se igi loso,
Amokoko fi apadi se ewa ikoko,
Onirese fi aro dara si igba lara,
Eleduwa fi ife se eso ile aye.
Ododo rewa ninu ogba,
Tetenboto n rewa lawujo efo,
Orunla dun ri loju gegebi obe,
Ife dun kaakiri aye.
Ife di suku si ori bi iyawo osinkin,
Ife kun atike o yo bi iyawo elese osun,
Ife ta gele, o wo a*o to se regi lorun,
Ife rewa o ka mama.
Kin ni ewa ife gan na,
Otito inu ni ewa ife,
Ifokantan lo pari oge si ife lara,
Igboara eni ye yeke yeke lo ri bi lofinda fun ife.
Ifi oro ro ara eni wo la*o aran lorun ife,
Amojukuro oun aforiji ni ileke orun ife,
Ifarada oun ifarajin ni dandogo a*o eye e,
Ibowo fun ara eni ni esiki to ye lorun ife.
Suru laga ola ti ife fi n joko,
Itelorun ni ibusun ti ife fi n sun,
Ikun ara eni lowo ni irori ti ife fi n rori sun,
Fifi ohun tutu ba ara eni lo ni a*o ibora ife.
Ewa ife ni ile ti a ko rigidin ti ife n bani gbe ibe,
Ife ni n je ki a fi idunnu wo a*o ko duro lara,
Ife lewa ile oun ni oso oju ona,
Ife lo ye laarin ebi to alajobi ma da bi edun.
Omo Ajanlekoko lo ni ewa ife dun ju ewa iganyin lo,
Iwa lewa ife, bi a ba se huwa si ife ni ife fi n pe,
Ife rewa ju omoge asiko lo bi eyin o mo,
Ewa ife ni n je ki emi eda gun, ko si tun dEWA IFE!

Ewa ife ni n je ki emi eda gun, ko si tun dun ri laarin jomoh.EWA IFE!

Ewa ife ni n je ki emi eda gun, ko si tun dun ri laarin jomoh. 
AshakeOmoEmi Healing Home Care's. Happy Sunday to you all