21/06/2024
ỌṢẸ ÌYỌ́NÚ
Esuru pupa, ao gun papo mọ kanhun bilala to mu daadaa,,ao fi ọṣẹ dudu ko o, ao maa fI omi gbigbona wẹ ẹ lalaalẹ
ỌṢẸ RÍRÍṢE
Esuru pupa,ao gun pọ mọ ọpọlọpọ ọṣẹ,ao wa adiẹ pupa, ẹjẹ rẹ ni ao fi po ọṣẹ naa,ao lọ ri adiẹ naa mọ ori akitan,ao maa fi ọṣẹ naa wẹ lalaalẹ pẹlu omi gbigbona, ao fi kun bẹẹ ni ao yọ kuro, fi adura ranṣẹ ko le jẹ fun ẹ.
ASEJẸ AṢÍÍRÍ BÍBÒ TÓ JẸ́
Kidinrin maalu kan,ao ge e si ọna mẹrindinlogun, ao wa ewe tannagbowo ati itanna rẹ,ewe ajeṣẹṣẹfun, iyere mẹrindinlogun,ata ijọsi mẹrindinlogun, ao se e lepo niyọ, ao sọ kalẹ sori oṣuka, ao wa gbadura sii ṣugbọn ko le mu wa kọja aadọta naira o,kii ṣe oogun owo o,aṣiiri bibo lasan ni.lẹyin oṣu kẹta ni o tun le dan an wo.
OÒGÙN ÌSỌ̀YÈ
Ẹye awoko, eye ẹga, ewe oniyeye, odidi atare kan, jijo pọ,a maa da sinu oyin, lila ni o.
AWO IGBA ÀÌSÀN
Tagiiri kan, ao wa ge si wẹwẹ,bara kan ao ge si wẹwẹ,eepo ọsan wẹwẹ ẹru alamọ, kanhun bilala, awusa tutu, ata adayeba, jijo pọ ao da sinu omi ọsan wẹwẹ, mimu laarọ ati lalẹ.
OJÚLÓWÓ ÀGBO ÌWÒSÀN FÚN ÀFẸ́LÙ RỌPÁRỌSẸ̀
Ao wa ọpọlọpọ ewe gbaguda tutu,ewe pia(pear) tutu,ewe esuru pupa tutu, ataalẹ pupa (tumeric), ewe ọsan banbu, eepo ọsan banbu, eepo igi ati ewe koko(cocoa), kanafuru to pọ diẹ,ewe dongoyaro tutu, ao fi omi to mọ daadaa se gbogbo rẹ lagbo ti yo hoo daadaa,ao ma mu ni gbigbona ni gilaasi kọọbu kan laarọ, ati lalẹ fun ọjọ marun leralera,ao ni gburo aisan naa mọ, ẹniti ko ba tii ni rọparọsẹ naa le lo, atẹgun buruku ko nii fẹ lu wa o, awọn to ti ṣe maa gba iwosan laṣẹ Edumare.
OJÚLÓWÓ ÀGUNMU FÚN ÀRÙN ILÉ ÌGBỌ̀NSẸ̀ ỌLỌ́JỌ́ PÍPẸ́ TÓ DÁJÚ
Ko si bo ti le wu ki aisan ileegbọsan buru tabi pẹ lara to, ti o ba fi le fi agunmu yii lo ẹkọ gbigbona, o ni gburo rẹ, mọ alaafia to peye yoo si de ba agọ ara rẹ, ao wa ewe ati egbo iṣirigun gbigbẹ,ewe ati egbo agbosa, ẹfọ yanrin, ao sa ti yoo gbe,taba jukuu,ao sa ti yoo gbẹ,alubọsa aayu,ao sa ti yoo gbẹ,ao gun gbogbo rẹ kunna daadaa,ao tun fi ajọ jọ ọ,ao mo fi ṣibi imukọ ọmọ kekere kan sinu ẹkọ gbigbona laarọ kutukutuki a to jẹun,iwọ naa yoo si ri bi awọn nnkan funfun kan yoo ṣe ma jade nibi itọ rẹ, itọ naa yoo si ma run gidi gan,ma bẹru,awọn nnkan ti ko da lara rẹ ni o n tọ danu yẹn, lo leralera fun ọsẹ kan, ao tọ gbogbo rẹ danu, alaafia to peye yoo si de ba agọ ara wa, dan wo ko fun ile labọ. Yoo jẹ fun yin o.
AṢÍNÀ
Bi ọda owo ba da ọ, tete lo iṣẹ yii ṣugbọn rii dajupe o tẹle ilana o. Lọ wa ewe ṣawerepepe oojọ,ewe tannagbowo oojọ,ewe orijin oojọ
Iyere, igbin to gbo meji .Ao lo awọn ewe yii pẹlu iyere ti yoo kunna daadaa , lẹyin naa; ao wa ge igbin kọọkan si mẹjọ mẹjọ eyiti mejeeji yoo jẹ mẹrindinlogun, ao wa ko sinu isaasun ao da ẹbu ti a lọ sii lori, ao fi epo pupa diẹ sii ati iyọ pẹlu omi , ao wa se ti yoo jinna , lẹyin naa ao sọ ka ori oṣuka ao wa ṣe adura ka ri aanu gba ni gbogbo ọna ati iranlọwọ kiakia, ao wa jẹ ni gbigbona,laṣẹ Edumare iyanu ayọ yoo ṣẹlẹ
Ìkìlọ̀: A ko gbọdọ jẹ ki asejẹ yii tutu ti ao fi jẹ o, ti asejẹ yii ba fi tutu ki a to jẹ,iṣẹ o ni tete gbera, dupẹ ko le jẹ fun ẹ.
ÀGBO ÌWÒSÀN FÚN EEGÙN YÍYẸ̀, LAGUN LAGUN, SÁNGUN SÁNGUN FÚN ORÍKÈÉRÍKÈÉ ATA TÓ DÁJÚ
Ao wa aran ọpẹ to pọ daadaa,Aidan onigun to pọ,ewe atora,egbo atora,ataalẹ pupa (tumeric) to pọ diẹ, itakun peju owiwi,ẹru Alamọ,ewe arunpalẹ tutu,eepo oganho,eepo igi ose,ewe sobodiho,poporo ọka baba,eepo igi ọdan,ao ko gbogbo rẹ sinu oru agbo,ao fi omi ogi to bi lita marun se ti yo hoo daadaa,ẹni naa yoo ma mu ilaji kọọbu kan laarọ ati lalẹ,eegun to ti ye yoo to daadaa,awon aagun kan yo ma jade lara wa,orikerike ara yoo na daadaa,ao si ni alaafia to peye, dan wo ki o fun ile labọ.