Asayan Iwe Yoruba ati Litireso.

Asayan Iwe Yoruba ati Litireso. Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Asayan Iwe Yoruba ati Litireso., AIDS Resource Center, Ako area Ikire, Lagos.

03/10/2024
03/10/2024

Awon agba a ma pa owe kan_ e ko bi mi bi nwon ti npa a ndan? Nwon nib" Bi egun eni ba joore ori a ya ni" Toto o se bi owe o. Nko fe ki e jo ilu mi bi igbati yanmuyanmu ba njo ibenbe, ti o nta ese waiwai ti ese re ko si ba ilu dogba, sugbon kaka be ki e jo ilu na dada, ki e jo o tayotayo, ki e jo o terinterin, tobe to awon eniyan yio ma fi owo le yin lori, ti nwon yio ma ju a*o si yin loju ijo, ti awon okunrin yio ma dobale, to awon Obinrin yio si ma Kunle niwaju yin , nigbati ijo yin ba ndun mo won; Sugbon bi e ba so nfe ki ijo yin dara, ohun meji ni e ni lati se: ekini ni pe,.......

03/10/2024

Enyin ore mi, bi owe bi owe ni a nlu ilu ogidigbo, ologbon ni ijo o, omoran ni si imo o. Itan ti nho so yi, ilu ogidigbo ni; omi ni eniti yio lu ilu na, enyin ni ologbon ti yio Jo o, enyin si ni omoran ti yio mo o pelu......

03/10/2024

OGBOJU ODE NINU IGBO IRUNMOLE
This book is of 8 chapters, the 1st one is; Akara-ogun ati awon obi re.

03/10/2024

Good day everyone of both home and abroad! This page is created for the readings of some Yoruba books/ Literatures especially the old ones so as to bring to our memories of the past stories ( real or imagine). The past, the present and the future are very important in human life. Some of the literature we're to start with, are the past Yoruba literature written by D.O Fagunwa. The text are; (1)Ogboju ode ninu Igbo irunmole. (2)Igbo Olodumare . (3) Ireke onibudo. (4)Aditu Olodumare. etc.

Address

Ako Area Ikire
Lagos

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Asayan Iwe Yoruba ati Litireso. posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share