
14/07/2023
,EGBOGI ATUDE TABI ITUSILE TABI ASINA AWON AGBA
, ,(Medicine for witchcraft).
ise
egbogi yi fun e ni lati bori
agbara oso ati aje ati gbogbo
emi okunkun, alakala, ohunje
oju oorun, ibalopo oju oorun,
alantakun, orinrin, ati bee bee
lo. Eewo ni fun won.___________
__ odidi ologbo kan, odidi okete
kan, opolo meta, ekun asin
meta, oga meta, eso ido, eso
iwerenjeje, ewe ajeobale, ewe
ewuro, ewe oriji, ewe iyalode,
ewe mafowo kan omo mi dudu
ati funfun, egbo tude, ewe
ooyo, ewe akuku, ewe wowo,
ose dudu, igbin kan, ori adin ati
epo, eepo obo, odidi atare, ao
jo papo, ao lo ki o kuna, ose,
ipara, schinap, eko susu la o
maa fi lo. OPARI. Ti o ba lo
egbogi yi, gbogbo elemi
okunkun ni yio teriba fun e. Oo
si ri ogo re lo, ota re ti ko ba
deyin yio binu fi o le saye lo
sipo oku tabi aisan ni. DANWO.
07031370390. 09033344499. 08061610360. 08079278101. Fun eni ti o ba fe ki a fi egbogi yi sowo si ohun ki o si sanwo lehin ti o ba ti tee lowo lorile ede yi ati loke okun . #27,000. Pay after delivery.