22/02/2023
Ekasan gbogbo ile oo!,adeku ifarada iluwa yi....... Ejeagba ise kekere yi .
OSE TIAFI NWE ISE ATI EPE TI EYAN YIO SIRI ANAANU:
Aolowa ewe aje die, ewe alupaida die, ewe akisan die ewe ire, ewe ogo , , aowa ikarahun igbin NLA kan tokufun arare, aowa lo to yio kuna dada, ao ko sibikan aowa gun gbogbo awon ewe wonyen po, Aowalo ra tinu eran eledan die pelu eran re die, pelu oju otun tosi elede na ,.aowa gun gbogbo re po, aowa pomon ose dudu , aowa fi egungun agbarin elede yen tele igba olomonrin kan , aowa ko ose na lelori , leyin no, aowa gbon iyerosun le ose na Lori, aowafi ika fite odu IFA EJIOGBE BABA IFA lelori , aowa pe ofore le , aowa ma fiwe Laro , ni keta-keta.
GBOLOHUNRE:
Isapari awo adagba, okunkun ni aya obinrin oru , ki ota yeri , ki gbongbo kioyeba , ki ohun buburu kio deyin leyin emi L omo L loni, ki ohun rere kiola ona rere komi , alupaida wapa ori mi dasi rere , ewe aje loni kiegbe aje tuntun temi wafunmi loni, akisan loni ki aye timowa kosan sowo, sola, sinkan mere-mere, ogoomide omo elewiji , ire kansoso nimope , nire-nire nikoma jetemi loni, Motibawon ra eran odede loni o! Ejeki ara o demi o sowo salaafia,,. Leyin na owa se gbogbo adua tobawuwa si . aowama pe gbolohun yi nigba-kugba tibati feyi we ose yi. Kanhinkan ibile tiafi nwe no ni , aowama fi we, ao gbode fiwe ose imiran. yio bawa Lara mun oooooo!
LATI OWO MR FAKEYE OOSA
+2349037988740