24/07/2025
SIGIDI IROKO ABIJA WARA WARA
igi iroko kan
ewe ina mejeji
ewe esinsin
ewe oloyin
ewe sawerepepe
ewe abamoda
ewe ogbo
won ma bayin fi igi iroko yen gbe ni ere eyikeyi,too baje wipe ere okunrin ni wongbe ao mon peni baba, ao fun ni oruko kan too baje wipe ere obinrin ni wongbe iya ni , ao monpe ao lo bamin si idi alade Igbo waale , ao bamin gun kun noo daada pelu awon ewe yi ewe ina mejeji ewe esisi mejeji ewe oloyin
pelu ewe sawere pepe abamoda ewe ogbo Leyin tia gun kun na daada , ao po mon yepe yen ao pa odidi erankan , ao gba ejere oun lao fise omin tao fipo , ao mon oun ni ijoko fun
SIGIDI IROKO YEN , ao wa gbe sigidi yi le lori yio joko daada.
Leyin too ba gbe , ao mun awo eronja yi bakan na ao gbo
lomin
ewe ino mejeji
ewe oloyin
ewe airagba
ewe esisi mejeji
ewe imun
ewe ogbo
ao fi mon gbo sigidi yi lara bi igba taun we , ao mon je ki omin yen kio mon gbe mon ijoko yen laara t**i tao fi setan tia ba ti setan baun leyin ojo keta ao pa akuko adie fun ao mon fi epo pupa bo pelu iyo ati akuko adie fun isure , tia ba fe ranse ao mon fi ekuru dudu boo pelu adi eyan ao karabsun kio Loja , ao wawa awon ako ewe mererin ao gun mon iru ao fifi turare nidire pe eniyen lo dana mon laara kin se awooo.
Oma n sise Bidan ni.
Babalawo Ifatope Ajanaoro.