
30/09/2024
SCORPIO ♏
Je Irawo Omi tutu
Colours: Scarlet, Red, Rust
Ojo ti o dara ju fun irawo yi ni Tuesday
Pluto, Mars ni ondari irawo yi (Planet)
Ta**us ♉ Cancer ♋ lo dara ju fun Scorpio ♏ lati ma ba se. Nipa Fife o se pataki fun irawo yi lati se iwadi ti won ba fe fera won.
Scorpio ♏ bere lati October 23 - November 21
Won je eni ti owulo lawujo
Won je Akanda eniyan Won ni agbara
Won je akinkanju eniyan. Won ki beru
Won je ore otiito
Won je eni to ma ni Ife si eniyan
Won je eni to ma jowu (jealous)
Won ki saba gbayan gbo
Won feran wahala
Won mo bi won se le so nkan meji di merin
Won feran ibalopo (s*x) pupo
Won ni agidi okan. Tinu mi ni ma se.
Won ko feran eni ti ko looto
Won ko feran eni ti ko ni asiri
Won ki fe ki awon eniyan mo inu won
Awon ise Scorpio ♏
Researcher
Engineer
Financial Advisor
Market Analyst
Psychologist
Surgeon
Auditor
Pharmacist
Chemist
Detective
Won ko gbodo ma rin ni oru
Won ko gbodo gba obi je (colanut) lowo eniyan
Won ko gbodo se oyun (Abortion) tabi se oyun (abort) fun eniyan.
Sara fun irawo Omi ki won ma fi agbon (coconut), iyo (salt), owo (money), omi mimu (water) se Sara. Scorpio ♏, Cancer ♋, ati Pisces ♓ ni won le ma se Sara yi.
Alfa {Olohun Ni}
Aanu Rahmot