22/06/2020
*Ojo Gbogbo La Ns'ore, A o Mo ojo Esan!!!!!!!!*
Iya alakara kan wa, Owo (Trade) Akara yi lo nse tosi ko Ile meji ti o tun ra motor nidi akara yi, Awon eniyan maa nto (Line up) lati ra akara yii ni, bi Oja (Market) ni Idi Akara yi,Sungbon Alanganna (Madman) kan ma nwa si odo Iya yii ni gbogbo Araaro loma nwa, ti o ba si ti de, *Dami lohun* ni nkan toma nso fun Iya alakara yi, Iya alakara yi a si fun ni Akara oni #50 ati Eko #50. Were yi a ba tire lo.. Bo se ma nwa ni lojoojumo ni yen..
Ni ojo kan! Were yi ko tete de,Iya alakara yi si ti setan lati ma lo, Iya alakara yi wa nfo awon abo re l'owo, sugbon o ti di Akara ati Eko yi papo sibi kan, Abo yii ni mama nfo l'owo, ni were yi pe Iya alakara yi ni Isoda t**i pe ki Iya alakara yi o wa. Iya alakara yi nwope were lotun npe ohun yii, Iya alakara yi wa so fun pe kowa gba onje re pe ohun ti ba di sile ohun si fe maa lo s'ile o.. Alanganna were yi so pe ki Iya alakara yi o soda t**i wa ba ohun. Iya yii ba gbe ohunje yi lati lo gbe fun ni isoda t**i kole je ki ohun o ba tohun lo lasiko, Bi Iya Alakara yi ti de odo were yi ni were yi nso fun Iya alakara yi pe. *OJO GBOGBO LA NSORE,A O MO OJO ESAN* Were yi so oro yi ni Aimoye Igba, sugbon ko ye Iya alakara yi rara... Ibi ti won ti nse eleyi lowo ni Igi Araba ti Iya alakara yi maa njoko si labe dede wo lojiji, Gbogbo ara adugbo ba figbe ta pe Iya alakara ti ku ooo, Eero tu jade lati wa wo ohun to sele yi, Sungbon fun Iyalenu Iya alakara yii ba fo t**i wa bawon pe "Ohun o ku ohun re o" Gbogbo Eniyan ba n salo pe Oku tun yoju s'awon, Iya alakara yi wa bere si ni Sunkun to si ndupe lowo Olorun fun yiyo ninu Ewu Iku Ojiji yi..
*Hnmmmm,,, Gbogbo Oore to nse yen o gbe ooo, Esan nbo fun lojo ti o ni rokan rara. Soresore ma sore nso, maje ko su ee, Awon kan nwo o fun iranlowo sugbon Iwo nwo pe wahala won po, hmmm, A gbe o kale lati pa awon EDA kan lerin kiwon ri Ayo lati odo re ni. Esan nbo fun, Maje ko su o. "Tori Sore Sore o mojo Esan"*
Eni toba nsore Ara e lo nse fun Lona Kan tabi Ekeji
Ojo Gbogbo La Nsore!!! A o Mojo Esan!!!!!!!
Ojumo Ire o.
Oni yoo san wa loruko Jesu.