
16/10/2024
Olala awo Obe
A difa fun Obe
Obe se odun eyi tan
Ota ni ko ni se omiran
Ebo ni won ni ko se
O gbebo nibe o rubo
Olala iwo lawo Obe
A se odun eyi tan
Ao tun se omiran
Happy birthday to you my princess
May olodumare bless you with knowledge and understanding