29/01/2026
OSOLE AGBALU
Hmmm, ise yi kii se omode ise o. Ogberi o gbodo de idi re o nitoripe ti a ba lo ti a nsi se ise Alfa walahi awon agbagba Alfa ti o wa ni ilu yen won ma gburo wa, Alfa tio ba si beru Allah ninu won yio fe dan wa wo die o. Agbodo ri pe a to pe ni okunrin gidi ki a to se ise yi o. Akiyesi to tun wa nibe nipe e je ki alo ye ise yi wo ki a to se o. Sugbon o ti irawo wa ba gba, ti awon iyami si je
Osole Agbalu
Eiye orofo, eiye opere, eeku ile, eeku gogoro, ori agbe kan, ori aluko kan, ori eiye kowe kan, ao ko won sinu isasun nla tuntun kan, ao gbe ka ori ina ao ko ina si ao wa ma jo, bi a se njo lowo ao ma fi ata ijosi ati eru alamo ko ina re gege bi gba ti a nfi esan ko ina, ti o ba jo tan, ao lo kunna dada, ao wa te ni odu ifa ogundabede ni oju opon ifa, ao wa pe ohun re si, ao ma fi oyin gidi lo laro laro. Ofo re: A*olumo binu ni oruko ti anpe ifa 3x Asa woro osa moja loruko ti anpe orisa 3x Asa yaba rerin wolu ni oruko ti anpe eyin iya mi aje 3x Digbolu kolu ni oruko ti anpe esu odara 3x Eyin le ni eni ti o ba mo oruko eyin mererin pe oju owo o ni pon, emi lagbaja omo lagbaja mo ti mo oruko eyin mererin loni ki e mo je ki oju owo pon mi mo lailai, bi omode ba ri eiye sese ni omode man yo mo eiye sese, ekuku loni ki won o ma gbe owo nla nla wa fun mi loni, agbe kii ji ko mo le da aro, aluko kii ji ko mo le kosun, eiyekeye kan kii ke ko bori eiye kowe lori, eiyekeye kan kii ke ko bori eiye aje, bi eiye kowe ba ke jinijini moo gbalu ni, ki eyin to laye o je ki jinijini emi lagbaja omo lagbaja o mu ilu yi kaakiri gbogbo aye loni, ki awon olowo nla nla wa mo fun mi lowo nla nla lati oni lo, bi ina ba sun isu aagbe je ni, bi orun ba sun isu aagbe. junu ni, ije ina ni ko je fun mi, ki o mo je ije orun, ogundabede o olori ole ki o lo re dari owo nla nla odo gbogbo eda aye yi wa fun mi lati oni lo ati t**i lailai.
ALFA OLA ADUA 09159185940