Àsiri Irawọ Gbogbo Ẹda Eniyan

Àsiri Irawọ Gbogbo Ẹda Eniyan ASTROLOGIST (AWORAWỌ), NUMERLOGIST AND PSYCHIC (RC: 8973961). Read more about your zodiac sign on our website:👇👇👇👇👇👇👇👇
https://asiriirawo.kesug.com

ÌWURE OṢU OKUDU (JUNE BLESSINGS).👉Ẹ jẹ ki a lo àkòrí àdúrà yí lẹẹkan- sì; 🙏Ọlọrun jọwọ ma fi ọna atijẹ atimu mi síbi to ...
01/06/2026

ÌWURE OṢU OKUDU (JUNE BLESSINGS).

👉Ẹ jẹ ki a lo àkòrí àdúrà yí lẹẹkan- sì;

🙏Ọlọrun jọwọ ma fi ọna atijẹ atimu mi síbi to nira.

🙏Nigeria le lóòótọ́ sugbọn ko gbọdọ le mọ mi tọmọtọmọ tẹbi tara mi.

🙏Oṣu tuntun tí mo wa yí gbọdọ san mi sì ire gbogbo láṣẹ edumare.

Amin amin amin àṣẹ edumare.

🤝Happy first monday of june, happy new week and happy new month🤝

👉Lẹẹkan-si, mo ki wá káàbọ sínú ibusọ keji nínú ọdun 2026.

✍PENNED BY ALPHAJOSEPH
Joseph Igbekele Ajayi
Àsiri Irawọ Gbogbo Ẹda Eniyan
ASIRI IRAWO GBOGBO EDA ENIYAN

31/05/2026

♊Eewọ (taboos) fun ipin Irawọ Afẹfẹ alawada (gemini) may 21 - june 20 part 3♊

👉Fun awọn videos wa lórísirisi lori Irawọ Ẹda Eniyan ẹ darapọ mọ wa lójú àwọn òpó wọ̀nyí: 👇👇👇

💢Youtube channel:
https://www.youtube.com/

💢Tiktok channel:
https://www.tiktok.com/?_r=1&_t=ZS-96pH33EByiL

💢Instagram channel:
https://www.instagram.com/alphajoseph34?igsh=aWJienRkMnpoYXB6

👉Ẹ darapọ mọ WhatsApp group wa:👇👇
https://chat.whatsapp.com/JgD4UD4721X3etMoQYfecr?s=cl&p=a&ilr=1&amv=3

31/05/2026

Eewọ (taboos) fun ipin Irawọ Afẹfẹ alawada (gemini) may 21 - june 20 part 3.

♊TABOOS/SPIRITUAL FORBIDDENS OF GEMINI SIGN (MAY 21 - JUNE 20) ENGLISH VERSION PART 4♊👉They must not be promiscuous.👉The...
31/05/2026

♊TABOOS/SPIRITUAL FORBIDDENS OF GEMINI SIGN (MAY 21 - JUNE 20) ENGLISH VERSION PART 4♊

👉They must not be promiscuous.
👉They must avoid smoking.
👉They should avoid using Black Palm
kernel Oil.
👉They should avoid sleeping by the wall.
👉They should avoid facing the wall while
sleeping.
👉They should avoid eating maize,
whether cooked or roasted.
👉They should avoid telling lies.
👉They should avoid making promises
they can’t keep.
👉They should refrain from sharing their
aspirations indiscriminately.
👉They should be careful of letting friends
know too much about them.
👉They should avoid talkativeness and
gossip.
👉They should avoid using Black and red
clothes.
👉They should avoid eating feathers
animal.
👉They should avoid eating snails.
👉They should avoid fighting over property
or inheritance.
👉They should avoid using swallow or
Swift Bird for spiritual work.
👉They must not kill or eat any member of
a monkey family.
👉They must not be envoius of other
people's success.
👉They must not repay evil with evil.
👉They should avoid offering excessive
help.
👉They should avoid becoming sad.
👉They should avoid boasting and eye
service.

🌺For consultation on our life issues, to know our predestinies, destinies and fates, to know our compatible soulmates, to know our destinies career paths, to know our Guardian angels, to know maybe we have spiritual mates, their name and for our spiritual mates appeasement, for separation between us and our spiritual husband/wife (incubus and succubus demons), for spiritual works that fit our destinies, fates and stars, for matchmaking, for head appeasement, for dream and it's meaning and many more, message me on WhatsApp at: 09040255987🌺

👉N.B: consultations are not free but the charges are not much.

✍PENNED BY ALPHAJOSEPH
Joseph Igbekele Ajayi
Àsiri Irawọ Gbogbo Ẹda Eniyan
ASIRI IRAWO GBOGBO EDA ENIYAN

31/05/2026
💢OWU ALANTAKUN (COBWEBS) PART 2💢👉Kabiyesi elédùmarè ọba to ni ile aye àti ọrun, iba ẹyin òrìṣà mi; Ọbatala mo júbà rẹ,  ...
30/05/2026

💢OWU ALANTAKUN (COBWEBS) PART 2💢

👉Kabiyesi elédùmarè ọba to ni ile aye àti ọrun, iba ẹyin òrìṣà mi; Ọbatala mo júbà rẹ, Ògun làákàyè mo júbà, Èṣù laalu ogiri oko mo juba, iba òrìṣà ibeji, iba aje mi, iba òrìṣà aje mi (oluwẹ̀rí magboojo), iba ẹyin iya mi oṣoronga; ẹyin iya mi akọ aja aboju mẹ́rìndínlógún, ẹyin iya mi abo aja aboju mẹrindinlogun, iba bàbà to ń tí iya mi, iba Alfa nlanla, iba woli, iba babalawo, iba Oníṣègùn, iba adahunṣe, iba oluwo, iba Ojugbana, iba ọkùnrin, iba obìnrin, iba onile, iba alejo, iba ọmọde, iba àgbàlagbà, iba lọwọ ori mi. Adaṣe ni n hunmọ iba ó gbọdọ hunmọ.

👉Owu alantakun jẹ ìránṣẹ́ awọn àgbàlagbà tí wọn ma ń lo láti fi de ènìyàn mọlẹ tàbí fi dé ènìyàn sínú ìgbèkùn bẹẹ owu yí fuyẹ lójú aye sugbọn ó wuwo nínú ẹ̀mí tàbí ayé odikeji. Owu alantakun kò le diṣú bẹẹ ko le digi sugbọn ti wọn ba fi di ọmọ eniyan t**i ayé kò ní bọ ayafi tí onítọ̀hún bá kún fún ọpọlọpọ ètùtù ẹ̀bẹ̀ àwọn àgbàlagbà, ẹyọnu awọn àgbàlagbà, awẹ, àdúrà àti sara ṣíṣe.

👉Ẹni tí awọn agbalagba bá fi owu alantakun de mọlẹ irú wọn kì kúrò lójú kan, nkan yio ma daru nínú ìgbésí ayé ẹni bẹ, Itẹsiwaju kò ní si, aṣeti àti àṣedanu yio pọ nínú ayé onítọ̀hún, kò sì bí irú ẹ̀dá bẹ ṣe lè jẹ ọlọgbọn ènìyàn tó wọn kò ní jẹ ki o ri ọgbọn ori rẹ lo, iru ẹnibẹ yio di alaimọṣe, àdáwọlé irú ẹni bẹ kí yọrí sí rere, igbeyawo irú ẹnibẹ yio ma daru, ikorira yio pọ, ìṣẹ irú ẹni bẹ kí i lọ dédé, ìpọ́njú, oṣí àti ìṣẹ yio gbilẹ ninu aye onítọ̀hún, ijakulẹ yio pọ (ÌBA ẸYÍN ÌYÁ MÍ OṢORONGA).

👉Ti eniyan ba ti n ṣe àkíyèsí wipe owu alantakun ma ń kọ òun níwájú ori, lọwọ, lẹsẹ tabi ni gbogbo ara àpẹẹrẹ wípé Awọn àgbàlagbà ń fi owu alantakun bá ènìyàn ja ni, ti eniyan ba wa ninu ile ti owu alantakun sì ń kọ níwájú ori, lọwọ tàbí lẹsẹ àti ní gbogbo ara èyí túmọ̀sí wípé irúfẹ́ ẹni bẹ wá nínú ìgbèkùn awọn àgbàlagbà ni, bí ènìyàn bá ń rìn lọ lójú ọna to mọ tí ọ̀pọ̀ ènìyàn tí gba ibẹ kọjá sugbọn ti owu alantakun sì ń kọ lára èyí túmọ̀sí sì ide awọn àgbà ọlọjọ pipẹ lára, tí owu alantakun bá pọ nínú ilé tí ènìyàn ń gbé wàhálà ni, tí ọmọ onile àti ayan bá pọ nínú ilé tí ènìyàn ń gbé èyí túmọ̀sí wípé oju àwọn àgbàlagbà pọ lára onítọ̀hún àti ile rẹ, tí ènìyàn bá ń fi ojú kò owu alantakun nínú ilé tabi iwájú ilé itaja rẹ èyí túmọ̀sí wípé ile itaja na wá nínú ide awọn àgbàlagbà bẹẹ kí yio jẹ ki ọja àti gbogbo nkan tí ènìyàn bá gbé kalẹ sínú ile itaja nà lojutu, bí owu alantakun tàbí ọmọ onile bá pọ nínú ilé itaja tàbí ilé ìṣẹ ènìyàn irúfẹ́ ẹnibẹ yio jẹ gbese tí yio sá fi ilé itaja tàbí ilé ìṣẹ na silẹ gbẹ̀yìn ni.

👉Ọpọ awọn eniyan lo ma n fi ọwọ yẹpẹrẹ mú ọrọ owu alantakun, ẹlòmíràn tilẹ ni igbagbọ wipe ikilọ lásán ni tí owu alantakun bá kọ ènìyàn láìmọ wípé owu alantakun ni agbára láti dá ìrìnàjò ẹ̀dá ru patapata tí kò ní sí atúnṣe ayafi ti onítọ̀hún bá tètè tọ awọn oni mimọ lọ, láàrin ọna ti awọn eniyan pupọ ń gba kọjá bí express tàbí ọna ti o mọ daradara tí owu alantakun bá ń kọ ènìyàn irúfẹ́ ẹni bẹ wá lábẹ́ ide owu alantakun tí ó ní agbara ni.

👉Ọna àbáyọ wá sí ide owu alantakun latara ṣíṣe ètùtù fún aforiji àti ẹbẹ awọn àgbàlagbà, ìṣẹ ọṣẹ wọn ní lilo àti ẹyọnu wọn. Awon àgbàlagbà kí dede bá ènìyàn ja láìnídi ayafi ti eniyan ba tasẹ agẹrẹ lọ si ọdọ wọn èyí lè jẹ wípé bàbà tabi iya ènìyàn tàbí ìran ènìyàn ṣẹ wọn tí wọn yio si ma gba ẹsan ẹṣẹ yí lara ọmọ. Nígbà miran ẹwẹ, ogo a má ṣokùnfà ìjìyà láti ọdọ awọn agbalagba sugbọn eyi ma n waye latara eewọ jíjẹ tàbí ṣíṣe àti àfọwọ́fà kí wọn to le wọle si eniyan lara.

🌺Fún ayẹwo, iwadi àti awari lórí ọrọ ìgbésí aye wa, láti mọ akọsejaye, kádàrá àti àyanmọ wa, láti mọ irú ọkọ/aya tí a le fẹ, láti mọ ìṣẹ aṣela wa, láti mọ òrìṣà idile/Irawọ wá, láti mọ bóyá ọmọ ẹlẹgbẹ ni wá, orúkọ ẹgbẹ wá, fun ẹrú ẹgbẹ dídì tàbí ẹgbẹ bibọ, fun ìpínyà láàrin wá àti ọkọ/aya ọrun wá, fun ìṣẹ igbiyanju èyí tí ó bá kádàrá, àyanmọ àti Irawọ wá mu, fun orí bibọ, fun ibaniwaya/ọkọ, fun ala àti Ìtumọ rẹ àti bẹẹ bẹẹ, ẹ message mi lórí whatsapp 👇👇👇
Message ÀṢÍRÍ ÌRÀWO GBOGBO ẸDA ÈNÌYÀN on WhatsApp. https://wa.me/2349040255987🌺

👉N.B: Àyẹ̀wò kí ṣe ọfẹ sugbọn owo rẹ ko gani lara.

✍PENNED BY ALAFAJOSEPH
Joseph Igbekele Ajayi
Àsiri Irawọ Gbogbo Ẹda Eniyan
ASIRI IRAWO GBOGBO EDA ENIYAN

Address

Olainukan Ewu Aláṣẹ Mosimi Nnpc Depot, Lukosi, Ogijo Sagamu
Sagamu
121102

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Àsiri Irawọ Gbogbo Ẹda Eniyan posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share