02/09/2025
AWORO NLA( CROWD PULLER -By Dr BABALOLA from ijebu igbo, ogun state 08084714932.)
Mo ki gbogbo eyin fancy mi, eledumare a wa pelu yin o..
Ejo e sare kelo bami don eleyi wo.. ni tori wipe yio wulo fun gbogbo awon to nsise woli, pastor, filling station, eattery, big restaurant, school owner E.T. C. To wa ero pupo..
Kini elo bami?
1,elo bami wa olongbo nla kan.
2,ewe awara
3,ewe itiponrila pupo
4,Iyo pupo..
5,koko ajere nla kan
6,okon agunto ti won pa lojo..
7,obi abata oloju merin... Merin
8,orugbo merin
9,ako pepeye funfun Kan
10,omo nu ewe sapo mesan
11,eyo owo okonlelogoji.
Sisere....
Eo fi okon agunto si nu koko naa,eo ko obi, orugbo,ati gbogbo awon ewe na si nu re ke to gbe olongbo yen si,eo wa ko owo okonlelogoji si nu re,eo gbele loju ona ile ti e feri ise na si,e wa gbe Koko yen sinu koto ti egbe yen,eo wa ko Iyo pupo si nu koko yen,eo se adura be sefe ki ogun yen fun yin so rire daada,e wa pa pepeye yen so ri,eo ro gbogbo eje re si daada ke to gbe ori pepeye yen le,eo so fun ogun no wipe,ododun ni eo fun ni pepeye funfun yio ko dari awon eiyan pupo wa si chop yin o.
Leyin,iyen eo da iyepe pupo bo mole e tun da omi tutu le lori,le sekese,
Teba se yen ton o ti pari,
Ikilo to je pataki, ododun ni eo ma pa pepeye funfun sori ile ti e sise yen sio.
Akiesi pataki,e wa gbo mi o!
Ise yi ni etutu tan se taba ri ise yi mole tan o..
Ko le sise t**i lie lie fun wa o..
Ejo,e pemi lori Whatsapp Number 08084714932,ke le bere fun ise etutu naa.
Like e ke bami share eto yi ke elomi le je afanire...