IWULO EWE ATI EGBO

  • Home
  • IWULO EWE ATI EGBO

IWULO EWE ATI EGBO The uses of root and leaves
(1)

18/05/2025

ENGLISH:Join this PAGE to benefits more about root and leaf
YORUBA: Darapọ mọ PAGE yii lati ni anfani diẹ sii nipa gbongbo ati ewe
HAUSA: Ku shiga wannan PAGE domin samun fa'ida akan tushe da ganye
IGBO: Soro PAGE a ka ị nweta uru ndị ọzọ gbasara mgbọrọgwụ na akwukwo
ARABIC: نضم إلى هذه الصفحة للاستفادة أكثر من الجذور
والأوراق
FRENCH: Rejoignez cette PAGE pour en savoir plus sur les racines et les feuilles
SPANISH: Únase a esta PÁGINA para obtener más beneficios sobre la raíz y la hoja
GERMAN: Treten Sie dieser SEITE bei, um mehr über Wurzel und Blatt zu erfahren
HINDI: जड़ और पत्ती के बारे में अधिक लाभ पाने के लिए इस पेज से जुड़ें
CHINA: 加入此页面以获取更多有关根和叶的信息
FILIPINO: Sumali sa PAGE na ito upang mas makinabang tungkol sa ugat at dahon
GREEK: Εγγραφείτε σε αυτήν τη ΣΕΛΙΔΑ για να επωφεληθείτε περισσότερα σχετικά με τη ρίζα και τα φύλλα
HAWAIIAN: E hui pū me kēia PAGE no ka pōmaikaʻi hou aku e pili ana i ke aʻa a me ka lau
JAPANESE: この PAGE に参加して、根と葉についてさらにメリットを得る
KOREAN: 이 페이지에 가입하여 루트 및 리프에 대한 자세한 정보를 얻으십시오.
LATIN: Hanc paginam coniunge ut plus proficiat circa radicem et folium
MALAY: Sertai PAGE ini untuk mendapat lebih banyak manfaat tentang akar dan daun
POLISH: Dołącz do tej STRONY, aby uzyskać więcej korzyści na temat korzeni i liści
PORTUGUESE: Junte-se a esta PÁGINA para obter mais benefícios sobre raiz e folha
PUNJABI: ਜੜ੍ਹ ਅਤੇ ਪੱਤੇ ਬਾਰੇ ਹੋਰ ਲਾਭਾਂ ਲਈ ਇਸ ਪੇਜ ਵਿੱਚ ਸ਼ਾਮਲ ਹੋਵੋ
ROMANIAN: Alăturați-vă acestei PAGINI pentru a beneficia mai mult despre rădăcină și frunze
RUSSIAN: Присоединяйтесь к этой СТРАНИЦЕ, чтобы узнать больше о корнях и листах
THAI: เข้าร่วม PAGE นี้เพื่อรับประโยชน์เพิ่มเติมเกี่ยวกับรูทและลีฟ
UKRAINIAN: Приєднуйтеся до цієї СТОРІНКИ, щоб дізнатися більше про корінь і лист
ZULU: Joyina leli KHASI ukuze uzuze okwengeziwe ngempande neqabunga

11/01/2025
ATUDE ITUWO AYE TODAJUTI ENIYAN BA NI ISE TO FE LO, TABI JE ASEJE TABI FE LO OSHOLE, KI O BA LE SISERE DADA, ISE YIN JE ...
16/01/2023

ATUDE ITUWO AYE TODAJU

TI ENIYAN BA NI ISE TO FE LO, TABI JE ASEJE TABI FE LO OSHOLE, KI O BA LE SISERE DADA,
ISE YIN JE ISE GIDI, TI OGUN KI BA SISE LARA ENIYAN, TI A BA LO OSE YI, GBOGBO IDE ARA WA NI YO JA DANU,

EGBO TUDE OOJO
EWE YARIN OR EFO YARIN,
EYIN ORORO KAN
OSE DUDU

SISERE : AO GUN GBOGBO RE PAPO PELU OSE DUDU, AO FI EYIN ORORO PO PAPO,..
AO KO SINU IKE FUNFUN KAN

Notice: IDI RE KO GBODO KANLE MO,
LILO RE : LEYIN OJO KETA TI A BA TI SE ISE YI,AO MA FI WE
OPO ENIYAN LE LOO, TI A BA TI WE NI OJO MARUN, PERE O TI TO
LEYIN TI A BA TI WE TAN, KO SI ISE TI A LE LO TI KO NI SISE LARA WA MON,, ISE TO DAJU NI

KI ISEYI BALE JE FUN RE COMMENT and SHARE
WhatsApp 07041714797me FUN IBERE TABI RIRA ORISIRISI OGUN TODARA

Note2... We have it here for sell if you want give me call or WhatsApp (tita wa nibi ti eba fare oo,
If you need confirm oshole, awure,itaja,ashiri bibo,ose Anu Call..07041714797

16/01/2023

ASEJE ATUDE GBOGBO IDEKIDE INU ARA TODAJU TI O YE KI GBOGBO WA SE.

Ewe tude, egbo tude, iyere 16, e lo kuna daada, ki e dasi inu isasun tuntun kekere kan, ki e fi omi die si, iyo die, ati epo pupa die, ki e fi se odidi igbin kan je. Igbin yen, e ma bo ni inu omi gbigbona, a o wa yo kuro ninu ikarahun, a o yo igbe re kuro, a o wa ju sinu isasun yen lodidi. Ti o ba jina tan, a o so kale, ki o tutu. A o gbe losi inu iyara wa, a o bo gbogbo a*o ara wa pelu bata, chain, bead, earrings, ring etc. Ti a ma wa ni ihoho omoluabi, a o nu ori ile ele yen daada either tiles tabi cement floor. A o da aseje na si ori ile yen, a o kunle si iwaju aseje na, a o ka owo wa mejeji si eyin, a o wa sadura itusile si, a o wa fi enu gbe igbin yen je, a o la ibe daada, a o dide pada, a o si wo a*o wa. Aseje yi daju gan o. A o lo fo isasun yen si ori akitan
Hmmm, ALAISAN ojo pipe le se ise yi, eni ti aye nda laamun lese ise yi, eni towa ninu igbekun aye le se. Kosi eni ti kole se o, infact, kosi eni ti ko nilo atude.
Ejowon ise yi wo,eni ti mose fun ni ana ti dide lori sick bed laaro yi. Ase olorun ni.

07041714797

 Bami gbinyanju ree lolaWa dupe Egbo tudeEwe tudeEwe olaAta ijosi niwonbaPonmo  eo lo gbogbo awon eroja yen po lori oloE...
16/01/2023



Bami gbinyanju ree lola
Wa dupe

Egbo tude
Ewe tude
Ewe ola
Ata ijosi niwonba
Ponmo

eo lo gbogbo awon eroja yen po lori olo
Eo wa fise ponmo tiwon ge si 16 je lepo Niyo

Ona yip si fuo kiakia

Walai ise yiii sise dada
Sare bami gbinyanju ree kofun labo

Iwo toba share ati iwo toba comment ni yio je fun

Fi asiko die kale lati share kosi comment and like

IWULO EWE ATI EGBO
07041714797

07041714797

O dara ki eniyan ni igbinyanju, igbinyanju dara ninu aye eda mo mu ise yi fun anfani eyin ololufemi mi mofe ki gbogbo wa...
12/01/2023

O dara ki eniyan ni igbinyanju, igbinyanju dara ninu aye eda mo mu ise yi fun anfani eyin ololufemi mi mofe ki gbogbo wa ri owo se aye wa oun ni pataki fun mi lase edumare gbogbo wa lama ni owo lowo ao ni ni lorun gbese lonje ki ani owo lorun ao ni je gbese lase olorun
OSHOLE ARISIKI OWO TODAJU
Ise dara fun gbogbo eniyan yala onise owo oni sowo onise ijoba papa awon omo yahoo tia ba nlo ise yi gbogbo ona ni ao ti ma ri oluranlowo gbogbo igba ni ao ma ni owo lowo awon ise ti moba post confirm emi osi ninu awon sogun dogoji ikan ti eda ba se loni ni yio ba lojo iwaju tori asele ni abowaba
Eroja re
Awo ekun
Lofinda sosorobia
Ewe ogo
Erupe ori akitan
#1000 tuntun
OSE
AKO OKUTA
EYO IGBALE KAN
Sise re
Ao gun awon eroja yen lototo ao wa po papo ao pomo ose ao fi sosorobia yen morawon ao ko sinu Ike funfun ao fi ako okuta yen si ori ose na pelu eyo igbale kan ao ma fi we lararo pelu gbolohun re
Owo ana kotomi na 3*taba gbale taba gbata akitan ladari resi ogo de omo elewuji ire kan soso ni mope igba ire ni kojemi eyin olowo orile ede yi efi owo yin bomi lasiri ao ma wi tia ba nwe ose na ko ju bai lo danwo kio fun mi labo yio je fun e lase edumare bami share ati post ati comment iwo ti ise yi ba wun lati se sugbon tio si aye mole bae se pelu iyanda olorun fun ibere lori oro igbesi aye re pemi tabi Whatsapp mi 07041714797

Mo ki gbogbo eyin eyan mi pe aku aseku odun opo re lao se lase edumare momu ise yi wa fun yin kie je anfani reAWURE OSHO...
12/01/2023

Mo ki gbogbo eyin eyan mi pe aku aseku odun opo re lao se lase edumare momu ise yi wa fun yin kie je anfani re
AWURE OSHOLE TODAJU
Iwo ti o ba gbiyanju ise yi wo wa mope aye ku sibikan gege bi oro mi osi o se lo ile aye olowo se oun gbogbo tan iwo na ma duro ma sun kole sun siwaju ni agbara olorun oba alanu gbogbo wa ni a ma ri ona abayo oni gbiyanju a jana lojo kan iwo sare si igbesi aye re ma fojudi ise yi mo fe ki gbogbo wa ri ona abayo ni mo se ma nfi awon ise yi sita gbogbo ise timo ba post lope kosi asa danu nibe awa o ki nse onijibiti iwo tio ba pa omo lakeji re lekun o tidi dandan won yoo pa iwo ati ebi re lekun dandan niyen osuwon tio ba fiwon fun eniyan ni won o fiwon fun iwo na lo dan ise yi wo kio fun mi labo wa dupe folorun
Eroja re
Okete aye kan
Ako alangba mesan
Abo alangba mejo
Egbo tude
Ewe ewuro oojo
A
Odindi atare mesan
Sise re lo bayi
Ao la aya okete yen ao ko ifun re kuro ao ko ako alangba sinu re pelu abo alangba yen ao tun wa ko ifun re si pada ao fi owu dudu ran pada ao gbe sinu ape ao ko egbo tude le lori ao to atare yen si legbe gbe ao wa ko ewe ewuro bo lori ao jo gbogbo papo ao lo dada ao ro sinu igo kan
Lilo re
Ao ma pelu omi aye larolaro o daju pupo gbiyanju re yoo je fun e iwo tio ba nife si ise yi sugbon ti o saye lati se mole se fun e to ba fe bami share ati post ati comment isoro ki soro yowun tio bao ninu je pemi tabi Whatsapp mi 07041714797 yoo dara fun e

Awon agbalagba loni igbinyanju o pin soju kan igbinyanju se Pataki ninu aye eda ti eda ba ni igbinyanju yio tete ri ona ...
12/01/2023

Awon agbalagba loni igbinyanju o pin soju kan igbinyanju se Pataki ninu aye eda ti eda ba ni igbinyanju yio tete ri ona abayo ise yi dara pupo
EYONU AWON AGBA TODAJU
Ti eyan ba nlo ise yi yio ripe gbogbo nkan nbo si irorun fun oun ni gbogbo igba eyonu se Pataki pupo lati malo eniti aye ba yonu si ni omo eyan ma yonu si ti aye ba binu si eyan omo eyan yoo binu si aye o ni binu siwa igbese ni pataki eyonu ma nje ki ogun sise lara eda tio ba raye lo ise yi wa ripe gbogbo eniyan ni yio ma yonu sie wasiri oluranlowo kiakia
Eroja re
Eiye ega kan
Odindi atare kan
Ado ijamo kekere meji
Sise re
Ao jo eiye ega yen pelu atare na papo ao ro sinu ado ijamo kan ao tun jo oun na papo tio ba jotan ao lo dada ao ro sinu ado ijamo keji ao fi a*o etu bo ado na lara ao mala ni araro o daju pupo danwo lobi iya okere bami share fun anfani elomiran yio je fun e lase edumare
Fun iwo tio ba fe mo nipa Irawo re tabi isoro yowun tio doju koe pemi tabi Whatsapp mi 07041714797

REPOST!!!🌿🌿 🌿🌿Enitoba sope kosi ogun ebamisofun enina p*e enina tiku tipe awon Yoruba sope ogun tioje ewe ee loku kan As...
12/01/2023

REPOST!!!

🌿🌿 🌿🌿

Enitoba sope kosi ogun ebamisofun enina p*e enina tiku tipe awon Yoruba sope ogun tioje ewe ee loku kan Asiri nbe airin jina lairi abuke okere ise yi dara pupo fun gbogbo eniyan Pataki omo yahoo bami gbiyanju re wo ise tia fi nri owo nlanla kiakia ni eni ti oni owo laye bio ku ni onitan un wa ona lati lowo laye

KOSI ENI TI YIO LO TI KONI DUPE LOWO OLORUN OBA LOKE

DAN WO LOBI IYA OKERE


👉Omo olongbo kan tikoti ma sode
👉ewe ajeobale oojo
👉ewe orijin oojo
👉ewe ewuro oojo
👉adi dudu
👉oyin gidi (pure honey)
👉epo pupa
👉ose dudu
SISERE

Aogbe omo olongbo yii sinu odo aogun tiyiokunna dada leyina aoko ewe ajeobale si pelu ewe ewuro ati ewe orijin aogun gbogbo awon eronja yii tiyiokunna dada tiobakunna aopo papo man ose dudu aonifi omi poo oseyi ooo adi dudu pelu oyin ati epo pupa laofipo osena aogbe osena pamon fun ojo meta

leyin ojo keta aoma we laro laro.

Walai koju bayi lo sugbon ata kere iyo dun nio😋

👂👂 ise yi wa nile fun tita oo nitori awa ti abalese fun rawa iwo tio ba ni isoro kan tabi ikeji lori oro igbesi re pemi tabi Whatsapp mi bami share ati post ati comment 07041714797

Mo mu ise yi wa ki e le je anfani re o dara pupo lati so eyan meji papo Pataki fun omo yahoo tabi okunrin to fe fe obinr...
12/01/2023

Mo mu ise yi wa ki e le je anfani re o dara pupo lati so eyan meji papo Pataki fun omo yahoo tabi okunrin to fe fe obinrin gbiyanju re wo
IFERAN ALASOPO TODAJU

GBOGBO EYIN TI IJA WA LARIN YIN ATI OLOLUFE YIN TIE SI FE KOPARI, ELO DAN ISEYII WO.. ABI EYIN TI OLOLUFE YIN KOSE DADA SI YIN MO. SARE LODAN ISEYI WO.. ODAJU GIDI...


ISENA RE:-
IKARAHUN IGBIN, PHOTO OKUNRIN ATI OBINRIN YEN, EWE SAWEREPEPE, EWE AMUNIMUYE, ABELA IYEKIYE.

SISE RE:-
PHOTO OKUNRIN ATI OBINRIN YEN, AO KOJU AWON MEJEJI SIRA WON, A MATI BO INU IKARAHUN IGBIN YEN, AO FI AWON EWE MEJEJI YEN NAA SI NINU DIE DIE, AO WA TANNA SI CANDLE YEN, AO WA KAN SINU IKARAHUN IGBIN YEN DADA, TI AYE KANKAN ONI SOFO, AO LO RI MO IBITI OMI KI GBE NIBE TABI NI ORITA META, NI IBITI AWON ENIYAN NGBA DADA, ODAJU BIKU.
Iwo ti ise yi wun lati se sugbon ti kosi aye latise pemi ki nba e se bami share ati post ati comment pemi tabi Whatsapp mi 07041714797

12/01/2023

Ise yi dara pupo fun gbogbo eniyan o ma nje ki owo wa lowo eniyan nigba gbogbo gbiyanju re wo EYONU OSHOLE OWO TODAJU
Ninu Awon Eyonu tó mú owo wa dáadáa, iṣẹ yìí jé òkan nínú wọn, tia bá lọ iṣẹ yìí, gbogbo eniyan yíò máa yonu sí wa, won o si máa tari owo síwá, ào máa rówó lonakona, ọmọ Yahoo le lòó, nitori ati ile ati ona la fi n jin ologinni
Eroja re................
Ori olongbo Toni IRUN Lara
Ori awodi to lese LENU
Ori OKETE tutu,
Sise re
AO Fi ENU meteta ko Ara won NINU Ape , AO Fi se bi Adiro, AO Fi ODINDI ATARE KAN le Lori, AO ko omonigelegele le Lori, AO ko ewe laa fufu ATI laa pupa bo Lori NINU Ape , AO jo papo,

Lilore.. AO ro sinu igo FF.

AO ma Fi Ekuru JE Lojo Monday AJE,..

AO MAFI Omi Alujonu lojo Thursday

.. GBOLOHUN RE..

Ofe ni ologini njẹun, atile atona lafin jin ologinni, Ki nji ifá aye,
Asa kii baale ko sanwo,
Ori OKETE ni OKETE Fi nru eru sile arare, eru owo wa fun mi loni, oju oni Pon Omo onigelegele Kofi gbongbo idi e won Omo Araye, ki oju owo ma Pon mi ..

FUN IRANLOWO LORI ISORO AYE RE PEMI TABI WHATSAPP MI 07041714797

Address


Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when IWULO EWE ATI EGBO posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

  • Want your practice to be the top-listed Clinic?

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram