Imule Ajesowapo Agbaye

Imule Ajesowapo Agbaye Informations de contact, plan et itinéraire, formulaire de contact, heures d'ouverture, services, évaluations, photos, vidéos et annonces de Imule Ajesowapo Agbaye, Clinique pour femmes, Cadjèhoun.

this page is for traditionalist for any body that need spiritual assistance for his life visible and invisible problems ,and to know much on orisa aje ,how to do sacrifice for aje to be locate on where you are ,aje is great ,omo alaje nimi aje a gbewa o ,

01/02/2025
03/12/2023

Check out oba imule aje's video.

Apada si aburu koni ba gbogbo eyin ololufe emi oba imunle aje obatala agbaye
05/09/2023

Apada si aburu koni ba gbogbo eyin ololufe emi oba imunle aje obatala agbaye

Check out oba imule aje's post.

04/12/2022

Darapo mo egbe imunle aje Agbaye ,fun ilosiwaju ati anfaani igbele aye pelu irorun

Omo alaje niwa o ,aanu eledumare ama wa pelu gbogbo wa, gbogbo eni toba fe darapo mo egbe imunle aje ,ki o fi WhatsApp n...
27/10/2020

Omo alaje niwa o ,aanu eledumare ama wa pelu gbogbo wa, gbogbo eni toba fe darapo mo egbe imunle aje ,ki o fi WhatsApp nomber e sile fun interview ,kato gbe sinu yara imunle aje ,nitori asiko ti won ma ngba awon omo alaje wole niyi ,aje a gbewa ooo

Gbogbo wa patapata omo imunle aje ,aje a gbewa o ,ose ayo lama se o
26/09/2020

Gbogbo wa patapata omo imunle aje ,aje a gbewa o ,ose ayo lama se o

Gbogbo omo alaje ,ipade ojukoju ti a fe se ninu osu keta odun yi ,o ma ba gbogbo wa ninu ola owo ati alaafia lase edumare,gbogbo omo alaje patapata ni a pe sibi ipade yi ni ilu ibadan ninu osu keta odun yi ,aje a gbewa o ,aje is great

Gbogbo omo alaje ,ipade ojukoju ti a fe se ninu osu keta odun yi ,o ma ba gbogbo wa ninu ola owo ati alaafia lase edumar...
20/01/2020

Gbogbo omo alaje ,ipade ojukoju ti a fe se ninu osu keta odun yi ,o ma ba gbogbo wa ninu ola owo ati alaafia lase edumare,gbogbo omo alaje patapata ni a pe sibi ipade yi ni ilu ibadan ninu osu keta odun yi ,aje a gbewa o ,aje is great

Odun ayo ,idunnu alaafia fun gbogbo omo alaje ati awon ololufe wa kari aye ,aje a bawa gbe di ojo ale ,iponju koni je ti...
01/01/2020

Odun ayo ,idunnu alaafia fun gbogbo omo alaje ati awon ololufe wa kari aye ,aje a bawa gbe di ojo ale ,iponju koni je tiwa ninu odun yi ati laelae ,ona a si,ona a la fun gbogbo wa o ,iku ojiji koni wo ile wa ,gbogbo omo egbe aje koni pedin ,oke oke lama lo o ,gbogbo adura ti a se fun gbogbo wa fun ilu wa ,fun orileede wa,fun gbogbo aye a se mowa Lara o,nigeria a roju ,benin republic koni daru o ,gbogbo awon adari wa eledumare a kowon moose o ,omo alaje niwa aje a gbewa o

Adresse

Cadjèhoun

Heures d'ouverture

Lundi 09:00 - 17:00
Mardi 09:00 - 17:00
Mercredi 09:00 - 17:00
Jeudi 09:00 - 17:00
Vendredi 09:00 - 17:00
Samedi 09:00 - 17:00
Dimanche 09:00 - 17:00

Téléphone

+22997872561

Notifications

Soyez le premier à savoir et laissez-nous vous envoyer un courriel lorsque Imule Ajesowapo Agbaye publie des nouvelles et des promotions. Votre adresse e-mail ne sera pas utilisée à d'autres fins, et vous pouvez vous désabonner à tout moment.

Contacter La Pratique

Envoyer un message à Imule Ajesowapo Agbaye:

Partager

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram