
21/08/2025
SORA FUN NKAN WONYII TI IWO NAA KOBANIFESI IPONJU OWO.
1:TI OBA YA OWO LOWO ENIYAN MASE FI OWO NAA PON ALAANU NAA LOJU KI OTOSAN PADA.
2:MASE JEJE OWO TI OMO WIPE OKONIFUN FUN ENIYAN NITORI KARINI.
3:TI OBARA OJA LOWO ENIYAN TABI TI ENIYAN FARASISE FUN E,MASEJEKI INIRA BA ENI NAA TIWAFI SANWO NAA PADA.
LOTITO ONIRUURU ISELE LOMA NSOKUNFA IJAKULE NIPA MAJEMU OWO LAARIN ENIYAN MEJI SUGBON GBIYANJU LATIJEKI ORO ELOMIRAN KAE LARA TOBATIDI ORO OWO NITORIPE AIPE ADEHUN OWO LESAKOBA FUN ALAAFIA TABI EMI ENIYAN
Courtesy:Nuru omo Iya Nuru