
08/04/2025
From Sosan Nurudeen Alao(Olori ebi)
*AWENU IKORIRA ATI IFERAN TIPATIPA*
Beeni! Gbogbo nkantiwon bafi omi ati sugar se naa loma nni agbara otun lati sise iyanu laye eniyan sugbon agbara towa lara oti ELERINDODO gegebi FANTA/MIRINDA tayo awon toku.
Nigbayii ejeki amagbiyanju awenu yii leemeji losu latifise atunse OGO wa.
Eyo ewe ewuro kan
Ori ako alangba kan
FANTA meji
Epo obo die,aogun won papo mose iwe aopin sori kankan merin
Aotu Fanta kan sinu omi ti afefiwe lale.
Aowapo eeru ikasi(ASHES)mo eko tutu,aofi pa gbogbo ara wa,aowafi omi yen we ose naa ni igun kookan tiyiofipe igun merin(Left,right, front&back)
Aoda awon kankan yen nu tabi ki ari mole.
Ti aba we tan aotu FANTA kansoso sita gbangba leyin ti atise adura sii.
Hmmm!Miofesoro repete,ti ebawe tan ki ewa salaye ise tobase larayin.
Dandan niki asiri yii je fun enitoba comment