06/11/2018
.........mo ki yin gbogbo eyin omo oduduwa........
ori ire je pataki ni ile aiye, ti eniyan ba je olori ire larin ebi, gbogbo ebi yio ma ponle, ti eniyan ba je olori ire larin ilu, gbogbo awon ara ilu yio ma sare too, lati le je ko ko, ori ire ran awon, nitori na eyin eyan mi ori ire je pataki fun omo eda, nitori idi eyi, iwo ti o fe ori ire fun ara re. gbiyanju asiri yii wo...
*******************************
lowa awo ekun ti o to owo otun, ori eiye osin,ori ologbo, kokoro aake 7, iko odidere, ewe ilu femi ka,ao lo si idi re ni ib ti o wu si, ao wa konle pe ase ori ire ree, pe oun la wa gba o, tabi ti so bee tan ao ja ewew re ao tun wa egbo re, ao lo si idi iroko, ao so fun iroko pe ase ori ire re la wa toro, ao pa ase ale ati aro re, gbogbo awon nkan won yii, o di ji jo papo, ao bere re jojo dede ago kan oru,ti a ba jo tan, ao lo ti yio kuna dada, ao ro sinu aato joolo, ao pa akuko adie funfun kan bo, leyin ti aba bo tan idi atoo joolo naa ko gbodo kan le mo, ao fi eje ediye yen si ni ara ati iye ree, ao wa ran apo a*o funfun to ni okun le nu, inu re la ma gbe atoo yi si, ao so ato yi mo ile ti ara re ko gbodo kan ogiri. ediye ti a fi bo yen, ama se edie yen ti yio lepo ni iyo, ikoko ape ti afi jo ogun yi, ao la si meji, gbogbo eran adie ti ase yen ama da sinu ree, ao wa se adura si, pe eyin osho aiye, eyin aje aiye, eyin le ma un so ori ire eni di ori buruku lati wakati owo yi lo, ki ori ire temi_________ omo________ ke ma le so di ori ibu mo, ki e je ki gbogbo nkan ori ire temi ko ma to mi lowo. ao wa ma toro gbogbo nkan ti afe... ile la fe ma ko ni, moto la fe ra ni, ilese la fe ni, okiki la fe ni, ao toro gbogbo oun ta fe na, ao gbe asee yi lo si ori fun awon agbalagba, ni ale.
lilo.ogun.na>
ama gbe bi apoti abi ijoko kan ti ale duro le lori, ni gba ti aba ri pe ojo sesee yo jade, ao wa bu ninu ogun yii, si owo wa, akin da owo bo ori ire ojo ki ojo ko ma yo, ori ire ekun, ni gbogbo eranko igbo fin pe sin ekun, osin o loruko meji osin ni osin unje, ati ewe ati agba, nise ni ki ema sin mi, gbogbo eiye igbo ni pe ri jo sin osin, ati ile ati ona lama fi unji ologbo, ni se ni won ma da owo ebo ti iroko, ilu femi ka loni ati ewe ati agba e ma fi oun rere yin fe temi, nitori, okorokoro ona lake so, ire mi a ko i shai san mi dandan, nitori yebe yebei odire ti iko idi re yebe yebe. ti a ba sa bee tan ao fi fo eko tutu mu lori nkan ti ese wa ko gbodo kaan le.
.