25/01/2025
OGUN JAPIRI TABI PAJA-PAJA
Lati owo alase fashola trado-medical Care.
1. GBERĘ JAPARI: Ao gun ewe osępòtú ao saa, ao joo lubulubu, Ao lo ose dudu ati omi idi igbin pelu ę. Ao fi sin ęsę naa kaa kiri.
2. CBERĘ JAPARI: Ao lo eso iwerenjeje, Eso lara (laalaa) pupa, igbę ediyę, Ata're ati Ętu-ibon po sinu omi osan węwę ao sin ęsę naa ni gberę ao fi paa
3. GBERE JAPARI. Ao lo egbo támólabiya lubulubu, ao lo etu-Ibon ati iyo obę ao fi omi idi igbin poopo, Ao sin ęsę naa nigberę o ao fi paa.
4. GBERĘ JAPARI: Ao lo ęsę érán étú di lubulubu, ao lo ewe tábà-ęgba, imi ojo, aidan, èèrù ati atare naa lubulubu ao poo po sinu omi osan węwę ao fi paa.
5. GBERĘ JAPARI: Isu ògìrì sako, ao lo lubulubu, ao po iyo moo, ao la osan jagunyin kan simeji ao daa si oju rę, ao maa fi gbo ara won pelu omi rę. Ao sin ęsę yen ao faa sii.
6.AGBO IWĘ-JAPARI: Egbo osan jagunyan, ati Ewe rè, Aidan, see po.
7.TI QWO TABI ĘSĘ BANKU RIRI : Taba gidi, taba oyinbo, kafura, kanafuru, Aidan(isu rę), èèrù álámó ati eyiti ko lámó, kanhun bilala, Aayu, Alubosa onisu, fi adi dudu poo, tu fi otun Shinap poo
LILO RE: Ao tę a*o silę, ao tę ewe kokò (coco yam)tabi ti ògèdè lee, ao san kini oogn yi mo ęsę tabi owo yen, ao fi a*o yen dii mpo, yio pę ki a to tu kuro nibę nigbati oba ti gbona moo daadaa.
From Prof Sidi-Ali