Ogun Abalaye ati ajesara

Ogun Abalaye ati ajesara A social platform for health and spiritual balance

28/04/2025

AGBO ERO OFA ASASI AIYE TO DAJU: - EKu asin gbigbe kan,oro agogo die,oro
adete die,etu ibon,ise eta odidi kan,aidan onigun,egbo ifon,egbo gbogbonise ao ki ni agbo
pelu oti lehin ojo keta odi mimu ni ekan soso lojumo.
NB: kose ma ni ni agbo yi fun idile kookan

Call or WhatsApp for spiritual and herbal solutions:09028498522

OSO AJO OJOJUMO (AKEESU) TO DAJU PA: - A o lo wa ole Inu eran ewure oojo, ewe alupaida 7, atare aja odindi 7, a*o funfun...
28/04/2025

OSO AJO OJOJUMO (AKEESU) TO DAJU PA: -

A o lo wa ole Inu eran ewure oojo,
ewe alupaida 7, atare aja odindi 7, a*o funfun opa kan , a o ko gbogbo re sinu a*o funfun
yen, a o wa di lenu , a o jo p.o., a o wa da sibi kan, a o lo wa ewure abo eyiti ko ti bimo ri ,
a o so mole sinu yara kan , a o se ise ti a jo yen , a o da papo mo eeri ogi ti ewure yi ba ti
waaje ounje yi tan , a o lo pa ewure na , a o la ikun ewure yi , a o ba ise ajo yen
lodindi ,sugbon kise jijo lama ban be pada ooo, a o wa kan apoti igi iroko kekere kan fun
ise na, a o ko opolopo owo ti a fi da loko, leyin ojo keje , a o ma lo mu owo nibe ,sugbon
ilaji ni owo ti a o ma mu nibe, yi o ma seku ilaji nibe. Eran ti a lo yen eniti aba se ise yen
fun eni na kogbudo je ninu eran yen o toripe sara lama fi eran na se.

Call or WhatsApp for spiritual and herbal remedies: 09028498522

28/04/2025

OMO TOUN JALE TI AO FE KIO JALE MO: - Ao wa isu jije kekere kan ti eniyan le
je tan lekan soso ti osi ni ori (head) ati idi (bottom) ti won ge ibi kankan nibe, ao wa lore
wa igbe ti eniyan ba su lai ni jeki eniyan mon pe a mu igbe re o, ao wa fi igbe yen re
gbogbo ara isu yen, ao wa sun isu yen ninu ina ti yoo jinna daada, ao wa bo epo ara isu
yen danu, ao wa fun eniyen ni isu yen je, gbogbo re lo gbodo je tan o, ti koba je isu yii
tan ko sise niyen o.

Call or WhatsApp me for spiritual and herbal solutions: 09028498522

Okan pepeiye, okan agutan, eso bomubomu, ewe emu, okan elede, ao di emu kan, aba kan, seke seke kan, abere 18 mo agadago...
28/04/2025

Okan pepeiye, okan agutan, eso bomubomu,
ewe emu, okan elede, ao di emu kan, aba kan,
seke seke kan, abere 18 mo agadagodo naa, awo
ekun ni ao fi ran.
Ofore – Sekeseke mu, Aba mu,
Emu ki mu irin ti ni agbede, Owu niti bomu bomu, Oran
haha ni se pepeiye, Oro huhu inu elede ni rasi, Akun sinu ni
ekun nkun,
Agadagodo bami mu nkan bayi bayi.

Very confirm, call or WhatsApp me for your herbal and spiritual solutions; 09028498522

15/04/2025

OGUN MAJELE INU OUNJE: - Tannatanna 9, eyo eyo atare 9, ao ko sinu okele iyan,
ao finu obe ewedu, ao gbe mi

Number mi: 09028498522

IWE ASASI, ABILU, PAAGUN DANU LARA: - Ao lo wa epo atare to po daada, egbo tude tooo die, ao gun ti yio Kunaa lubulubu, ...
15/04/2025

IWE ASASI, ABILU, PAAGUN DANU LARA: -
Ao lo wa epo atare to po daada,
egbo tude tooo die, ao gun ti yio Kunaa lubulubu, ao da ose dudu si, eyin adiye obu lao fi se omi re, ohun lao fi po papo, ao ko sinu ike funfun, ao gbe si ile iwe. Aki gbe wo ile oooooo...

Number mi: 09028498522

AWORO TO BERE ISE LESEKESE: - Ao lo wa isu ogirisako, Konjo tuntun kan, ao ge isu yi wewe, ao da sinu konjo yi, ao ko ew...
15/04/2025

AWORO TO BERE ISE LESEKESE: -
Ao lo wa isu ogirisako, Konjo tuntun kan, ao ge isu yi wewe, ao
da sinu konjo yi, ao ko ewe rinrin sinu konjo na, ao ha gbogbo aje ara tangiri to ka wo ja daada, ao ko le lori, ao bu oyin gidi aila le lori, ao tu da epo pupa si, ao da adin eyan si, ori
ni yio wo inu kehin, ao wa fi okun si lorun, ao gbe ko lenu ona.
Ojo taba se na ni oti bere sinu mu ero wa

Number mi: 09028498522

29/12/2024

MADARIKAN MASEKASIMI

Ogbe ori akuko adie, eyo atare mesan ao jo po ao fi sin gbere
9 si ori.

CONTACT:08082094348

29/12/2024

ISOYE TODAJU GIDI

Eja ojiji, ewe aran 9, ao lo po pelu ata wewe, ao fi se eja yi je
pelu epo ati iyo die. Jije.
Ofore –
Aran a ran mi leti,
Isoye a somiye,
Agbonji niti ojiji,
Ki ojiji wa ji mi leti,
Ohun gbogbo ti mo ba ti ko.

CONTACT: 08082094348

29/12/2024

OSOLE TODAJU.

10.Ewe awerepepe 201, ao lo kuna ao po mo se, oga gbigbe 16,
ao lo kuna ao teni ireteogbe, ao po mo ose yi, imi ojo alo fit e ni ifa
yi, ao fi oga aiye kan tele awo funfun, ao wa ko ose le lori, ao padie
fun ose yi.
Lilo – wiwe ni ago merin idaji. Ao gbo ewe iwerenjeje mo oti
oyinbo, ao ro sinu igo, ao gbe igo naa si egbe ose yi, ti aba ti we
tan, ao ma mu die die.
NB. A ko gbodo rin jinna ti aba nlo ose yi.

Contact:08082094348

14/10/2024

KI WON MAA LE BAA IYAWO WAA SUN
Ao wa Ewe Ewuro 3 ao fi nu idi bi a baa ya igbe tan ao jo pelu
odindi ataare kan ao po mo ori ao maa fi paa oko baa iyawo waa sun

WhatsApp tabi call: 08082094348

A social platform for health and spiritual balance

14/10/2024

AWURE (ASINA OGBE DI)
Odindin igbin apinu kan, ewe aje oojo, ata ijosi 16. sise re : ao
koko lo ewe aje naa loto, ao tun lo ata ijosi naa loto, ao wa fi
se igbin naa je l'odindin bee lepo niyo.. ti o ba jina tan, ao so
kale sori osuka a*o funfun kan, ao wa fi iyereosun te ifa odi-
meji.
Ao pe ohun re si : ayo kesekese fowo ba aje, okisi olomo adi oke rin.
ifa ti o mo odi ni won pe ni ogbedi, ogbedi o, o to gege kio wa
di owo nla fun emi lagbaja omo lagbaja loni o, ao se opolopo
adura si, ao da sinu obe yi, odi jije,, ao mu oti die le lori..
odara lopolopo ninu ose tuntun, yio je lase edumare!!!..
Call tabi WhatsApp:08082094348

A social platform for health and spiritual balance

Address

Asin, Ikole
Ado-Ekiti
234

Opening Hours

Monday 06:00 - 18:00
Tuesday 06:00 - 18:00
Wednesday 06:00 - 18:00
Thursday 06:00 - 18:00
Friday 06:00 - 18:00
Saturday 06:00 - 18:00

Telephone

+2348105065490

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ogun Abalaye ati ajesara posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share