Iwulo ewe ati egbo

Iwulo ewe ati egbo Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Iwulo ewe ati egbo, Medical and health, Ede.

29/07/2024

OOGUN OGBE INU (ULCER)
Ao wa efo gbure ..ao gbo daada ti yio MUN bi igbati won ja
ewedu..ao gbe sori ina..ao ni fi omi sio..
Ao da gari si ti obati gbona daada..ao fi teba...ao wafi eba naa je obe
toba wuwa...walahi walahi walahi DANWO...kosi bi ulcer naa se pe
Lara to..

29/07/2024
29/07/2024

STROKE (ROPAROSE)
ALUBOSA AYU,AO GE SINU IGO,AO WA FI OMI IGBIN SI,AO MA MU
NI SIBI MEJI FUN AGBALAGBA,SIBI KAN FUN OMODE
LOJOJUMO,OLOHUN KONI FI STROKE BA WA JA OO.

29/07/2024

OGUN INU RIRUN
AKOGUN,AO RE SINU IGO KAN,AO FI OMI TUTU KI LAGBO,AO MA
MU NI SIBI KOOKAN LOJOJUMO

29/07/2024

OGUN JEDIJEDI

EWE EFINRIN,EWE OWU AKESE,EWE EWURO,AO WA OMI TUTU
GBO PELU IYO DIE,MIMU LAROLALE.

29/07/2024

OGUN IDI YIYO
AO FA P**I EGE(CASSAVA) OLOMO KAN TU,AKO NI JE KI O KAN
MOLE,AO WA JO P**I NAA PELU IYEPE ARARE ATI ODIDI ATARE
KAN,AO MA FI FOKO

29/07/2024

OGUN IKO
EGBO IPETE,EGBO IFON,AO GE KEKEKE SINU IKE RAGOLISI,AO BU
IYO DIE SI,AO WA TU OMI ORORO MAALUSI,AO WA GBE PAMO FUN
OJO META,AO MA MU NI SIBI KANKAN.

29/07/2024

OGUN IKO IFE/AWUGBE (ASHTMA OR TB)
EWU OGAN, OBU OTOYO ADIN DUDU.
AO DA EWU OGAN YI SINU IKOKO ORU TI A O SUN TI YOO DI ERU, TI
O BA TI FE DUDU TAN AO FI OBU OTO YO SI NI IWON BA, AO JE KI
EWU OGAN TI ATI JO YEN KI O TUTU, A O WA BU ADIN SI, ENI NA
YOO MA MU NI SIBI KANKAN NI ARAARO

29/07/2024

QUICK EJ*******ON
Orogbo, obi gbanja,etu ibon,ako okuta,esuru funfun,ege tia fi ngun
iyan,ogede agbagba dudu,agbado ,iyere,ao fi sugar die si, ao gun
po,ao ma fi fo eko tutu mu.

29/07/2024

AGBO INU IGO FUN ALE OKUNRIN* (MAN POWER) part 1
Itaku gbonyingbonyin,Itaku eruju,ao ge mejeji sinu igo kan, ao wa
ro 7up si tabi oti oyinbo, gaasi kokan ni ojojumu.

Address

Ede

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Iwulo ewe ati egbo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram