Adifaselojo trado home pelu ewe ati egbo adayeba

Adifaselojo trado home pelu ewe ati egbo adayeba Igbinyanju loni ile ayee,masun,maduro,makanju

Ultimately, health is our greatest asset.

By prioritizing it, we not only enrich our own lives but also gain the strength to uplift and support those we care about.

25/11/2025

Focus and stay strong πŸ’ͺ

25/11/2025

πŸ”₯πŸ”₯πŸ”₯ISE EYONU AWON IYA TOGBONA πŸ”₯πŸ”₯πŸ”₯

Epo obo tofin mu dada ,ewe ajeofole tutu ojoo,ewe iyalode mejeji,ewe aladun ojoo,omunu ewe akoko,Ao gun gbogbo papo,Ao fi oronro malu po Ose naa dada , Ao ko sinu ike funfun, Ao ma we ni igbakugba odaju

Tio baje ki Oje fun ooo
Sope ewe aje oooo
Please share and like and comment
Ire oooo

Tio bani ohunkohun tio ruo loju kan simi
☠️☠️☠️☠️☠️☠️

25/11/2025

They left him alone

25/11/2025

Toba se igbinyanju lati je eniyan ninu aye mase Adura

07/11/2025

πŸ”₯πŸ”₯πŸ”₯EYONU AWON AJEπŸ”₯πŸ”₯πŸ”₯

Odindi okete tutu, ao ge gbogbo iru re ati ori re kuro. Ao tu ifun re
danu. Ao fo dada. Ao wa ge okete yen kekeke sinu awo sobi tio ba
di ale, ao fi eko kan le lori. Ao bu opolopo epo pupa le, eepo iginla
die, eepo obo die, orogbo kan, obi abata kan, atare kan. Ao ko le
lori. Ao gbe siwaju ita gbangba ile wa. A ki gbesi orita meta rara o.
Ako gbodo jade mo ti abati gbe sita. Bi ile ba ti mo, ao lo ko
gbogbo ohun ti o wa ninu awo yen yatosi orogbo ati obi pelu atare.
Ao wa fi ori okete yi tele inu ape. Ao fi okun ti oku si oju ona si ati
ewe kilefimise ati gbogbo ohun ti ako ninu awo ipese yi. Ao jo po.
Ao fi epo pupa si ori aro meteta. Ao wa jo ,at a ijosi ni ao ma fi ko
ina re , ti abati jotan ao tenu ejiogbe ao pe ohun re si

lilore: ni ale ao bu epo pupa sinu abo loto lona meji, ao bu etu yi si
ona mejeji ao fi iyo sinu ikan ao la iyen, ao fi eyiti ako fi iyo si yen
para ako gbodo jade movtiti ile yio fi mo.

Ohun Re : ise kii se aiye ku emi l omo. l ma se ise laiye mi edi ki di ile
kin ma sise laiye mi ki edi ma my mi, ebo riru kii mu ogun , odifa
fun alafia nigbati onti ikole orun bo wa si ikole aiye, nigbati ode ile
aiye , osho ile ni awon yio gba nkan tie lowo re, oni sebi moti rubo
fun esu, won kini ofi rubo, oni ewureewure ewure, woni awon kofe
oni obuko, woni awon kofe, oni ikeregbe dudu toun ti omo redede
labe, woni awon kofe, oni emi ( kini) eo gba, nigbati ogbe okete
de. ode oya enu koto orin awo bo silenu, onse iya gba okete gba
okete, iya osoronga, iya gbokete ma gba eniyan, iya osoronga, owo
ti mo ni ti yin ni,aso ti mo ni ti yin, kin di eniti gbogbo aiye yoo ma
mo si rere lati oni lo, adura.

Tio bani ibere kan simi or message mi
Sope temi adara

07/11/2025
19/10/2025

ELEYI NI AGBO INFECTION TOGBONA KOSI IRU INFECTION NAA YIO FO PATAPATA KURO LARA NI IWO TI OBA FE KI ISE YI JEFUN O GNIYANJU LIKE E SHEAR RE KIO SI COMMENT ADURA WA YIO GBA
🌿🌿🌿AGBO GENERAL INFECTION 🌱🌱🌱.
Olojongbodu leaves, Ipeta herbs, Inabiri Egbo, Baara, Epakun, Baka, Alamo, orange, bitter sugar will not be put into white plastic like 5 days. We will drink in the morning and at night for 15 days.
Osise fun,πŸ‘‰πŸ‘‰πŸ‘‰ staphylococcus, syphilis, gonorrhea, sexual in*******se,
EMI NAA NI OMOAJEORUN πŸ§™πŸ§™πŸ§™
FUN IWADI OHUNKOHUN OKANSIMI
IRE OO
SHEAR RE KIO SI LIKE E KIO SI COMMENT TIO BAFE KI ISE YI JE FUN OOO
GBOGBO WA ONI FI AISAN LOGBA

11/03/2025

Wealth shall locate us (amen)

11/03/2025

Prayer for all my family here on Facebook

10/01/2025

Respect to all witches πŸ™‡β€β™‚οΈπŸ™‡β€β™‚οΈπŸ™‡β€β™‚οΈ

25/12/2024
07/12/2024

Address

Ewu Ogun

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00
Saturday 09:00 - 17:00

Telephone

+2349067650781

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Adifaselojo trado home pelu ewe ati egbo adayeba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Adifaselojo trado home pelu ewe ati egbo adayeba:

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram

Category