Ewe ati egbo Ogun ibile todaju

  • Home
  • Ewe ati egbo Ogun ibile todaju

Ewe ati egbo Ogun ibile todaju Ona abayo fun orisirisi aisan ati igbiyanju eda.

24/04/2025

FUN IWO TI O KO RI NKAN ALEJO REMO TI O KO SITI DI ARUGBO

1) Egbo tude, kanfo, ewe tude tutu, ao lopo sinu omi osan lakuregbe, ao wa SE Lori ina, ao ma je asaro( ebe) tele inu kia to wa mu agbon cup kan Le Lori.
2)ewe esunsun pupa, epo oruwo, osan, kahuna, alubosa, epo, ao fi omi dun sepo, cup kan laro laro.

ODAJU!!!

24/04/2025

EYONU OWO!!!

Agbon meji ao jo omi inu re, ao fi omi inu re yen gbo ewe sinkinmini, ao yo omi na, ao da lofinda tabi perfume toba wuwa si, ao fi #1000 tele igun ile, ao wa gbe ogun yen le lori, ao wa fi epo obo le lori, ao wa ma fi para losi ibi ise wa.

Fun iwo tio ko ba le SE fun rare, o wa fun tita
ODAJU!!!

24/04/2025
16/10/2023

Ohunfa kositoma!

Iwo tio bani shop tabi ile ise nla , Alfa tabi pasito nio ni ise yii.
Gbiyanju lati wa kanhinkan ibile iyekiye, ao jo pelu odidi atare kan, ao lo efun mo, ao ro sinu ado kan, ao jipo daada, ao toju re pamo sinu ile ise wa, to kositoma bati dide lori ibi tio joko SI, ao mu ao ta die si ori aga tabi eni tio ti dide,

Fun iwo ti o kole se ise yii fun ra re, o wafun tita lowo tiko gunpa, WhatsApp+2348128100596

16/10/2023

As Sugar Attracts Ants......So shall your hands will attracts plenty money from today.i solve problem like..

*Instant Money
*Married issue
*Business Boom
*Court Case
* promoted at work
*Spiritual Husband

if you need my help,in any kind of spiritual problem, call me on+2348128100596 or message me on Whatsapp,

16/10/2023

ENI OJO AJE!!!
It's Monday it's new week
Good thing shall locate you today
What so ever you lay hand upon today shall prosper
Eledumare open new door for you today
AJE Olokun oguguniso,oniso iboji
Aje alaso ala funfun gboooooo
Aje ko sare tete wa je wa
Awa oni se eru AJE l'ose yi ooo
Ta ba ti nnawo a ma ri mu
Ta ba ti nla enu a ma ri pe
Aje ko je wa ni gbogbo ona
Ose yi a san wa oooo
A oni ba ode pade
A oni jade le iku lowo
Ayunlo ayunbo ni owo nyun enu
Ina ogo wa koni ku
ASE NTEDUMARE
ONFA KO FA IRE AJE WA FUN GBOGBO WA
ASE OOOOOOOOOO!!!!!!

16/10/2023

Agbalagba ton to sile!

Ao Jo igbe die, ewe arun fofo ati atare po, Lila diedie.

Danwo kio fun mi ni abo.

16/10/2023

Adaajina (unhealed wound)

Ao ha iyepe ara ogiri, odidi atare kan, ao jopo, ao lo Kuna, ao fi die sin gbere yika egbo na, iyoku ao Po mo ose, ao ma fi fo oju egbo na,

odaju danwo kio fun mi labo!

06/10/2023

ITAJA!!!

Iwo tio n taja ti owo da lowore, bami gbiyanju iseyi wo,ao gun kanfo rogodo meta pelu ewe abamoda mo ose eyikeyi,ki o ma fi we na kio firi owo ta oja re.

06/10/2023

Eku owuro o, eledumare a bawa se o!

05/10/2023

ATOSI!!!

Ao wa bara, ao wo egusi inu re danu, ao ge kekeke sinu keg kan, ao ro ogidi emu tabi oronbo si, kahun bilala die, leyin ojo meta odi mimu, yio ma yawa nigbe o, glass cup kekere kan kia to jeun aro.
ODAJU!!

04/10/2023

OGUN INU RIRUN

Ose dudu die, iyo die, ogogoro eyikeyi die, ao wa po gbogbo re papo mo ara won, ti yio se lubulubu daada, ao wa da sinu ogogoro yen, ao wa jipo daada, ao ma loni sibi meji laro, losan ati lale, ti eniyan baje nkan tikoda yio po gbogbo re dasi ilenle,
Odaju!!!

Address


Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ewe ati egbo Ogun ibile todaju posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

  • Address
  • Alerts
  • Claim ownership or report listing
  • Want your practice to be the top-listed Clinic?

Share