Omo akufo herbal center

Omo akufo herbal center Fun itoju gbogbo isoro

18/08/2024

Aseje ebe awon agba
Ewe ati egbo AJEOBALE,,ati ewe ati egbo ORIJIN ,, ataijosi die aolo papo aofise eyele funfun kan ti agesi 16, lepo niyo aoje pelu adura

31/05/2024

Aseje asina
Awo EKUN die ,,obe kan ,,oga gbigbe ibile kan ,,1000 new note,,ataijosi ______ aolopo aofise Ori ogunfe kan aogesi 9 or 7 aose lepo niyo aokoje a*o tobadara ni aowo je

Order for your selfWhatsApp 07036491297
29/05/2024

Order for your self
WhatsApp 07036491297

20/05/2024

Ose eyonu ,, igbin apinu kan,,ewe ajeobale tutu,,ewe orijin,,epo obo aogun mose aoko sinu Ike funfun aomawe laro laro

Happy new month
01/05/2024

Happy new month

Imule ni Ebe awon agba ni eyonu to Rin jina ni EYE KANAKANA KAN. EYE KOWE KAN. AOKO SINU APE TUNTUN AOFI EYE OWIWI KAN S...
13/04/2024

Imule ni Ebe awon agba ni eyonu to Rin jina ni EYE KANAKANA KAN. EYE KOWE KAN. AOKO SINU APE TUNTUN AOFI EYE OWIWI KAN SI AOFI TAKO TABO EYE EGA LE AODA ATAIJOSI KONGO KAN LE.AOFI ATARE KAN .AOJO AOLO KI AMAFI OTI TABI OGI GBIGBONA LO

07/04/2024

Eyonu awon agba
Adire akuko opipi kan,,eye kowe kan,,obi ifin OLOJU 4 toje 16,,obi IPA toje OLOJU 4 toje 16,,aopa akuko opipi ye sinu ape Aoko awon inkan ye le aoko ewe ajeobale tutu,,ewe orijin,,ewe alupaida,,ewe ailu,,bo ataijosi laofi Kona re odi jijo aolo aoro sinu Ike funfun aomafi eko tabi oyin lo lale

Oso eyonu aye  Ori ewure ati ese re mererin pelu okan e aoko sinu isasun tuntun Aofi eye kowe kan le aoko isu gbegbe 3,,...
06/04/2024

Oso eyonu aye
Ori ewure ati ese re mererin pelu okan e aoko sinu isasun tuntun Aofi eye kowe kan le aoko isu gbegbe 3,,eru awonka Siri 3,, gbogbo owo currency ti oba wuwa aokole Aofi atare kan le odi jijo aolo aoro sinu sere tabi iGO funfun aomafi oti tabi eko lo laro laro

06/04/2024

Awebidanu ewe ajeobale die,,ewe egele die,,epo obo die aogun mose Aofi oronro malu Po aowe fun ojo 9 lalale

16/03/2024

7036491297
Emiola ismaila
Opay
Fans please support us with any amount o🙏🙏🙏

03/03/2024

Ebe awon agba. Akuko adire asa totobi kan aopa sinu ape aoge obi gidi kan SI 201,,orogbo 201,,eyo atare 201,,eye kowe kan,,aoko epo obo,, epo igila,,ewe ajeobale tutu,,ewe orijin,,ewe alupaida bo aoda epo pupa iGO kan le Lori aojopo aolo aomafi eko tutu tabi oti lo lalale

22/02/2024

Address

Ibadan

Telephone

+2347036491297

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Omo akufo herbal center posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Omo akufo herbal center:

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram