29/06/2025
MOKI GBOGBO ILE PATAPATA WIPE AKU ASALE ONI YII OOO
AO NI DAAMU PELU OGO OLOHUN
TOOR AWA TIA WA NINU OGUN IDIWO ATI IDENA NIMO FE BA SORO, YALA ALFA, WOLI PASTOR TABI BABALAWO OR ONISEGUN
OPOLOPO LOTI GBIYANJU T**I SUGBON KOSI ONA ABAYO
AWON AGBALAGBA LO NDI ISEMI AIYE ELOMIRAN LOWO, ELOMIRAN TI SO OPOLOPO AWON TIO NSISE FUN DI ONIRO LATARA WIPE ISEMI AIYE RE KOTI KURO LOJU KANNA
DAKUN BAMI GBIYANJU ASIRI YII
AWON AGBA KONI RI IRIN AJO TIO FE RIN LAARIN ODUN KAN
OOOOGUN NBE ASIRI SIWA, IWO TIO BATI PADE ALAWOORE TIE LOKU
MA SO BEE MO, ENITI O DURO NI TIE TI TAN
SUGBON LAI DURO AO DEBITI A NLO
Eyin adire ibile 3, igba olomori kan, ewe tangiri topo, ao gbo lomi, omi re lao fise eyin yen ninu igba, ao da omi yen sinu igba, ao fise eyin yen jinna, Tobajinna, ao bo epo eyin yen, ao je, inu igba yen lao bo epo eyin yen sio,
Ao wa lo ja ewe ajeobale, ao ko sinu igba ti epo eyin adire wa yen, ao wa lo boo mo ori akitan pelu epo eyin adire naa,
IWE RE
Ewe peregun ati egbo peregun, ewe tude ati egbo tude, ao ko okuta ako 9 sinu ikoko, ao wa da awon ewe ati egbo yen sinu ikoko, ao fise lagbo
Ewe peregun die ati egbo peregun die, ewe tude die ati egbo tude die, ohun lao fise ose tia o fiwe
Ao wa a*o pupa, ao so mo orun owo mejeji ati orun ese mejeji,
Ibiti o ba mo daada lao ti we ooo, ibiti ao siti ma ri sanmo lao ti we ose yii, tia ba we tan, ao tu a*o yen kuro lowo ati ese wa, ao boo kahinkahin ati a*o yen monle, odi ojo keji kia to jade losi any where
Ale lao we ose yii pelu ago yii.
Ao gbodo fi omi la agbo yen ooo, ao gbe kale tiyio fi tutu nio.
Mofi ojo tima jade kuro laye bura tio ba gbiyanju re ti isemi aiye re tun ri bakanna dakun jade to awon agbalagba lo, o lee fi owo re se nkan ko je niyen oooo.
EJEKI adupe ore olodunare kolejeee
Efunyemi 1