Olorunloni Wosan Traditional Healing Center

Olorunloni Wosan Traditional Healing Center Oluwo osun Alawoye anything you need,ifa initiation and all orisa initiation or spiritual work message me private or chart with me whatapp

Ọlọrun Olodumare modupe ooOri mi modupeIfa olokun asorodayo modupePe mole lodun kan sí lókè erupẹ Happy birthday to me
19/05/2024

Ọlọrun Olodumare modupe oo
Ori mi modupe
Ifa olokun asorodayo modupe
Pe mole lodun kan sí lókè erupẹ
Happy birthday to me

Aku ọsẹ ifa lóni oooIfa niAja loku lofi Egun sayeAdìẹ loku lofi wuwu silẹÌgbín losubu tohun ti ikarahunAdifa fúnORUNMILA...
02/06/2023

Aku ọsẹ ifa lóni ooo
Ifa ni
Aja loku lofi Egun saye
Adìẹ loku lofi wuwu silẹ
Ìgbín losubu tohun ti ikarahun
Adifa fún
ORUNMILA
Wọn di ẹrú asingba silẹ won ni komo gbé lọsí ode òrun
Ẹbọ lawó ni kose
Njẹ
Òjíṣẹ orun kìí jẹ ila
Ìdènà ọrùn kìí jẹ ikan
Olódùmarè kìí fojú ba iko
Ẹgàn roro gori awo
Ori awo ako asingba
OLÓDÙMARÈ MAJẸ KABA WỌN YỌRUN OSAN GANGAN OOO
L'ASE EDUMARE

Address

Ibadan

Telephone

+2348063777504

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Olorunloni Wosan Traditional Healing Center posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram