15/09/2025
OOGUN TI OTA FI NJADE LAYE / ASINA NLA
Ao lo ra opolo ijokun nla kan, epo obo,igo epo pupa kan...ikoko tuntun...
SISE RE...ao fi owo mu opolo yen...ao se adura si leti otun...ao sepe iku fun awon ota wa nni eti re keji...ao wa fi si inu ibi kan...
Ao da epo pupa yen sinu ikoko tuntun na...ao wa gbe kana...ao je ki epo yen o gba daada...ao wa ju epo ebo sinu re...ao tun ni suuru ki o fi din daada...ti o ba se die ti a o gbo dindin epo obo yen mo...ao wa ju
opolo yen si ni aaye...yio si ku lekaana...ao wa ni suuru ki opolo yen o fi din daada...
Ti o ba ti gbe daada...ao wa so ikoko yen. Kale lori ina...ao fi nkan yo opolo to ti din gbe sori olo ati epo obo yen...ao wa gun won papo mo ose dudu...epo ti a fi din yen ni ao fi po ose yi....ao wa ko ose na sinu ike funfun olomori kan...
Ao ni suuru ki epo toku ninu ikoko yen o fi tutu daada..to ba ti tutu, ao wa da sinu ike kan.
LILO RE...Ao ma fi ose yen we ni ale ati aaro...ti a ba ti we ose yi tan..ao fi epo ti a ro sinu ike yen fi ra idodo wa..opari.gbogbo ota ti o. Ba ndi ire ayo wa lowo ni yio ku koto di ojo meje!!!...e danwo ni kiakia ki e fun mi laabo ise yi oo..
O wun mi ki gbogbo wa o bo lowo ota...olorun yio si je ki a ri ogo wa loo