20/03/2023
Otito oun togun tiko ni opin ni won n pe ni oogun,sugbon dandan ko ni kio je wipe eronja oogun gbodo je pupo,nitori loju elomiran ti eronja oogun o bapo kii joju loju e,emaa gbinyanju kie maa dan awon ise ti mo n fisile yi wo kie yin olorun logo,kia maa se diedie bayi nitori eni ti koi tii ri 5k to maa fi jeun se iru eninaa lemaa sofun wipe kio lo wa 30k wa kio wa se aajo.hmm, oya sare bami dan eleyi naa wo kio fun ile labo.
OSOLE TO DAJU
EYO OWO 16
OKO ATARE KAN
EWE EJIRIN LOPOLOPO
ORI OLONGBO TONIRUN DAADA
SISE RE==>Ao koko mu die ninu ewe ejirin yan aosu bii osuka,aogbe tele ape tia fe fijo ise yi,aowa gbe ori olongbo yan le,aofi oko atare yan si legbe,aowa to eyo owo yan yika re bosewa ninu aworan yi,aotun mu ewe ejirin miran aosu bii osuka aogbe le lori mole,aowa jo tia ba jo tan,aote ni ifa ogundabede lori olo,aowa pe ohun re si,leyin naa aoko sinu ike kan,aomaa fi oti loo laarolaaro.
OHUN RE==>Ti a ba fa ejirin,ejirin a fa igbo,ki eni to momi,ki o lo fa eni ti ko momi wa,ologini kii dara t**i ki o mo jale,ogundabede olori ole,bose jiji,bose yiya,bose wiwa,elo ree dagara owo lanla wa fun emi lagbaja omo lagbaja,lati odo omode ati odo agba,ati odo okunrin ati odo obirin,Ase
Fun Ibeere 👉 08146378639
Lati owo alase ati oludasile yara==>TEWE TEGBO TI OLORUN NI.