Asiri Ogun Adayeba Baba Tapa

Asiri Ogun Adayeba Baba Tapa Spiritualist

Asiri Ogun Adeyeba Baba Tapa
20/04/2023

Asiri Ogun Adeyeba Baba Tapa

20/04/2023
20/04/2023

Baba Tapa....

21/02/2023

NAME:- wealth soap, this soap is to make anyone rich within a short period of time. It attracts helpers and opportunitie...
18/02/2023

NAME:- wealth soap, this soap is to make anyone rich within a short period of time. It attracts helpers and opportunities, changes failure to success, boost sales massively. This soap can be used by just one person (can't be shared), avoid s*x during the period of bathing this soap, it must be bath with native sponge, a little sacrifice like killing of a goat, fowl, ram should be done before/after/during this period as sacrifice.
Using for clients: they must surely pay 💯
If you think anyone will cut soap for you, well dey play.

Don't fold up your hands and allow the evil ones to destroy your destiny.

Neck beads aren't just worn to adorn our necks, wrists, waists etc. nor are they worn to intimidate or scare others with...
15/02/2023

Neck beads aren't just worn to adorn our necks, wrists, waists etc. nor are they worn to intimidate or scare others with the believe that we are in a particular system of spirituality.

RESPECT is the primary purpose of ileke, ide, eleke, osun, they showcase the humility of the wearer to the physical and spiritual realm while simultaneously demanding mutual respect from any external force(s). Hence, it results to the safety and protection of both parties.

If you’re interested message me ❤️

11/02/2023

*BI ỌMỌ BA JA OLE*

*Ọmọ na yio yà igbẹ sínú isasun titun kan, ao wa fi odidi atare kan lè lórí igbẹ na, ao wa de fún ọjọ́ méje, tí ó bá di ọjọ keeje, ao wa jọ, ao lọ tio kunna dada, ao fi ẹbu yí sá gbẹrẹ mẹta mẹta ni isalẹ ojú mejeji,*

*IKILỌ :- Ao fi aṣọ kan di ọmọ na lójú, tí ọmọ na kò gbọdọ fi ojú rí ẹniti yio sá gbẹrẹ na, kosi gbọ́dọ̀ ma ẹniti o sa gbẹrẹ na*

*BI ỌMỌ BA NJALE*

*Ao wa ikamudu to ndarin kiri loun nìkan, yio jẹ mẹta, odidi atare kan, epo pandọrọ diẹ, igbẹ ojú ọna to tí gbẹ diẹ, ao wa joo papọ, gbẹrẹ yíká ọrùn ọwọ́ rẹ méjèèjì àti gbẹrẹ kọkan nisalẹ ojú rẹ...

11/02/2023

IFERAN TIPATIPA LATI RI ANU GBA TABI LATI RI OKO TABI IYAWO FE...

Ewe isu ọọlọ ( ìṣù igangan Pupa), ewe egunsi ito osun efun ao lo won papo ao wa sa ko gbe ao wa tun lo dada, ao wa teni ifa eji ogbe ao se adura si pelu oruko eni na, ao da sinu cream wa ao ma fi para, ti aba fe ko sise dada inu ipara funfun ni ki a da si ooo.

Asiri bibo Ewe Ina ewe esisi oju eyele kopo die bisiki die ao lo gbogbo e papo ao dasinu Lofinda to loorun dadaaa tested okay ✅

11/02/2023

*MAYEHUN AWISE TODAJU*

Ori ooni tiko ni agbondo rara, ti aba ra eyiti oni agbondo, ao ri wipe, ao yo gbogbo agbondo re kuro patapata ki ato lo, awa woo ori naa pepepe da sinu agbada ti ao fi jo, awa ko ewe abamoda eyo meta 3,odidi atare kan, le lori, ao jopo ,alo kunna dada, awa ro sinu igo funfun kan, awa tun lo ata ijosi gbigbe ti yoo kunna dada nigbere fuu lai fomi kankan si rara, awa ta ebu ogun ti ajo die le lori, ao bu iyo isebe die le, awa po po dada, awa maa to sori ahon ba eeyan soro tabi gba nkan lowo re, o daju.

11/02/2023

Asiri psalm

12,21,42,70,72,75,112. Ao ka awon ese bibeli yi sinu omi ever water nla kan oni 250 # ni ojo kan pelu awe , ao wa ma mu lararo tia ba ji lai ti Soro si eniyen kokan fun ojo meje
Divine favor
Odaju

Asiri psalm
Ao ra iyo Kongo meji tabi meta ao wa ka psalm 51 si ngba meje ao gba Adua itusile si amubo promise and fail si ao ma bu die die sinu omi iwe wa , akiyesi walai ija ma waye tia ba n lo ise yi fun idi eyi ka soraa fun ija odami loju

Ori bibo ilana Christian

Eja abori , iyo,,sugar oni Koroo , orogbo , obi gidi ao ko gbogbo e sinu awo lototo, ao wa ka psalm 24 ngba meta si psalm 51 ngba meta , pelu oruko mimo yi VAH 21*
Ao fi se adura gidi gidi ao La die die ninu awon sugar iyo ao je die die ninu obi orogbo ao je die ninu eja otan

11/02/2023

ASEJE OWO KIAKIA
Ogede omi merin eyin Agric merin ao fo papo dada ao wafi ori sinu agbaada tobatiyo dada ao wa a won nka ti afi owo fo yen papo dada ao fi iyo sii

ASEJE ASIRI BIBO
Ewe aje, ewe sawerepepe pelu Ataijosi ao gun mo alubosa funfun pelu ori okete Kan ao wafise eran molu ekiri meta je pelu eyin Agric meta ao wa se lepo niyo ao wada aniyan sii owo nla nla si leyin na aojeni ihoho Omo luwabi odaju

ASEJE OWO TODAJU PA
Ewe omisimisi onitakun oojo, ewe abamoda oniga meta oojo, ewe sawerepepe oojo, ewe tanagbowo oojo, ewe onitiku oojo, eyin adiye ibile meta, iyere die tabi Ataijosi die, asisu ao lo gbogbo awon eroja naa papo ao fi din eyin lepo niyo ti o ba Jina tan ao so ori osuka a*o kosi eeyan ti ko le je aseje yi, a bawa Lara mu

11/02/2023

Asiri bibo
Ewe sawerepepe 201 , itana sawerepe 201 ao lopo ao dasinu otin schinap ao ma mu lararo
O gbiyanju

Ipara anu todaju
Ororo Goyal kan agbon to lomi ninu kan ewe owu akese ojoo 16 bintu original kan ao gbo ewe yi pelu omi agbon yen ao se idiot e danu ao ja bintu yen sinu omi agbon tia ti gbo ewe si yi ao wa da sinu ororo goyal yen ao gbe pamo
Ao bere lilo e lojo keji ngba to ba wuwa
Odaju o
Ao ma ri Anu gba nio tested ok

*MAYEHUN*A*O OSU OBINRIN, A*O WERE GIDI DIE, ETU IBON  OJUDA, OSE DUDU, AO GE ORI ALANGBA ADARIPON, AO KI ATARE AJA KAN ...
11/02/2023

*MAYEHUN*
A*O OSU OBINRIN, A*O WERE GIDI DIE, ETU IBON OJUDA, OSE DUDU, AO GE ORI ALANGBA ADARIPON, AO KI ATARE AJA KAN BO LENU, AO WA LO FI SI ENU OGIRI TOLANU FUN OJO META, AO WA GUN GBOGBO RE PO MO PELU AWON ERONJA TOKU NI ARO OJO KEJI, AO PO LOSE DUDU, AO WA GBE OGUN YII LO SI IDI EGOO TIKO TI TU, AO FI BO LARA, TO BA DI EHIN AGO MEJILA OSAN, AO KO IWO ETU LO SI IBE, AO MA KO SINU IWO ETU NA, AO MA FI BA ENU SORO... ENITI OLORUN BA FUN SE, KIE FUN WA LAABO LORIE...

*AFOSE*
ORI OKA AGBOJO , INA ESISI FUNFUN PELU ODIDI ATARE KAN, AO JO PO, AO MA FI BA ENU SE ADURA...

*OGUN AWOGBA ARUN TODAJU*
AAGBON TI WON TI LO DAADAA TO TI JA NI IDI, AO GE KEKEKE SINU APADI, IGBA TI WON TI FI GUN OPE TO TI GBOO DAADAA, AO GE OHUN NA KEKEKE AO KO SI,AO MA FI IHA TAN INA SI T**I YOO FI JO TAN, TO BA JOTAN, AO LO ,AO WA LO WA EPO AYAN, AO GUN KUNNA DAADAA, AO TUN GUN ERU ALAMO NA KUNNA, AO WA DA GBOGBO RE PAPO, AO WA PO LOSE DUDU, AO WA PE OHUN YII SII;
OHUN RE👉AGBON KO GBON GBOGBO IBI ATI ARUN ARA EMI L.OMO.L, AYAN KO YAN GBOGBO ARUN DANU LARA MI, ENI KO NI GBOGBO IBI ARA MI DANU, IHA KO HA GBOGBO ARUN ARA MI DANU...OMI TUTU YIO NI AO MA FI WE ...

*OSHOLE OWO TODAJU*
EWE EYINOLOBE FUNFUN, EWE PAPA*ON FUNFUN, OLE INU AGUNTAN, EWE SAWEREPEPE, ODIDI ATARE KAN, AO JO PO, AO RO SINU SEERE KAN, AO PA EYELE FUNFUN KAN FUN, AO GBE SI IGUN YARA ILE WA, AO FI A*O FUNFUN BO MO BE, AO MA FI OYIN IGAN OJUDA LA LAROLARO...

Address

Ijebu Igbo

Telephone

+2347052369852

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Asiri Ogun Adayeba Baba Tapa posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram