11/04/2018
EYONU AWON AGBA TODAJU
----eyin adie ororo 3,aofi tele ape,aoko epo obo lelori,odidi atare kan,ewe anu,ewe orijin,ewe ajeobale,ewe owo,ewe oyo,aojo gbogbo re po,aolo iyo mo,ogbe iyonu ni ifare--OHUN RE---haa!3x,olukibinu olu 3x,osinkibinu osin 3x,obajalaye ki binu oba ajalorun 3x,oba ajalorun ki binu oba ajawole 3x obajawole ki binu oba aja dobiridobiri 3x oba aja dobiridobiri ki binu oba atiledilele 3x otoku ilu ki binu ko iyosile komaje 3x oso ki binu kiwon ko iyo sile kanmaje 3x enikan ki fi oyin senu kotu ito 3x beni enikan ki fi iyo senu ko pose 3x mulobe ni oruko ti ifa npe iyo,yowon ninu gerege ki omode mayonu simi,ki agbalagba ma yonu simi------emi-omo----lati oni lo.eyiti abafe dasinu oyin laote ni ogbe iyonu ooo,aomala lararo,,,,,08030805064