Fajemisonu Ewe Ati Egbo Trado-medical Herbalist

Fajemisonu Ewe Ati Egbo Trado-medical Herbalist Fun Ilera Ati Isoro Eda, Ilera l'ọrọ.

20/09/2023

AWEBI DANU IWE ODO TODAJU TESTED AND CONFIRM ✅

0 00
00 00
0 00
00 0

IKARAHUN IGBIN KAN AO LO TI YIO KUNNA DADA AO PO MOSE DUDU AO PIN SI ORI KAINKAIN MESAN AO WA TEFA YIII SI ORI OSE NI ORI KAINKAIN KOKAN

GBOLOHUNREE 👇

MOSISE SISE BI AILANI ARA, MORANMURANMU BI ALAI NI EYAN, BI ISE BASENI NI ASEJU ARA ILE ENI AKONI LOMO ODIFAFUN OKARANN OMO AWESENU LOJO TI OLO WE ISE OMI SINU IGBO, ONI IWO OKANRAN OMO AWESENU LOJO MALO WE ISE ISERE SINU IGBO ONI TORIPE ISE INU IGBO APADAWA BANI NIBE, ONI IWO OKANRAN OMO AWESENU LOWE ISE REE SINU OLUWERI EMI L-L MOSETAN LATI LOWE ISEMI SINU OLUWERI, MODI OLORIRE MODI OLOWO, OLOLA, OLORO, ENIYANN PATAKI, BOROKINI, ESO FUN ALARA PE MOTIDI OLORIRE, ESO FUN AJERO PE MOTIDI OLORIRE, ESOFUN ORANGUN ILE ILA PE MOTIDI OLORIRE EMI L-L GBOGBO IRE MI TOSONU TI PADADE OOO ( AO FI OSE NAA WE SI ODO TONSAN GIDI PELU OPOLOPO ADURA..ODAJU

BABA YIN NI MOJE TIO BASE YIO JE FUN O NI AGBARA OLODUMORE.

Address

No 90 Adin Street
Ilawe Ekiti

Telephone

+2349043283343

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Fajemisonu Ewe Ati Egbo Trado-medical Herbalist posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Share on Facebook Share on Twitter Share on LinkedIn
Share on Pinterest Share on Reddit Share via Email
Share on WhatsApp Share on Instagram Share on Telegram