16/06/2023
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
ORO ISIWAJU
Ki oluwa maje ki ase ise onise ; Eni se ise onise loman pariwo kiri ile adahunse pe aiye nse ohun ; Eni mu ise re pon tosi yori si rere lomo araiye ma a*ope omu lukudi, ose ogun awure sibi oja re ati bebelo, ile aye konira rara, eda inureti nwon nse ise onise ni zon npariwo enu pe ita le, kosi owo lode ati bebelo : eniirawo re se ise jagunjagun bi aries ti nlo ta eja enia o timo pe osina
Eyin oluka iwe yie e fi ara bale ka iwe yi tan sn ki oronu re wo daradara kioranti olorin tio o ko bayi pe \ ki aiye mama pa kadara wa da, ara nbe ta fe da eyitu ;osi pe onan ise asela ohun lohun wa yi sugbon awon ti won se ise onise ti wonjowu ohun, ki won ma le ranti ati gbe ti ohun se,Gbogbo wa lamo pe awon ti won se ise onise lati aro di ale, pupo ninu wonti won o ba ni emi olohun ninu ti won baranti awon ti won jo betre ti won ti ni lari,biri tiwon ba yi pada won aparada di Asa ti o ngbe o omo adie je ;Iwo ti osi wa ni idi ise boya eni oda, ola ada, ron piwada, masin ori olori ku,mu ona ise asela re pon oluwa yio mu e yori e si rere ki otodi ojo ale ; Iwo ti oba siti gbo ma pada di asa, toju iwe yi fun omo ti oba bi yio wulo fun, Ranti npe iranmeta kole to si po dandan ari eyi ti o jana ; Ranti Iran tie ti omadi oloro lehin oladandan Asa Egbe re toba ku lehin loma gbe iran re ti oloro mi ; Iwo ti osi mo ijo tiabie ti o kosi fe se ise onise, jowo pe mi sori number 08132375507
ORO NIPA IRAWO ATI OHUN TI O BAA IRAWO OLUKALUKU MUN LAYE
Opo Obi loti da igbese aiye omo re ru nipa pe dandan ise bayi bayi ni ogbodo ko, Olukuluku eda ni Olohun ti fun ni ise ti yio maa se laye, sugbon latariagidi ti awa omo Eda Adamo ni koje ki a ni ifura. Oro Olohun ko le ye omungoEda sugbon Ologbon eni ni nye, Opo ti o yeki o lo se ise Briclayer sugbon alaniakiyesi ko je ki o tete yan ise ori re layo, Eda ti o baa je omi laye ti o baa nse ise inakole ni aluyo laye, eda to si je ina ti o nlo nse ise omi kole ni ilosiwaju laye. Imonipa Irawo se koko laye awa omo eda, eleyi a jeki eda mo iru igbese aiye ti o le gbe,ohun ti oye ki a maa se ati ohun ti koye ki ase. Eda ti OIohun da lati ara omi ti o waa nlo se ise ni ile ise Bread, ki se epe raara kole ni aluyo laye. Ti abati bi omoEjeki a gbiyanju ki a to awon to ni imo nipa Izab wiwo ki won se alaye lori Iruirawo ti omo naa gbe waa si aiye, iru ise ti ole se. Esu koni da irin Ajo gbogbo waaru mo wa lowo laye. Amin
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
IGBEYAWO
Igbeyawo kiise ohun ti ole wole ki osare jade, idi niyi ti yoruba fima nsoni oro wipe oloko meji koni duro lori eyokan oro yi wa fun awon ti oba sina feoko oloko papa awon ojise olorun alfa ati adahunse ma ntan opolopo eniyan jewon aba won ye ise wo won a ni awon ri ibujoko wa nibe nitori awon ri omolarin won oto ni ki irawo oko ati iyawo ba papo oto ni pelu ti irawo oko atiiyawo ba funwon ose wo. Iwo ti oba si ti lofe okoloko ti omo bati wa larinigbeyawo yin mase fi oko e sile sugbon toju Iwe yi fun awon omo re nitorie ojoiwaju ki omobatun ri biti tire. Mo loba enikeni mo rara, wo ojo ibi ti iyawo ati tioko ki ofimo boya oto kiwon fe ara tabi ko to. Ni naye ojosi, ama nwadi idile tiomo wa ti fe loko tabi ni aya sugbon ni ode oni kosi iru e mo, ife ni won nlo fi nioko tabi aya. Omo ti oba fi ara bale yio gbadun igbeyawo re de ojo ale.Eyiti koba fi ara bale ni oro olopko meji koni duro lori eyokan. Ti iruawon wonyi ko ba rora se won yoo di oloko meta koni duro lori meji ati papaoloko merin koni duro lori meta, awon miran atun ni irun eni bayi kolori okolaimo wipe gbogbo eda ti oba konju ni oko laise iwadi lori irawo won boya obara mu tabi koba ara won mu yoo kanju jade.Mase gbagbe wipe oja meji ni awa na ni aye, oja akini mofe ra motor,a*o, bata ati bebe lo, wa mu ojo losi oja lati eyeti odara ; sugbon oja keji mofe feoko mofe fe iyawo odi dandan ki o mu ori lo, or iwa koni tiwa lofe oko olokotabi aya alaya amin fun alaye ni eku rere tabi oni ikose lori igbeyawo re tabi
igbeyawo re koso eso rara etc….. yowo gbiyan ju lati ri woli Awo Irawo
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
ORUKO AWON IRAWO
Aries belier ; Ta**us tauraux ; Cancer cancer; Germini germaux ; Leo lion;Virgo vierge; Libra balance; Scorpio scopion ; Sagitaire sagitaire ; Capricorncapricorne ; Aquarus verseaux ; Pisces poisson ;IRAWO INA Aries ; Leo ; SagitaireIRAWO IYEPE Ta**us ; Virgo ; CapricornIRAWO ATEGUN Germini ; Libra ; AquarusIRAWO OMI Pisces ; Cancer ; Scorp
Symbole Signe astrologique DateÉlémentBélierAries 22 mars au 22 avril InanTaureauTa**us 23 avril au 22 mai Yerupe
♊
GémeauxGermini 23 mai au 22 juin Afefe
♋
CancerCancer 23 juin au 23 juillet Omi
♌
LionLeo 24 juillet au 23 août Inan
♍
ViergeVirgo 24 août au 22 sept Yerupe
♎
BalanceLibra 23 sept au 22 octobre Afefe
♏
ScorpionScorpion 23 octobre au 22 nov Omi
♐
SagittaireSagitarus 23 novembre au 22 déc Inan
♑
CapricorneCapricorn 23 décembre au 20 jan Yerupe
♒
VerseauAquarus 21 janvier au 20 février Afefe
♓
PoissonsPices 21 février au 21 mars Omi
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
AJOGBE AWON IRAWO KANKAN LOTOTOATI LAPAPO FUN GBOGBO AWON TI WONSE DARA PO MOWA ATI AWON TI WON BERELORI AJOGBE PO
1 ) Ajogbe Po Adamo Omi ati Omi
Ire Omo Iya mi ninu esin islam mo fe ki e mo wipe awon
Irawo yi ni O rewon si ni ota awon Irawo Omi ati Omi lee fe ara won tabi ki won mura won niOre won si le jo da Ise papo. Pelu opolopo suru
2) Ajogbe Po Adamo Omi ati Yerupe
Bakanna ni Omi le fe yerupe, won si le mura won ni Ore won sile jo daIse po Bi o ti leje pe yerupe ni Ise ajose yen ma gbe.
3) Ajogbe Po Adamo Omi ati Ina
Lotito ni opo ninu awon Onimimo nipa Irawo ko fi owo si ajogbe Irawo Omi ati Ina, nitori Omi yoo pada Pa Ina, Sugbon won le jo da Ise po won silefera won ti won ko ba jo gbe papo lo dara ju nitori Ija. Koda won le ma ba arawon Sore, sugbon won yoo pada tuka pelu Ija tabi lori Ireje ti yio ma sele larinara won pelu aifinu han ara eni tan.
4 ) Ajogbe Po Adamo Omi ati Afefe
Awon Onimimo nipa Ijinle Irawo tako Ajogbe Irawo Omi ati Afefe, nitoriwahala ati idamu ti afefe saaba ma nkoba Omi, sugbon won le fera won gegebitoko taya won si le jo sore tabi ki won jo da Ise po bio ti je pe won yo tete ma riasise ara won ki si nii si Igbadun fun Afefe pupo nitori Afefe yoo ma fe si OmiOmi yo si ma tan kakiri eyi tumo si wipe Omi ni ajogbe won yo gbe pupo.
5) Ajogbe Po Adamo Yerupe ati Yerupe
Ajogbe awon Irawo yerupe ati yerupe dara pupo oore si ma nbe nibeajogbe won Ti o ba je wipe yerupe ati yerupe ba fe ara won tabi won mu ra wonni Ore tabi won jo da Ise po odara pupo won ki si ri Inira tabi Ija rara Afi tieniyan kan ba wo won larin ni o le fa Ituka. Be sini Adamo yerupe ati Omi naa.
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
6 ) Ajogbe Po Adamo Yerupe ati Ina
Opolopo ninu awon Onimimo Ijinle ninu Irawo ni won ko fi owo siajogbe yerupe ati Ina, nitori inira ati wahala ti ina yo ma fun yerupe ti ko si le kesita sugbon won le fe ara won gegebi toko taya won si le mura won ni Ore tabiki won jo da Ise po sugbon Ina yo pada re yerupe je nitori yerupe koni fe Ija besini ko ni je ki o ma soro lasiko ti o baye ki o soro yoda ni awon yerupe fi manko nira ba ara won ni odo awon Irawo Ina gbogbo ise ti yerupe ba se Ina ni yiofi sin won yo pada tuka ni ayafi ti Adamo yerupe ba fi Ori ro inira yan loku.
7 ) Ajogbe Po Adamo Yerupe ati Afefe
Awon Ojogbon ninu Imo Adamo ko fi ara mo Ajogbe Irawo yerupe atiafefe nitori wahala ati fitina ti Adamo Afefe ma nko ba Irawo yerupe sugbonwon le fera won gegebi toko taya ti won ba fe ki Ajogbe Ife naa pe dada won lema gbe papo ninu ile kunna nitori ti o ba je Okunrin ni Irawo Afefe koni ma fiIfe han si Adamo yerupe gbogbo owun ti Irawo yerupe ba se ni ko ni mo se lojuIrawo Afefe yo tete ma ka ese si lese, won le mura won ni Ore won si le da owo papo sugbon Afefe yo ma re yerupe je
8) Ajogbe Po Adamo Ina ati Ina
Ajogbe Irawo Ina ati Ina ni o dara ju lati fe ara won tabi ki won mura wonni Ore, won si le jo da owo papo Oore nla nla si ma njade ninu Idawole won papo won fitina tabi wahala kii si sele larin ara won Ayafi ti awon iyawo won batuwonka loku ti o baje toko taya ni awon molebi ni won ma nda arin won ru tabi
Ore Bakanna…
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
AWON EGBO IGI TI O DARA FUN IRAWO RE
1. IRAWO AFEFE
Je eniti yio maa se Adua daadaa, ki osi maa tan Turari pupo ni igbati o baanse Adua lowo, Maa lo Turari Adua dada ni gbogbo igba, Aseje, Ose, ati Etu ntetemaa nsise lara iru irawo yii nidiwon ti won baa nti nse adua ki won to lo
2. IRAWO OMI
Ki won je iru Eda ti o nlo unkan ti won fi omi pipe, gegebi Hantu mumu,Obe Aseje tabi ki won maa we ose dudu. Ebu Jijo ki sise lara won, bi won baa fione million se ebu fun iru won kole ri one naira ni ibe.
3. IRAWO INA
Irawo ina gbodo sora fun wiwe ose ni gbogbo igba, Ohun ti o dara fun iruirawo yii naa ni Ki won maa lo Ebu ti a jo.. Ebu ni o nsaba maa sise pupo fun wonju gbogbo ogun miran lo, Awon Ogun miran naa maa nsise fun won sugbon kodabi ki won lo Etu
4. IRAWO IYEPE
Irawo yii gbodo maa se Sara Daadaa, ki won maa fon awon unkan jije si ilefun awon eda ti won nse aiye iyepe, Ose Dudu ati Aseje dara pupo fun won
AKIYESI PATAKI
Opo igba ni awa omo eda nsun gbagbe, opo ninu eda ni koni akiyesi, opolo ti lo se ayewo si oro aiye re ti obaa de ibi kan bi won ko ba so wipe awon agba londa lamun won a*ope iya re ni o waa ni idi oro re, igbamiran won a ni egun idile,ohun ti awa omo eda nfi owo ara waa faa gan ngba miran gan ju ki awon apapoagba ma da enia lamun lo. Ojo kokan ninu osu loni ohun ti o nba enikokan wa rin,Irawo ati Ojo ibi maa nda opo eda lamun, ,, opo igba loti lo ogun dudu sibe sibepabo lo nja si, boya eleda re ko lo ni ilana unkan be sibe sibe o ko agidi bori onidandan iwo naa fe se ogun osole!
1) Irawo Omi,
Ewe ki je lara iwo omi, ogun asasi ota ki si saba ran won, Je enikan ti yio maa sabalo Hantu, tabi ki o maa se Adua si omi, Ebu lilo ki je lara won, bi won ba fi Millions se Ebu fun won ko le sise, Ose si nma nsise die die lara ju Ebu lo
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
2) Irawo Ina.
Ha! Irawo yii gbodo je enikan ti o nso ara re kuro lori wiwe ose ni gbogbo igba, Biose wiwe ba po lapoju o da gegebi eni npa ogo ati imole ara re ni, Ebu a maa sisedaadaa lara won ju ose lo 3.
3) Irawo Afefe...
Awon irawo yi gbodo je enia ti ntera mo adua sise lopo lopo, bi won se ni agbara tobe naa ni won yaa ole (lazy) to, ogun asi maa tete je lara won, besi ni asasi ntete maanmun won, won gbodo munra gidi gidi, won ki fe ki won se aseyege eko, enia nla ni won.
4) Irawo Iyepe,
Awon irawo yii maa nje oni suru, won ki tete binu, won gba iwosi sugbon bi wonba binu tan ibinu won ko dara raa, won ki si fe gbo imoran eda miran yato si ti won, inakuna asi maa ba won ja pupo, bi iru irawo yii baa tete munra si isori latiibere pepe aiye won, won ama bori Awon isoro bi ki owo maa daa lowo won.
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
Aries BelierMarch 22–avril 22
Oruko Irawo akoko yii ni ‘’Omo ti a ba bi ni March 22 t**i de April 22 yoo
je omo ti yoo maa huwa aigboran. Nigba miiran, iwa agidi won le maa fi iya je,tabi se won ni rere. Aisiki ko po fun won to bee, ti won ba n sise labe aniyan afiki won je oga ise ara won. Ki won da ise ara won sile. Won ko gbodo ba eniyanda ise po, ewu wa fun won ti won ba se bee.A bi Aries ni Irawo kan ti a n pe ni Mars ti ode orun, ti n joba ile kinnininu kadara eda. Eyi yoo fun won ni igboya, agbara ati iwa okikanju, won si le je eniyan ti o ni iwa agidi ati orikunkun nigba ti won ba n fe ohun kohun. Suurukii se ebun won, o si soro fun won lati ni ore otito ti yoo wa pelu won fun ojo pipe nitori pe won je alagidi ati eda ti o feran iwa asahan, enu-didun ati karimi.Irawo won yii lo n joba agbara ati imusasa tabi idasasa, eyi lo si fun wonni abuda ara gbigbona ati owu jije tabi fifi itara pupo se ohun gbogbo. Irawowon si kun fun ogun jija ati iwa lile bi ti jagunjagun. Iwa won yii nii je kigbogbo nkan ti won ba dawole maa yori sir ere, oun naa ni kii je ki won gbe ibikan nitori ainisuru to won. Olukuluku eniyan lo ni iwa ati abuda rere ni apa kanati eyi ti ko dara ni apa keji. Ohun kohun yowu ti oluwa re le je, ko si eniyan kanti o je maleeka patapata, bee si ni ko si eda kan ti o kuku je omo satani san-an, tiko si ni rere kan ninu igbesi aye re ti i se.Ina ni a fi se eda won, eyi yoo si fun won ni ookun ati agbara itagiri, tiwon yoo fi je onigboya eniyan ati eni ti o yara pupo. Won yoo je eniyan ti ko beru lati so otito bi o tile je pe eyi le so won di ota opolopo eniyan. Won yoo niaya bi ti kinnihun, won ko ni fe je omo ehin ninu ohun kohun bi ko se asiwaju.Lati igba ewe won ni iwa odaju ati igboya yoo ti wa fun won, a si kiyesi Inpe gbogbo omo ti a ba bi labe ase irawo yii n fe amojuto gidigidi lati igba ewewon wa, ki iwa orikunkun won ma ba won dagba ki won ma baa di omokomo.Won o je eniyan ti o ni aapon ati akikanju pupo ni igbesi aye won. Wonyoo si mo eto ohun gbogbo ni sise lona ti o to laarin ore, alabase, alabagbe ati alabarin won. Awon ni yoo saaba fe je olori ati asiwaju. O si tun seese ki wonmaa gbidanwo lati fi agidi se nkan. Nigba miiran aini suuru to won ni o maa n jeki won so awon nkan ti elomiran I ba fun won nu, nipa pe kekere ko to won afi bi won fi won ba gba nla. Won je eniyan to lawo to bee ge ti won fi le maa gbo bukata awon ore tabi ibatan won.Ibukun, orire, owo nini ati idunnu wa fun won ni igbesi aye won ti won bale ni suuru. Mo ro won ki won maa toju owo nitori ojo ale won, ki won ma baa
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
kabamo. Won yoo maa wo a*o daradara, won a si feran nnkan oso lati maa lofun ara ati omo won pelu. Won feran lati maa tan elomiiran je, sugbon ti won basi ri aisedeede lati odo eni keni, ki won ni suuru, ayo ni yoo jasi fun wonnikehin.
IKILO
E maa sora fun iwa akoba lenu ise, ki e ma ba eni keni ledi apo po seohun to lodi si ofin, ki e maa ba kabamo. E ma se kegbekegbe ni ibi ise, e sora kie ma gba ija onija ki eleyi ma baa yori si ota. E ma se wahala aseju lori ise ti konilaari, e maa se suuru fun gbogbo nnkan ki e si sora lati ma wo aago alaagosise. Won je eniyan ti o ma an tete nilaari ni igbesi aye won sugbon ki won mase je ki ola bo won loju lati ma le se ife Olorun. Paripari re ni pe ki won sora funiwa buburu lati hu si eni keni.E je iru eniyan ti ko gbodo fi aye sile fun igaara tabi iwa emi ni mo to yii, bi e ba se bee asilo agbara ti Olorun fun yin ni, o si le yori si isubu tabi iparunojiji. Nigba miiran emi itara ati aapon ti e ni yoo maa ti yin, o si le so yin dialailero tabi alaini suuru. Nipa aironu jinle ki a to se nkankan tabi aifi suuru se e,eyi le koba eniyan ki onitohun si fi owo ara re fa isoro tabi yanpon-yanrin baara re.E sora nipa fifi agidi tabi tipa-tikuuku je asiwaju, e ma se je ki inufufu boyin loju, ki e si ti ipa bee huwa tabi soro ti ko ni tan nile. E ma se je ki aifarabalemu yin huwa tabi soro ko-a-tan, ni igba pupo, o le je iwa enu fifun tabi gbigbeara eni ga ju bi a ti to lo ni a o fi fa akoba fun ara eni. Nipa aile ko ara eni ni ija nu tabi fi asiri ara eni pamo, ko dara ki e maa figba bo oro ti e e ba gbo lenu eni keni se ibinu, ifarada se pataki julo.E gbiyanju lati le maa pa asiri ara yin mo ati ti awon elomiiran, iwa aleebuyin kan tun ni eyi. E ma se taku si ibi ise ti ko fun yin ni ere, ki e ma si se je kiija onija di tiyin, e ma si se gbagbe tati fun ara yin ni isinmi. E ma se fi orotembelu eni keni tabi yaju si eniyan e ma si se jo ara yin loju nipa agbara, egbiyanju lati maa gba imoran. Eyin obinrin, e maa bowo fun oko yin, ki awonokunrin si maa toju iyawo won.
ILERA
Aisan ti yoo maa yoju si won ni efori, otutu, oju didun, iba, ooyi, arariro ati eje riru.
ISE
Ise ti o dara fun won niwonyii : Ise ero lorisirisi ona, oselu, ina monamona(electrical work), hoteeli (hotel), owo sise ati akowe oja. Won si tun le se ojiseOlurun, olopaa, onisegun (doctor), akowe labe ijoba, gbogbo ise ni o ba wonlara mu sugbon iseda won ko ba eniyan da ise po, ki won sora fun inakuna.
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
IGBEYAWO
Iyawo tabi oko ti o ba won mu niwonyii: Leo, Aries atiSagittarius. Won si le fe ninu awon irawo miiran pelu suuru ati adura. Awo to baoriire won mu ni awo pupa tabi eyikeyi ti o ba tan daradara. Ojo Isegun(Tuesday) ni ojo oriire won, nomba oriire won si ni 9, 18, 27 ati 54. Abela ti odara fun won lati maa lo fun adura ni pupa resuresu (pink) pupa ti o ni awoofeefee ninu (orange) ati pupa foo (red).Awure tabi isora (Talisman) ti a pinle se fun won labe ase irawo won lo bawon mu. Iwo obinrin ti a bi labe ase irawo yii, boya e lewa ni tabi e burewa,ohun ti a kiyesi nipe ife yin a maa gbona gidigidi lokan eni ti e ba nife. O siseese ki iwo obinrin je ojowu, ko si obinrin ti kii jowu sugbon ti obinrin irawoyii yoo fere peleke kii se aimo iwa hu won bi ko se pe abuda won ni inu fufu,igbakuugba si ni won maa n binu pelu, sugbon mo ro won lati maa bu omi suurumu.
April 22
–
may 22
Oruko Irawo akoko yii ni ‘’Tauros’’ Omo ti a ba bi
lati April 22 t**i demay 22 yoo je eniyan jeeje ti kii tete binu, sugbon eekan ti ibinu iru won barusoke, won kii tete gbebe. Ahun ni won nitori pe won hawo. Bi o tile je pe alaanuni won, sibe won maa n wonkoko mo ohun ini won ju bi o ti ye lo. Iru won se bakeebe, ologbon ni won, iruwon ni ipamora, won si maa n tete faramo samooniiyowu ti o de si won. Won feran alaafia ati irepo lopolopo. Won kii si ko latimaa fi egbin mora nigba miiran tabi lati padanu ohun kan ki irepo ba le wa ni ibikibi.Iru won je eniyan ti o n duro tinpinnu tabi ileri won. Eyi si le je pelu orikunkun ati aife se ayipada okan nigba miiran.Irawo ti n joba igbesi aye won yii naa ni n joba oro ife, eyi yoo fun won niabuda ati iriri ti o ni ise pupo pelu awon abinrin ati okunrin. Irawo wonyii je eyiti o fun won ni emi iforiti ati opolopo suuru. Won je eniyan ti won feran lati maafi eto ti o gbamuse se ohun gbogbo, won yoo feran ohun ti o lewa, oso sise atinnkan osin. Ti won ko ba sora, obinrin ti kii gbele oko ni won o fe sile, niwarasesa ni won yoo salo. Won o ni owo sugbon inukuna ni won o maa na an.
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
Mo ro won ki won sora fun inakuna nitori bi oni ti ri, ola le ma ri bee ko si si eniti o mo eyin ola.Ibinu kii pe tan ninu won, bi o tile je pe won ni orikunkun ti o le fa akoba ba won. Obinrin Ta**us maa n feran oko won pupo, amo sa, won feran ounje pelu. Won maa n ran awan obi won ati gbogbo eniyan lowo, won lawo si eni tiOlurun ba ran won si sugbon obinrin won maa n bimo ju okunrin lo. Tokunrintobinrin awon irawo yii ma n lowo. Bi wahala ba wa fun won lowuro, asale wonnilati dun yungba-yungba ni, ki won ni suuru, elemi gigun si ni won pelu.Olorun da awon irawo yii yato nitori pe bi eniyan sa oogun si won, kii ranwon rara. Won si korira opuro ati alajaigbiba eniyan. Bi won ti je ologbon atialaanu to ni won je eniyan Olorun ti won si ni arojinle lati fi okan te tabi gbekelennkankan nitori ojo ale. Abajo ti owe tabi asayan oro awon baba nla wa ti o wi
pe ‘’agbekele ko pa ni lebi’’ fe se iwo mo won lara nbi o ti kan won gbon
-gbon-on-gbon to.Olooto eniyan ati ore ti o se gbekele ni won je, won si ni ife gbogbo eniyan. Won maa n ni oro pupo sugbon won feran lati maa wo owo mo ohun iniwon ju bi o ti ye lo, koda, won le toju nnkan won pupo ju.
IKILO
E mu suuru daradara ki e si wadi finnifinni ki e to gbe iyawo. E ma sena inakuna, bee ni ki e ma se ilara omonikeji, e je ki ohun ti e ba ni te yin lohun.E ma se wo aago alaago sise, ki e ma si se maa se aabo ise e sora fun oti mimu.Bi eniyan kan gbe yin ga, esora nitori pe ota yin n be laarin won. E ma se mu otilile rara, bee ni ki e ma se ta oti nitori adanu. E sora lati ma se gba ona eburu waowo nitori ona iparun ni eyi yoo yorisi fun yin. Bi suuru yin ti po to, bee naa sini orikunkun to nigba ti e ba n binu. O seese ki e je bajumo eniyan sugbon boyaiwa imo-tara-eni-nikan diedie ko le sai ma si. E je oninuure ni tooto sugbon odabi pe ife ohun ti aye po ju lokan yin. E je eniyan ti yoo maa ni ife si baba juiya lo, sugbon sa, e ma se maa ya nnkan lo lowo ore tabi eni keni.
ILERA
Aisan ara bi ofun didun, ara riro, eje riru, ori fifo ati inu rirun po funawon irawo yii. E sora gidigidi nipa ounje jije lode, ki o ma je pe ibe ni won yooti fi majele sinu ounje fun yin ti yoo si se iku pa yin tabi ki e ri aisan nibe. Nipati obinrin, aisan ara ti o je mo ti ibimo le maa yo won lenu, sugbon o seese kiyipada maa wa fun won ni odun kefa-kefa ni gbesi aye won.
ISE
Ise ti o dara fun won ni oja tita sugbon to dara ki won ba eniyan da owo poOrisirisi ise owo ni o dara fun won Ise ile kiko (bricklaying), agbe, irohin ati
IRAWO RE PELU ISE ASELA RE
ounje siseta pelu, awon oti eleridodo (minerals) ni tita. Kadara won ko ba isetete ati oti tita mu. Ise ti o pa won lokan po situn dara fun won pelu.
IGBEYAWO Irawo ti o ba won lara mu ni Ta**us, Virgo, Capricon tabiScorpion. Won le fe ninu awon irawo miiran pelu suuru ati opolopo adura.Maleeka won ni ile. Ojo ti o dara fun oriire won ni ojo
Isegun ati Eti(Tuesdays ads Fridays) Awon awure tabi isora (Talisman) ti o si dara fun wonni awon ohun ti a ba se ni akanse labe ase irawo won tabi gege bi ohun ti e ba nfe. Awon Nomba oriire won ni 6, 15, 21. Awo ti o ba won lara mu ni olomi buluati wura (blue and old gold)
GEMINI GERMAUXMAY 23
– JUNE 22
Oruko Irawo yii ni ‘’Gemini’’ omo ti a ba lati May 2
3 t**i de June 22 yoo je eni ti yoo maa fi igbona okan gba nkan mora sugbon ko ni pe ki nkan naa tosu u, yoo si je eni ti ko ni maa ni ilara. Ire ayo wa fun un, yoo si ni aapon atiagbara lati se ohun ti inure ba dun si.
Awon irawo yii yoo je’a
-ri-yawo-ko-
iyale’, won kii
si fe gbo alaye afi tiwon saa.Alaanu ni won, won si lawo pelu. Oniwa rere ni won, won lemi aseyoriise sugbon ologbon ewe ni won. Ogooro won lo feran awon obi won, won silaanu won pelu. Ota maa npo fun won lati maa jowu won. Mo ro won ki wonsora lati maa fi inu han ore, ki o ma baa je ota ti n farahan bi ore ni won n fi inuhan.Won feran lati maa jiyan pupo nitori pe ogbon ti Olorun fun won po,ogbon ori won nikan ni o pe julo loju ara won. Pupo ninu won je eniyan ti o maan mo iwe, ti on ba ran won lowo lati ka a. ko si ibi ti won ko le ka iwe de, peluogbon si ni won maa n se gbogbo nnkan won.Won je eniyan ti o jafafa ti o si yara pupo sugbon ti won le soro ju Ogbonati oye won po to bee ge ti won fi maa n fura si nnkan ijinle tabi ti o farasin sikolofin ju bi awon irawo yoku ti le mo lo. Irawo ti o si n joba won ni
Mercury.
Won je eniyan ti o maa n ko irin meji bona leekan soso. Won si ferannnkan mejimeji lati maa se ati pe ise kan soso kii wu won afi ki won se nnkan to po dada,,,, Oro po Ni be dada a tun ma so Nipa re Ni igba mi