31/03/2022
AKIYESI PATAKI
Ninu oro elekarun ninu awon majemu ti ati soro re koja re
(V) 5 Ninu imule karun, eyi ti ise majemu karun ti iya Aje na fi owo so'ya nipa re fun Solomonu wipe, O ni agbara lati ko awon Aje ni ijanu, eyiti a ti so nipa re siwaju, nigba ti a bere si ni to pinpin, nipa opolopo iwadi a ri i daju wipe Okan ninu awon Hayat meje ninu Al-kuran mimo ti o ni agbara pupo ni won mu lati inu Surat ikedogun, ese iketadinlogun ati ikejidin-logun,(Kuran 15:17-18) pelu okan ninu awon Oruko mimo meje ti o n je: (AL-ZAHEIR) eyi ti olohun tikalara re ti fi owo so'ya nipa re wipe, on se oruko mimo na ni abo ati isegun lori gbogbo awon emi buburu tabi emi esu ati Oruko Maleka ti o n je SARFAYAHILU ( SACHIEL) ti o je okan ninu awon Maleka meje ti nwon gbe ile-aiye ro, ni won papo ti nwon fi hun agbara tabi Talisi-manu na.
Eleyi ni Oro lori majemu karun ti ati soro re koja, ko le ma iru agbara re ati pe oruko awon Maleka ti o nba sise ni.
Fun Iwo ti oni iso ro kan ti oti wa ro ra re pin
Kan siwa olohun yio gba adua re, abi oti e wa agbega lenu ise re
Abi o nwa ipo kan to jasi pe ko to e lowo abi otun fe te siwaju Lori ipo na.
Gba pe olohun ni yio se ooo.
Abi eyi keyi ikan ti o je ibanuje fun e, jeki a ma, kosi ikan ti olohun ko le se gbigba adua wa ni Ilorin o.
Ma sope kosi Alfa ma ni ilorin o, nibi ti iwo rinde lo ma o.
Sugbon gbogbo oro lori owo ni o. Ki se ofee ooo.