
25/11/2024
Ajé ìwọ ni eni ajiki
Ajé is you we wake up to greet
Ajé ìwọ ni eni ajige
Ajé is you we wake up to praise
Ajé ìwọ ni eni ajipe
Ajé is you we wake up to call upon
Ajé ìwọ ni gbogbo èèyàn ń sá sì ibùdó ẹ
Ajé you are the one who people seek solace under your shield
May the presence of Òrìṣà Ajé continue to bestowing upon us the blessings of prosperity, abundance and success...... Àṣẹ!!!
Ibosi Aje Ooooooo
Eeeepa Aje Oooooooooo
A kú Ojúmọ́ Ooooooo 🙏🏿🙏🏿🙏🏿🙏🏿