17/05/2023                                                                            
                                    
                                                                            
                                            OSE OSHOLE CONNECTION FUN AWON CONTRACTOR,  ONISE OWO,  ONISOWO, OMO YAHOO LELO PELU
π
°o lo wa odidi obuko kan, egun ori esin, alakan meta, eku eda meta, adan meta, ewe anu, ewe orijin, ewe adosusu, ewe sinkinimini, ewe sawerepepe, igba olomori nla kan.
Ao gun gbogbo awon nkan yiii papo yato si obuko yen ati igba yen,  awon omo ti koitii balaga  ni won ma bawa gun ose yi,  ao gun iti ogede,  ao fun omi ree sinu igo kan , omi yi lao fi po ose yi papo dada,  ao tun  wa pa obuko yen sibi ose yii, eje re  ni ao fi po ose na,  ao wa  fi  iyere osun te ejiogbe,  ao ro itan re si,  ao dasi ori ose naa,  ao fi iye agbe meji, iye aluko meji , ikode meji fi gun ose yi lori 
*OHUNRE*
Ni Ojo ti aba mu obuko wolu ojo naa ni nkan alanu,  ki ...omo...kan alanu okunrin ati obinrin, ori esin kii buru koma ni olusin ki ...Omo... maa ri eni rere sin, akii ri kekere akan kio ma nile lori ki ...Omo... kole mole,  abimo lemo niti eku eda ki ...omo... bimo lemo , adan loni  ki tewe tegba tokunrin tobinrin o wa maa fi gbogbo ohun rere owo nlanlan dan ...Omo... wo , ewe aanu loni ki tewe tagba o wa ma semi lanu , ewe oriji loni ki efi ire owo ati ire gbogbo jinmi  adosusu kii duro lohun nikan , ki tokurnrin tobinrin wa fi ire gbogbo owo won duro timi , sinkirinmini afaimoni konimora loni ki gbogbo aye oo wa ma fi ire gbogbo owo won famimora sawerepepe loni ki gbogbo aiye o wa mafi ire gbogbo owo won pe bomi. Ao wa dasi ori ose naa  
*NOTE*
Ti aba nwe ose yi lowo,  ao sope "eyin loni kefi ise min yin mi"
*IPARA OSE NA*
Ori ijimere ati padi atare kan,  ao jopo,  ao da sinu adiagbon,  ao ma fi para.
*OHUNRE*
Ti ijimere ba nbe lori igi, tigbo tiju ni nforibale fun, tokunrin tobinrin ewa maa fi ori bale fun emi ...omo... towotowo ati oore owo yin 
*NOTE*
Ao fi obuko naa se sara ni oooo, eni toni ise yi ko gbodo je  ni beee oooo