17/09/2022
Ise ITAJA TODAJU
Ewe ejinrin oso,ewe ewuro ati efun,
Sise re:a gun Gbogbo awon ewe yen Po Mon ara won a o gun efun na Mon pelu ose dudu TABI ff e jeka ko sinu Ike funfun
A o ma bu we larolaro