13/02/2023
ISOYE TODAJU GIDIGAN
Ejowo eje kia gbiyanju ise yii wo,okere loju sugbon o daju ti awon eniyan si ndupe Lori e lojojumoni,odamiloju pe ti eniyan ba gbiyanju isoye todaju gidigan yii yo royin si ogo olorun .
Igbin to gbonu 1, Odindi Atare 1, a o yin atare yen, a o fe pantiri re danu, a o ko si oju igbin yen, a o fi ewe iran di, a o fi si egbe amu fun ojo mokanla, bi ojo re ba pe, a o sa atare yen si inu orun yio gbe. Agba yi o ma lo eyo meji, omode eyokan
EWO RE: A ki gbodo juwe ogun isoye fun eniyan mo.
Fun ibeere tabi iranlowo miran epemi sori 07083054973