16/12/2022
*AKU OLA JIMOH ONI ADEKU IPALEMO ODUN MOFE KI GBOGBO WA LODAN AWON ISEYIN WOKI AFUN ILE LABORE*
*ASINA.IWE ODO*
*ISAWURU KAN,EWE EWURO, EYE OBE KAN AO GUN PAPO,AO FI OSE DIE KO,AO LO FIWE S**O TO NSAN LEKAN SOSO,AO FI EPO PARA KIA TO WE OOOO,,,*
*ATUDE IWE ALALE*
*OBI ABATA OLOJU META,EWE ONITIKUTI, ISAWURU META,AO GUN PAPO MO OSE,EYIKEYI, AO MA FI EPO PARA KATOMA WE LALALE SUN, EWE EKO LAO FI MO WE ISE YI O ,AO GBODO JADE SITA MO LEYIN WIWERE OOOO....*
*EYONU ASINA*
*EPO OBO,EPO IGI NLA,GIGUN PAPO MO OSE,OTI LAO FISE OMI TAO FIPO OOO,,WIWE NI OWURO KUTUKUTU,,*
*ASEJE TOMU OWO WA*
*EWE ORUNGO,AWO EKUN DIE,OGA TONI EYIN NINU,ATA IJOSIN 16,AO GUN PAPO,AO FISE ABO ADIE AGBEBO ALAWO META,AO GE ADIE YISI 16,KONISI ORI PELU ESE NIBE OOOO,AO SE LEPO NIYO,AO MU OMI AIYE LE LORII,,,*
*ITUWO ASINA AWON AGBA BI NKAN O BAFE SE DEDE MO*
*AO FI EPO OBO DIE TELE APE,AO FI EYE OBE KAN LE LORI, ATARE AJA LEGBERE NINU APE,AO EWE OGBO EYO KAN BO MOLE NINU APE,JIJO PAPO,AO FI FOKOMU LEKAN NA LALE...*
*ASIRI BIBO*
*OGA GBIGBE KAN EWE OLA DIE PELU ATARE KAN,, AO JO AO FI MILK OLOPE KAN LO,,ASIRI WA YIO BO,,,*
*ASEJE ASINA OWO...*
*IGBIN NLA KAN,EWE EYIN-OLOBE TUTU,IYERE,LILO EWE YI PELU IYERE YI PAPO,AO BO IGBIN YI,AO GE IGBIN YI SI,16,AO WA FI OMI INU AGBON SEE LEPO NIYO, TOBA TUTU,AO FIYERE OSUN TEIFA EJIOGBE,AO PE OFO YISI,,AO WA DA IYERE OSUN YISINU OBE YI AO KOJE,,AO WA MU,EJE ALUJONU LE LORII,,,*
*OFORE....*
*IGBIN KIKO ILE TIRE KIO MAN KUN,,OJUMO KIMON KI EYIN-OLOBE O MA SO OWO RE, EYIN OLOBE KI SUNKUN OWO RE DI OLA, OLODUMARE NISE OMI INU AGBON,ONA KONA LOMI AGBON GBA WONU AGBON,ONA KONA NIKI EMI L OMO L,GBARI OWO NLA ATI ISE KEKERE OWO NLA,,ADURA OHUN TIA NFE,,,*
*AO WA DA IYERE OSUN YI SINU OBE ASEJE TOWA NILE YIII,,AO WA KOJE,,,*
*ASIRI BIBO...*
*EWE EYIN-OLOBE LILO PELU EGUN ORI ESHIN DIE,AO WA SE ADURA OWO SI,,AO WA DASI ENU,AO WAMU OTI LE LORI DADA*
*IWO TOBAFE KI ISEYIN DAHUN BAMI FI ASIKO DIE FI WIPE MIO NIWA OWO TI NINU AIYE🙇♂️🙇♂️🙇♂️*
FUN IBERE LORI OHUNKOHUN
08181222918
09157512719
08186829496